- 1. 1.
Okoo le nirinwo je ……………ni figo
A) 220 B) 420 C) 320
- 2. 2.
Orin le nigba din mewa ni figo ni
A) 280 B) 270 C) 290
- 3. 3.
Ti a ba ro ogoje ati ogorin papo, o je
A) 230 B) 220 C) 240
- 4. 4.
Bawo ni a se n ki alaro?
A) e ku ise o B) aredu o C) igba a roo o
- 5. 5.
Awon onise wo ni a n ki ni ‘ aluye o ”?
A) onilu B) awako C) onisowo
- 6. 6.
Eni ti o ni iwa rere, ti o si je eniyan daadaaa ni aarin ilu ni a n pe ni
A) omoluabi B) omo ti nua bi C) olubi omo
- 7. 7.
Apeere iwa rere niwonyii, ayafi
A) iwa irele B) iteriba C) ole jija
- 8. 8.
Awon wonyii ni orisi leta ti a lee ko si ebi , ore tabi ile ise ,ayafi
A) aigbefe B) gbajumo C) gbefe
- 9. 9.
Apeere ikini ti a ba n ko leta gbefe ni
A) emi ni ti e B) o dabo C) aya mi tooto
- 10. 10.
Igbese ti o keyin ti a ba n ko leta ni kiko oruko
A) akoleta B) agbaleta C) ile ifiweranse
|