Yoruba : 3rd Term Revision Questions: JSS2
  • 1. 1. 1100 ni onka Yoruba ni
A) Eedegbefa
B) Edegberin
C) Egberun
D) Egberin
E) Eedegbeta
  • 2. 2. Egbewa ni Figo je....
A) 4000
B) 6000
C) 5000
D) 3000
E) 2000
  • 3. 3. Orisii Oro ti a n lo ninu gbolohun ni a n pe ni ........
A) Ege Oro
B) Isori Oro
C) Ede Oro
D) Oro gbolohun
E) Oro edan
  • 4. 4. Oro ise ni ede geesi ni ...
A) Syllable
B) Verb
C) Paragraph
D) Alphabet
E) Sound application
  • 5. 5. Melo ni isori Oro ti a ni ninu ede Yoruba? .
A) Ogbon
B) Ogun
C) Mesan
D) Mejo
E) Mewa
  • 6. 6. ....... Je afo ti a fi ohun to dun gbe Jade, ti o so dun leti lati gbo
A) Ibile
B) Ilu
C) Ofo
D) Isare
E) Orin
  • 7. 7. Ewo ni orin Ibile ninu awon wonyii? Orin
A) Eebu
B) Epe
C) Ose
D) Ikokuko
E) Igbeyawo
  • 8. 8. Irufe Orin to awon omode maa n ko ti won ba n sere ni Orin....
A) Ekun iyawo
B) Eremode
C) Esu pipe
D) Orin eebu
E) Epe sise
  • 9. 9. Orin " Boju Boju " ni asiko osupa he apeere Orin
A) Eremode
B) Ebo
C) Ayeye
D) Ifa
E) Oosa
  • 10. 10. Irufe Orin to awon osise maa n ko ni enu ise ni Orin
A) Oosa
B) Igbeyawo
C) Amuseya
D) Eremode
E) Eebu
  • 11. 11. Orisi isaare melo ni o wa ninu ede Yoruba?
A) Meji
B) Merin
C) Meta
D) Marun
E) Mefa
  • 12. 12. Ewo ninu awon wonyii ni apeere isare ajemesin?
A) Apepe
B) Ekun iyawo
C) Bolojo
D) Eti yeri
E) Iyere ifa
  • 13. 13. Awon ohun pipe ti a n lo nibi ayeye ni isere....
A) Ajemeko
B) Ajemayeye
C) Ajemere
D) Ajemesin
E) Ajemese
  • 14. 14. Orisii Alo to ko ni orin ninu no a n pe ni Alo....
A) Apagbe
B) Apaso
C) Apami
D) Apamo
E) Apaje
  • 15. 15. Aalo ti o ni orin ninu ni aalo
A) Apagbe
B) Apaso
C) Apamo
D) Apari
E) Apagbo
  • 16. 16. Ona esin ti Yoruba n gba sin Olorun ni Ilana abalaye ni esin.....
A) Alejo
B) Atijo
C) Gbajumo
D) Ibile
E) Tileyii
  • 17. 17. Esin see Pataki ni awujo Yoruba nitori pe esin
A) n je ki a maa paro
B) n je ki a maa ri agbalagba fin
C) n ko wa ni iwa jagidijagan
D) n ko wa ni iwa ti Olorun fe
E) n ko wa lole
  • 18. 18. Ewo ni kii se oruko Olodumare ninu awon wonyii?
A) Elepeyo
B) Elemii
C) Olorun
D) Eleda
E) Obarisa
  • 19. 19. Lati fi ipo Olodumare han , awon Yoruba tun maa Olorun o ba bayii, ayafi
A) Olowo gbogboro
B) Ogbagba tii--gba-alailara
C) Esu kukuru
D) Atoobajaye
E) Apata ayeraye
  • 20. 20. Ewo ni kii se esin ode-oni ninu awon wonyii? Esin
A) Musulumi
B) Abalaye
C) Kirisiteni
D) Ekenka
E) Buda
  • 21. 21. Ija esin kii waye laarin awon Yoruba nitori pe, won gbagbo pe, esin ko faja,
A) Jagidijagan ni o daa
B) Ife ni Olorun
C) Epe ni won yoo fi lole
D) Orisa ni awon yoo maa sin
E) Aje ni won mo
  • 22. 24. Ara ose to ija esin maa n da sile ninu ilu ni pe, o maa
A) bi ore si aarin awon eniyan
B) je ki awon ero maa po sii ninu ilu
C) je ku ounje maa po sii ninu ilu
D) n tu ilu ni
E) n tun ona ilu se
  • 23. 25. Ewo ni kii se ohun eelo ogun ninu awon n kan wonyii?
A) Obe
B) Kondo
C) Oko
D) Ofa
E) Ounje
  • 24. 26. Ewo ninu awon n kan wonyii ni ko so ninu ohun eelo isomoloruko ?
A) Eku
B) Epo
C) Iru
D) Elubo
E) Eja
  • 25. 27. Ni ile Yoruba, ojo kelo ni a maa n so awon ibeji loruko? Ojo
A) Kefa
B) Kesan
C) Kejo
D) Kewa
E) Keje
  • 26. 28. Ona melo ni litireso apileko pin si?
A) Merin
B) Marun
C) Mefa
D) Meje
E) Meta
  • 27. 29. Litireso ti a kii ko sile, sugbon ti o je pe Inu opolo ni won ti maa n soo Jade ni litireso
A) Apeko
B) Apileko
C) Awitunwi
D) Apetunpe
E) Alohuun
  • 28. 28. Eni ti o ko iwe litireso fun kika awon eniyan lati ka ni a n pe ni
A) Olukawe
B) Akowe
C) Oniwe
D) Olusewe
E) Onkowe
  • 29. 29. "Oruko omo ni ijanu omo" fi han , Pataki
A) Orin kiko fun omo
B) Omo bibi
C) Omo tito
D) Bibimo
E) Isomoloruko
  • 30. 30. Ewo ninu awon gbolohun wonyii ni ko si ninu eto isomoloruko ni ile Yoruba?
A) Fifi ohun eelo isomoloruko wure
B) Fifi ara omo gbe ekan omi Ori orule
C) Fifun omo lowo
D) Fifun omo loruko
E) Jiju omo sodo
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — where test making and test taking are made easy for math and other subject areas.