Yoruba: Third Term Exam JSS2
 • 1. 1. Ipnle wo ni ilu Epe wa?
A) Oyo
B) Ondo
C) Ogun
D) Ekiti
E) Eko
 • 2. 2. Eya meji ti o te ilu Epe do ni ilu Ijebu_Epe ati ....
A) Ijebu_Remo
B) Eti_okun
C) Ijebu_ife
D) Eko_Epe
E) Ikorodu
 • 3. 3. Ilu Epe gbajumo fun....
A) Eja_pipa
B) Ode sise
C) Eran pipa
D) Oko riro
E) Igbon sisin
 • 4. 4. Gege bi ayoka yii see so fun wa, ekun melo ni o wa ni ipnle Eko?
A) Màrun
B) Merin
C) Meje
D) Mefa
E) Mejo
 • 5. 5. Ewo ninu orisii eja wonyii ni won ko daruko re ninu ayoka yii?
A) Lele
B) Obokun
C) Aro
D) Agbodo
E) Titus
 • 6. 6. Oriki ti won fun ilu Epe lati fihan pe ilu to eja po nibe ni
A) 'Epe olomi okun'
B) 'Epe onipepe eja'
C) 'Epe eleran tutu'
D) 'Epe eleja tutu'
E) Epe olomi osa'
 • 7. 7. Kinni idi ti eja pipa fi rorun ni ilu Epe? nitori pe
A) omi osa yii ka
B) eja won ni ibomiran
C) omo wewe po nibe
D) awon agbe alaroje po nibe
E) awon okunrin po nibe
 • 8. 8. Ede ti o gbile julo ni ilu Epe ni
A) Ibadan
B) Ijebu
C) Awori
D) Eko
E) Ikorodu
 • 9. 9. Odo wo ni won ti n pa eja ni ilu Epe?
A) Okun
B) Odo-eran
C) Kanga
D) Lagoon
E) Osa
 • 10. 10. Kinni o fa ifaseyin fun eto kara-kata eja pipa ati tita ni ilu Epe?
A) Awon eja ti saalo tan
B) Awon apeja ko ri eja pa mo
C) Awon apeja da ise sele
D) Awon apeja ti ku tan
E) Awon apeja to din ku
 • 11. 11. Ewo ninu awon wonyii ni o pon dandan ki o wa ninu leta aigbefe?
A) Adiresi
B) Ikinni
C) Akole
D) Koko oro
E) Ikadi
 • 12. 12. Ewo ninu awon wonyii ti o lee wa ninu leta gbefe?
A) akole
B) adiresi
C) Koko oro
D) awada
E) Ikinni
 • 13. 13. Konsonanti aranmupe asesilebu ni
A) en
B) en
C) an
D) on
E) n
 • 14. 14. Ihun silebu ' akekoo' ni
A) FKF-KFF
B) F-KF-KF-F
C) FK-Fk-FF-K
D) FK-FK-FF
E) F-KFK-FF
 • 15. 15. Orisa to maa n yo Ina lenu ni
A) Yemoja
B) Oya
C) Esu
D) Sango
E) Agemo
 • 16. 16. Ewo ni ohun eelo isomoloruko ninu awon wonyii?
A) Bata
B) Atike
C) Elubo
D) Ataare
E) Aso
 • 17. 17. Ewo ni o wa fun ayeye ninu awon Isare wonyii?
A) Esu pipe
B) Esa
C) Iwi
D) Bolojo
E) Iyere ifa
 • 18. 18. Ohun pipe ti awon babanla wa n lo nibi esin orisa ati ayeye ti ko je mo esin orisa ni
A) Awigbo
B) Ayajo
C) Isare
D) Aruge
E) Ofo
 • 19. 19. Afo ti a fi ohun to dun ni eti ko sits ni
A) Eebu
B) Epe
C) Afose
D) Esa
E) Orin
 • 20. 20. Irufe litireso wo ni won kii ko sile, sugbon ti won maa gbe jade lati Inu opolo? Litireso
A) atijo
B) apileko
C) akanse
D) alohun
E) igbalode
 • 21. 21. Orin to a n ko lati je ki omode dake nigba ti o n sunkun ni Orin
A) Igbeyawo
B) Eremode
C) Aremolekun
D) Faaji
E) Okoyawo
 • 22. 22. Okan ninu isori litireso alohun ni
A) Yoruba
B) Ewi
C) Akoto
D) Leta gbefe
E) Isare
 • 23. 23. Orisii aalo ti o ni orin ninu ni aalo
A) ariwo
B) apomo
C) apagbe
D) efe
E) isare
 • 24. 24. Iyere ifa ati Esa je Isare ti won n lo nibi
A) ile ounje
B) isinku
C) ibudoko
D) ile -iwe
E) esin Ibile
 • 25. 25. Isori oro melo ni a ni ninu ede Yoruba?
A) Mejo
B) Meje
C) Mesan
D) Mewa
E) Mokanla
 • 26. 26. Egbawa ni figo je
A) 1500
B) 2000
C) 3000
D) 4000
E) 5000
 • 27. 27. ( 200 x 4) +44=
A) Ojile le legbefa
B) Ojile legberi. o le merin
C) Orin le legberin
D) Egberin
E) Eedegbeta
 • 28. 28. Silebu melo ni o wa ninu'gbogbonise'
A) Mejo
B) Merin
C) Mefa
D) Meje
E) Marun
 • 29. 29. Ewo ninu awon wonyii ni ko si lara ohun eelo ti a fi n jagun?
A) Kannakan
B) Ibon
C) Aga
D) Kondo
E) Ofa
 • 30. 30. Ewo ninu awon wonyii ni kii se esin ode-oni? Esin
A) Ibile
B) Kirisiteni
C) Gurumarji
D) Buda
E) Ekanka
Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.