- 1. Iikede ohun ti a n ta fun awon eniyan ki won lee nife sii lati ra tabi lo ni
A) ipate oja B) ipolowo oja C) ikiri oja
- 2. Gbigbe oja le ori kiri lati ta ni a n pe ni
A) ikiri oja B) ipate oja C) ipolowo oja
- 3. Langbe jina o , oroku ori ebe…………ni a n polowo bayii
A) eko gbigbona B) isu sise C) agbado sise
- 4. Ona ti awon baba n la wa fi n baa ra won soro asiri lai lo ohun enu ni a lee pe ni
A) aroko B) akoto C) akaye
- 5. Ewo ninu awon oro wonyii ni kii se orisii aroko?
A) aaga B) isegiri C) itufu
- 6. Aadojo ni onka geesi ni
A) 150 B) 350 C) 250
- 7. Okoo le nirinwo ni onka figo je
A) 420 B) 320 C) 520
- 8. Bayii ni a se n ki agbe
A) aroko bodun de o B) e ku oko o C) e ku ise o
- 9. Ti a ba n ko leta, igbese akoko ni , kiko
A) adiresi B) koko oro C) ikini
- 10. Awon wonyii ni a lee ko leta gbefe si, ayafi
A) molebi B) ore C) oga ile ifowopamo
|