PES Yoruba JS 1 First Term Exam 2025
  • 1. Gbogbo Konsonanti ede Yoruba je........
A) meedogbon
B) meedogun
C) meji din logun
D) Marun din logun
  • 2. Konsonanti ti o gbeyin alifabeeti ede Yoruba ni..........
A) D
B) B
C) Y
D) T
  • 3. Konsonanti inu ede Yoruba pin si meji
A) Afetigbo ati aifetigboe
B) Ayanmupe ati airanmupe
C) Aranmupe ati airanmupe
D) Akunyun un ati akunyun un
  • 4. Ojo akoko ninu ose ni Yoruba n pe ni ojo.....
A) Isegun
B) Aiku
C) Abameta
D) Aje
  • 5. Ewo ninu awon won yii ni ko si ninu alifabeeti ede Yoruba?
A) T
B) C
C) O
D) P
  • 6. Eerinla ni figo je......,
A) 14
B) 54
C) 24
D) 34
  • 7. 75 ni onka Yoruba je....
A) aarun din logoji
B) aarun din laadowa
C) aarun din logorin
D) aarun le laadota
  • 8. Ewo ninu awon oro won yii ni o ni faweeli aranmupe ninu?
A) Iyun
B) Odo
C) Ara
D) Baba
  • 9. Ewo ni Konsonanti arehon ninu awon won yii?
A) M
B) B
C) P
D) R
  • 10. Faweeli aarin lori ate faweeli ni
A) u
B) e
C) i
D) a
  • 11. Ege oro ti eemi lee gbe jade laye leekan soso ni......
A) Faweeli
B) silebu
C) Konsonanti
D) Ohun
  • 12. Kin ni ami ihun silebu "KF" duro fun?
A) Konsonanti+ iro ede
B) Silebu + iro ohun
C) Konsonanti + Faweeli
D) Faweeli+ ,Silebu
  • 13. Silebu melo ni o wa ninu "oronro"?
A) Merin
B) Meta
C) Marun
D) Meje
  • 14. Tani oba ati olori awon elesin iborisa ni ilu Mela? Lamurudu
A) Lamurudu
B) Buraimo
C) Agbonmiregun
D) Oduduwa
  • 15. Osu ti o gbeyin odun ni ede Yoruba ni
A) Agemo
B) Ogun
C) Ope
D) Beelu
  • 16. Osu "March" ni ede Yoruba ni Erena
A) Owawa
B) Owewe
C) Seere
D) Erena
  • 17. Omo obinrin melo ni Okanbi bi?
A) Okan soso
B) Meta
C) Marun
D) Meji
  • 18. Awon omo eyin Oduduwa kan duro ni apa oke oya nitori...... .
A) airomi mu
B) Oduduwa le won pada
C) aare ara
  • 19. Ojo melo ni Oduduwa ati awon eeyan re lo ni ona nigba ti won kuro ni Meka lo si Ile Ife?
A) Aadorun odun
B) Ogoji ojo
C) Aadorun ojo
D) Aadota odun
  • 20. Ewo ninu awon omo Oduduwa ni o jogun ileke?
A) Olupopo
B) Oranmiyan
C) Okanbi
D) Orangun
  • 21. Ewo ni kii se eya Yoruba ti a lee ri ni apa oke oya
A) Egba
B) Yorubawa
C) Bawa
D) Gogobiri
  • 22. Ewo ninu awon won yii ni awon Yoruba gba gege bii babanla won?
A) Oranmiyan
B) Oduduwa
C) Okanbi
D) Lamurudu
  • 23. Iro faweeli ede Yoruba pin si iro
A) Airanmupe ati akunyun
B) Afojuri ati aifojuri
C) Aranmupe ati airanmupe
D) Akunyun ati airanmupe
  • 24. Ewo ni kii se iro faweeli aranmupe ninu awon won yii
A) In
B) On
C) Un
D) Mi
  • 25. Faweeli aranmupe inu alifabeeti ede Yoruba je
A) Meji
B) Mokanla
C) Marun
D) Meje
  • 26. Konsonanti afegbe enu pe ni
A) T
B) B
C) S
D) L
  • 27. Ewo ninu awon won yii ni a mo si VOICELESS CONSONANTS
A) Faweeli aranmupe
B) Konsonanti aikunyun
C) Konsonanti akunyun
D) Faweeli airanmupe
  • 28. Ewo ninu awon Konsonanti won yii ni a n fi ete mejeeji pe
A) S
B) B
C) D
D) T
  • 29. Konsonanti wo ni a mo si asesi?
A) W
B) Y
C) H
D) J
  • 30. Konsonanti aikunyun je melo?
A) Meje
B) Mokanla
C) Mewa
D) Mesan
  • 31. Iru Konsonanti ti a pe nigba ti tan-an-na sunmo ara won ni Konsonanti
A) Afimupe
B) Aikunyun
C) Akunyun
D) Airanmupe
  • 32. Ewo ni oro onisilebu kan ninu awon oro won yii?
A) Gbon
B) Bolugi
C) Abata
D) Ide
  • 33. Konsonanti aranmupe asesilebu ni
A) P
B) D
C) T
D) N
  • 34. Oro wo ni o ni ihun oro yii "KF- F(n) - KF "
A) Bolatito
B) Bolanle
C) Bankole
D) Banke
  • 35. Iro.......... ni iro ti a n pe nigba ti ko si idiwo fun eemi ti a iro naa jade .
A) Konsonanti
B) Ohun
C) Silebu
D) Faweeli
  • 36. Ami ohun ede Yoruba ni ami
A) Isale, odo ati egbe
B) Aarin, eyin ati oke
C) Iwaju, aarin ati eyin
D) Oke , aarin ati isale
  • 37. Ewo ni iro ami ohun ti a kii ko sori oro? Ami
A) Fa
B) Re
C) Mi
D) Do
  • 38. Ewo ni kii se ododo ninu awon gbolohun won yii?
A) A kii fi ami ohun sori Konsonanti, ayafi Konsonanti asesilebu 'n'
B) Ori iro faweeli ni a n fi ami ohun le ninu oro
C) A kii fi ami ohun aarin han
D) Ori iro Konsonanti nikan ni a maa n fi ami ohun si ninu oro
  • 39. Ami ohun ti o ba "Alantakun" ni
A) Re mi do re do
B) Do re mi do re
C) Re re mi do do
D) Mi re do re re
  • 40. Ege ti o kere julo ti a lee fi eti gbo ni......
A) Ede oro
B) Ede Yoruba
C) Iro ohun
D) Iro ede
Created with That Quiz — a math test site for students of all grade levels.