PES JS 2 Yoruba (Obj) 2nd Term Exam 2025/2026
  • 1. . . .. .ni awon ewi alohun ti a le fi oro inu won ti a gbo da won mo yato.
A) Aroko
B) Litireso
C) Arangbo
D) Isare
  • 2. Ona ti opo eniyan fi n pawopo ran eni kan lowo se ise ti o le gba asiko pipe lati se ni asa............
A) Idara - eni - lokowo
B) Iranra - eni - lowo
C) Ifowo-so-wopo
D) Ifara - eni - goke
  • 3. Ewo ni ona Iranra-eni - lowo ajemowo ninu awon won yii?
A) Owe
B) Ajo
C) Aaro
D) Arokodoko
  • 4. Anfaani iranra eni lowo ni......
A) O je ki ise ti o le gba akoko pupo lati se je sise kiakia
B) O je ki awon onise kan maa se imele
C) O mu ifaseyin ba opo eniyan
D) O n dina mo awon odo ilu lati se oriire
  • 5. Owo ti a n da jo titi ti yoo fi joju ki a to ko o ni.......
A) Esusu
B) Ajo
C) Owe
D) Aaro
  • 6. Anfaani esusu ni pe, ......
A) kii je ki a nawo ni inakuna
B) o n so eeyan di otosi
C) o je ki eni ti o ti lowo tele di alaini
D) o n je ki eeyan ma mo ohun ti a n fowo se
  • 7. Ti inawo pajawiri ba de, eeyan le gba....... lati fi bo asiri.
A) Esusu
B) Ajo
C) Owe
D) Aaro
  • 8. Awon ise ti a le be owe se ni won yii, ayafi......
A) Ile kiko
B) Ona oko yiye
C) Ise oko
D) Omi pipon
  • 9. Ewo ninu awon ona iranra - eni - lowo won yii ni o tumo si 'bami ro temi, ki n ba o ro tie '?
A) Esusu
B) Arokodoko
C) Owe
D) Aaro
  • 10. Awon wo ni o maa n be ni aaro sise?
A) Awon alagbaro fun agbe aladanla
B) Awon agbe aladanla
C) Awon ore ti oko won wa nitoosi ara won
D) Awon ore ti oko won jina si ara won
  • 11. Riro oko kiri gege bi ona ti awon agbe n gba lati fi ran ara won lowo ni........
A) Arokodoko
B) Alupayida
C) Aaro
D) Owe
  • 12. Ewo ninu ona Iranra-eni - lowo won yii ni won n seto eyawo onilopo meji iye ti omo egbe ti da si apo egbe?
A) Ifomosofa ti igbalode
B) Egbe alajeseku aye atijo
C) Egbe alafowosowopo ode oni
D) Sogundogoji ti igbalode
  • 13. Ewo ni ona Iranra-eni - lowo ajemose ninu awon won yii?
A) Eesu
B) Ajo
C) Sogundogoji
D) Owe
  • 14. Ewo ninu awon won yii ni kii se orisa ni ile Yoruba?
A) Obatala
B) Sango
C) Alapinni
D) Orunmila
  • 15. Ona Iranra-eni-lowo ti awon eniyan pawopo laarin ilu lati se, fun idagbasoke ilu ni.........
A) Arokodoko
B) Owe
C) Aaro
D) Ebese
  • 16. Orisa wo ni awon Yoruba n ki ni 'omoran ale Ife '?
A) Obatala
B) Ogun
C) Orunmila
D) Opon ifa
  • 17. Awon Yoruba timo Olodumare si.....
A) Eni ti o da orun ati aye
B) Eni ti o seda gbogbo e
C) Oba awon orisa
D) Eni ti o tobi julo, ti titobi Re ko lopin
  • 18. Eedegbeje ni figo je.....
A) 1300
B) 1700
C) 1500
D) 1900
  • 19. Orin le nirinwo je...
A) 480
B) 780
C) 380
D) 580
  • 20. 200 × 9=?, o je..... ni onka Yoruba.
A) Egbewa
B) Egbeta
C) Egbesan
D) Egberin
  • 21. 250 + 115 = ?, o je..... .....ni onka Yoruba.
A) Orin le nirinwo din marun
B) Oji le nirinwo le marun
C) Oji le nirinwo din marun
D) Ota le nirinwo le marun
  • 22. 2000 ÷ 5 =? ni onka Yoruba, o je........
A) Oodun
B) Ogorun
C) Igba
D) Irinwo
  • 23. Orisii meji ti arangbo pin si ni arangbo........ ati arangbo.....
A) Kikun ati kekeke
B) Wiwuwo ati fifuye
C) Nla ati kekere
D) Ode oni ati ti atijo
  • 24. Awon Yoruba gbagbo pe onigbowo awon lodo Olodumare ni awon........
A) Muhamodu
B) Orisa
C) Aborisa
D) Kirisiteni
  • 25. Awon elesin ibile maa n se gbogbo awon nnkan won yii, ayafi....
A) Jija ija esin
B) Ninfe ara won
C) Ba ara won lo pelu ooto inu
D) Lile ipa alaafia
  • 26. Ewo ni arangbo kikun ninu awon won yii?
A) Aalo apamo
B) Ese ifa
C) Aro
D) Owe
  • 27. Ewo ni arangbo kekere ninu awon won yii?
A) Owe
B) Ijala
C) Esa egungun
D) Ofo
  • 28. Awon won yii ni asa Iranra-eni- lowo ajemowo, ayafi.......
A) Aaro
B) Sogundogoji
C) San an diedie
D) Ifomo sofa
  • 29. Oriki Ogun saaba maa n jeyo ninu........
A) Ijala ode
B) Arungbe
C) Sango pipe
D) Iyere ifa
  • 30. Awon elesin oro lo ni......
A) Ijala ode
B) Arungbe
C) Esa egungun
D) Iyere ifa
  • 31. Ewo ni o yato ninu awon won yii?
A) Ekun iyawo
B) Iyere ifa
C) Esu pipe
D) Oya pipe
  • 32. A tun mo iwi si.....
A) Iyere ifa
B) Ijala ode
C) Esa egungun
D) Arungbe
  • 33. Ewo ninu awon orisa won yii ni a maa n ki ni 'Elerii-ipin, a tun ori eni ti o sunwon se'?
A) Orunmila
B) Olodumare
C) Esu
D) Obatala
  • 34. Ki ni eewo Esu?
A) Eko tutu
B) Adi
C) Adie
D) Epo pupa
  • 35. Ewo ni ko si ninu oriki ti Yoruba fi n pe Olodumare?
A) Adakedajo
B) Asenibanidaro
C) Alawilese
D) Gbanigbani
  • 36. Eya wo ni o pe Olorun ni Mawu?
A) Igbo
B) Egun
C) Tapa
D) Hausa
  • 37. Oriki wo lo fi han pe Olodumare maa n gbo oro?
A) Adaniwaye
B) Arinurode
C) Olumoran okan
D) Eletiigbaroye
  • 38. Ewo ni ko si lara ohun ti a fi n bo Obatala ?
A) Emu
B) Obe - efo
C) Igbin
D) Adie
  • 39. Ta ni Yoruba gba gege bi Olorun Airi tabi eni ti a ko le fi oju ri?
A) Olodumare
B) Esu
C) Ogun
D) Sango
  • 40. Orisa wo ni Yoruba gbagbo pe o seda ara eniyan ti Olodumare si fe emi si ara naa?
A) Ogun
B) Sango
C) Esu
D) Obatala
Created with That Quiz — where test making and test taking are made easy for math and other subject areas.