AIC YORUBA JSS2 3rd TERM EXAM 2026
  • 1. _________ ni itunmo ede kan si omiran
A) Ibanisoro
B) Aayan ogbufo
C) Iranra eni lowo
D) Isunki
  • 2. Eni ti o n tumo ede kan si omiran ni a n pe ni
A) Ogbufo
B) Elejo
C) Alaroye
D) Alalaye
  • 3. E ni fe tunmo oro gbodo____
A) Gbo ede mejeeji daradara
B) Buru
C) Lohun
D) Lowo
  • 4. Ni nu aayan ogbufo,a gbodo fun oro ni
A) Itunmo ti o jin na si
B) Itunmo ti o bamu
C) Itunmo ti ko ye rara
D) Itunmo ti o tobi
  • 5. Itunmo 'happinness' ni
A) Idunnu
B) Ironu
C) Iforiti
D) Ibinu
  • 6. Itunmo 'faith' ni
A) Itiju
B) Iwa
C) Ikorira
D) Ìgbàgbọ
  • 7. Itunmo 'secret' ni
A) Akínkanjú
B) Anfaani
C) Asiri
D) Asise
  • 8. 'He was slapped' tunmo si
A) Eti ti jabo
B) O gba wón leti
C) Won Gba leti
D) Eti n dun
  • 9. ________ ni a fi n ke ' Ewi'
A) Oju
B) Enu
C) Emi
D) Imu
  • 10. A ma n lo 'Ewi' nibi ________
A) Ija
B) Oro aje
C) Ayeye
D) Ogun
  • 11. Tumo èdè yìí "the woman was capable
A) Obinrin naa ko lagbara
B) Obinrin naa kún oju osunwon
C) Obinrin naa buru
D) Obinrin naa jebi
  • 12. O salo nítorí iwa re
A) He ran away because of his behavior
B) He didn't want to run
C) He was guilty of the offence
D) He was shy because of his life
  • 13. My boss sacked me
A) Oga mi yo mi ni nise
B) Mo le oga mi danu
C) Oga mi fe na mi
D) Oga mi bù mi
  • 14. Ni ile yoruba 6am--11am is
A) Ale
B) Owuro
C) Oru
D) Idaji
  • 15. A ma n ki awon "onidiri" pe
A) Enu gbe o
B) O jù gbórò o
C) Oju le o
D) Inu dun o
  • 16. Yoruba ma n fi kiki_____________
A) Gbe asa laruge
B) Re eni Yan je
C) Di olowo
D) Bù ẹní yan
  • 17. "E ku ireju "wa fun
A) Someone sleeping
B) Someone fighting
C) Someone relaxing
D) Someone eating
  • 18. Eku ayeye"
A) For hot weather
B) For party
C) For farmer
D) For someone who farts
  • 19. Se aayan ogbufo oro yii: "struggle"
A) Iwa
B) Igbiyanju
C) Ijakadi
D) Ibinu
  • 20. Contentment
A) Ibinu
B) Inu bibi
C) Ori pipe
D) Itelorun
  • 21. Pride
A) Asayan
B) Iwadi
C) Apara
D) Iwuri
  • 22. Hatred
A) Asa
B) Ikorira
C) Esin
D) Iwa
  • 23. He was scared of the animal
A) Eranko na bá leru
B) Eranko na buru
C) Io buru nitori eranko naa
D) Eranko búburú wa
  • 24. Aayan ogbufo ni
A) Pipa ede kan re
B) Kiko ede kan
C) Lilo ede kan
D) Tutu ede kan si omiran
  • 25. 400
A) Irinwo
B) Aadorin
C) Ogorin
D) Ogoji
  • 26. 1000
A) Ogowa
B) Egbewa
C) Egberun
D) Aadowa
  • 27. 500
A) Marun le lodo
B) Eedegbeta
C) Aadorun
D) Ogorun
  • 28. Nínú iwe Iitan "ODAJU" kini orukọ ọmọ obinrin ti a n so nipa rẹ nínú iwe yii
A) Janet
B) Adeola
C) Bolanle
D) Adesola
  • 29. Irú ènìyàn wo ni ará birin náà jee
A) Ole
B) Elejowewe
C) Oniranu
D) Alakikanju
  • 30. Ọmọ ìlú bò ni arabinrin naa
A) Ibadan
B) Oke ogun
C) Ogbomosho
D) Kwara
  • 31. Iṣẹ wo ni ọyàn layọ, ti o sí gba iwe ẹrí lẹ lori
A) Agbero
B) Olukoni
C) Adajo
D) Dokita
  • 32. Ọmọ ọdún melo ni arabinrin naa
A) Ogorun odun
B) Aadota odun
C) Ogoji odun
D) Igba odun
  • 33. Ilu wo ni o padà sí nigba ti o kuro ni ilé oko re
A) Saki
B) Okeho
C) Kebbi
D) Aha
  • 34. Ọmọ melo lo bi fún ọkọ re
A) Merin
B) Meta
C) Meji
D) Mefa
  • 35. Kini yoruba fín ka aago ni Aye atijo
A) Owo
B) Oorun
C) Osupa
D) Irawo
  • 36. E wo ni ko sí nínu asiko ojo
A) Aajin
B) Oroorun
C) Iyaleta
D) Afemoju
  • 37. Kini a fín ka osu ni Aye atijo
A) Ila kiko
B) Owo kika
C) Oorun
D) Osupa
  • 38. Ko aago yii ni èdè yorùbá"9:30 am"
A) Aago mesan din ogbon iseju owuro
B) Aago mesan le ogbon iseju owuro
C) Aago ọgbọn le mesan iseju owurọ
D) Aago meta le aadọrun iṣẹju owuro
  • 39. 4:15pm ni yoruba
A) Aago mẹrin le meedogun iseju
B) Aago marun le l'ogijo iseju
C) Aago meedogun le merin iseju
D) Aago mẹrin le àádọta iseju
  • 40. 2:45 pm ni yoruba
A) Aago marun le l'ogoji ati meji
B) Aago meji le ogbon iseju
C) Aago meji din ogbon iseju
D) Aago meta kù isẹju meedogun
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.