- 1. 106 ni onka Yoruuba ni
A) eerin din logun B) eerin din logorun C) eefa le logorun
- 2. okooleerugba din mew ani
A) 220 B) 210 C) 320
- 3. melo ni faweeli airanmupe ti o wa ninu alifabeeti ede Yoruba?
A) mesan B) meje C) mejo
- 4. . Odun wo ni awon igbimo ede fi owo si lilo akotoYoruba ?
A) 1973 B) 1974 C) 1972
- 5. kini igbese akoko ninu leta kiko? kiko
A) deeti B) oruko akoleta C) adiresi
- 6. .Ewo ni akoto ode oni fun gbolohun “ Lailai”
A) leaalea B) lailai C) laelae
- 7. . Konsonanti melo ni o wa ninu gbolohun ‘’ogedengbe ’’
A) 4 B) 6 C) 5
- 8. Ewo ninu awon eniyan wonyii ni a lee ko leta gbefe si
A) egbon baba B) alaga ijoba C) oga ile ise
- 9. Ninu ami ohun ni ede Yoruba, ewo ni ami isale ?
A) mi B) re C) do
- 10. Leta gbefe ni a n pe ni ………………… ni ede geesi
A) informal letter B) formal letter C) semi-formal letter
|