jss2 yoruba 1st term exam 2025/26
  • 1. Ninu EWI-' ise ki I pa ni'
    Eni to sise lo jare ____
A) Aso
B) Ise
C) Owo
D) Osi
  • 2. ________ lo bomo je
A) Ise
B) Ole
C) Owo
D) Aso
  • 3. To a ba sise Ara en a
A) Yagaga
B) Daru
C) Doti
D) Baje
  • 4. Eni ba sise ni se n so di eni
A) Eyin
B) Osi
C) Ilele
D) Aponle
  • 5. Ai sise n fa _________
A) Abuku
B) Igbega
C) Ariyanjiyan
D) Aponle
  • 6. Eni ti ebi ba pa si le
A) Le ra moto
B) De ibi giga
C) Jale
D) Lowo
  • 7. Ti a ba sise, eje Ara a
A) A ribi rin kaakiri ara
B) Dudu
C) Gbona
D) Gbe
  • 8. Itoju Ara ni
A) Lilo Ara ni ilokulo
B) Bi ba ara je
C) Ki ko idoti ba ara
D) Sise Ara loge
  • 9. ________ je Ara iwa yoruba
A) Obun
B) Idotasile
C) Imototo
D) Ikorira
  • 10. Iwa obun Le fa
A) Igbega
B) Owo pupo
C) Ilera
D) Aisan
  • 11. Ona ti a Le fi toju Ara ni
A) Ji je ESO ti ko pon
B) Ki ekanna doti
C) Wiwo aso didoti
D) Iwe wiwe
  • 12. Awon ohun eelo itoju Ara ni iwonyii ayafi
A) Omi
B) Koinkoin
C) Ata
D) Ose
  • 13. "Ojoru" ninu ose ni
A) Friday
B) Sunday
C) Saturday
D) Wednesday
  • 14. "Ojobo " ni
A) Saturday
B) Monday
C) Thursday
D) Friday
  • 15. June ni a n pe ni
A) Owewe
B) Agemo
C) Sere
D) Ogun
  • 16. August ni a n pe ni
A) Okudu
B) Belu
C) Sere
D) Owewe
  • 17. September ni
A) Ogun
B) Owawa
C) Belu
D) Igbe
  • 18. Onka 1100 je
A) Eedegbeta
B) Egbefa
C) Egberundinlogorun
D) Eedegbefa
  • 19. Onka 1700 ni
A) Egberun
B) Egbeje
C) Egbesan
D) Edegbesan
  • 20. Onka 1900 ni
A) Aadosan
B) Ogosan
C) Egbesan
D) Eedegbewa
  • 21. Awon ohun eelo inu Ile ni iwonyi ayafi
A) Faanu
B) Aago
C) Patako
D) Ibusun
  • 22. A Le ri faanu ni ibi wonyi ayafi
A) Ile igbe
B) Ofisi
C) Ile itaja
D) Ile iwe
  • 23. Iwa ika je
A) Iwa obun
B) Iwa daradara
C) Iwa ole
D) Iwa buburu
  • 24. Awon wonyi ni iwa ika laye atijo ayafi
A) Lilu iyawo
B) Ofinisofa
C) Fifi eniyan rubo
D) Ikonileru
  • 25. Apeere iwa ika ode oni ni
A) Ifinisofa
B) Fifi eniyan rubo
C) Lile obinrin ni magun
D) Jijinigbe
  • 26. A Le dekun iwa ika nipa
A) Gbigba alaafia laye
B) Gbigba Owo aito lowo elese
C) Pipa elese
D) Fifi iya je elese
  • 27. Awon to won ma n ko ila ni a n pe ni
A) Onila
B) Ilagbemi
C) Kolakola
D) Olola
  • 28. Awon to won lu ilu ni
A) Ojo
B) Ode
C) Ayan
D) Agbe
  • 29. Blacksmithing ni
A) Apeja
B) Akope
C) Onidiri
D) Agbede
  • 30. Onigbajamo ni
A) Haircutter
B) Carving
C) Farming
D) Tailoring
  • 31. "Ise ona" ni
A) Blacksmithing
B) Hunting
C) Shaving
D) Carving
  • 32. Awon agba ma n fi "Owe"_____
A) Gba eto elomiran
B) Fi idi oro mule
C) Ba Oro je
D) Fa ija
  • 33. Pari owe yi. "a ki fi ikanju________
A) Wewu odi
B) Mu Omi gbigbona
C) La obe gbigbona
D) Je eba mo iresi
  • 34. Aja lo leru"________
A) Ere laja n se
B) Iro ni pepe n pa
C) Otito ni pepe n so
D) Pepe ma to ja
  • 35. #50 ni yoruba ni
A) Ogorun naira
B) Aadota naira
C) Ogbon naira
D) Ogun naira
  • 36. #200 ni
A) Irinwo naira
B) Igba naira
C) Edegbesan naira
D) Ogoji naira
  • 37. Agba ki WA Loja" _______
A) Ki ede wo
B) Ki ori omotuntun wo
C) Ki ori daru
D) Ki ori baje
  • 38. Eni a Fe la mo"
A) A ko mo ota eni
B) A ko mo Eni to inu n bi
C) A ko mo Eni fe ni
D) A ko mo olorire
  • 39. Pipe ni yi o pe,______
A) Omo a sare
B) Akololo a pe baba
C) Ori a mi
D) Omi a denu
Created with That Quiz — the site for test creation and grading in math and other subjects.