PES Yoruba JS 3 Mock 1 Exam
  • 1. 1. Aadofa ni figo je......
A) 170
B) 150
C) 110
D) 130
  • 2. 2. 500 ni onka Yoruba ni
A) Oodun
B) Irinwo
C) Ogofa
D) Eedegbeta
  • 3. 3. Ogota naira ni ede Yoruba je
A) #120.00
B) #90.00
C) #50. 00
D) #60.00
  • 4. 4. 125 ni onka ni
A) Aaun le laadoje
B) Aaron logojo
C) Aaron din laadoje
D) Aaron le nigba
  • 5. 5. Ninu aroko wo ni a ti n so isele ti o se loju wa?
A) Oniroyin
B) Alalaye
C) Asapejuwe
D) Onisorongbesi
  • 6. 6. Leta ti a ko lati fi wa ise ni..........leta
A) Iroyin
B) Alaye
C) Gbefe
D) Aigbefe
  • 7. 7. Batani silebu wo lo wa ninu "alapansanpa"?
A) Mejo
B) Meje
C) Mefa
D) Merin
  • 8. 8. Faweeli"I" je faweeli
A) Iwaju
B) Egbe
C) Aarin
D) Eyin
  • 9. 9. Faweeli/F/ je faweeli
A) Ahanupe
B) Afeyinpe
C) Ayanupe
D) Arehon
  • 10. 10. Melo ni gbogbo konsonati ede Yoruba je?
A) Mejilelogbon
B) Mejilelogun
C) Mejidinlogbon
D) Mejidinlogun
  • 11. 11. Oro ti o n toka si isele ninu gbolohun ni oro
A) Ise
B) Asopo
C) Aropo
D) Oruko
  • 12. 12. Bola so oro naa fun baba re ."naa" ninu gbolohun yii je oro
A) Atokun
B) Apola
C) Eyan
D) Oruko
  • 13. 13. Ise ajose to ko ni esan owo tabi ise asepada ise naa pada ni
A) Esusu
B) Owe
C) Ajo
D) Itufu
  • 14. 14. Igbese akoko ninu aroko kiko ni........
A) Koko oro
B) Deeti
C) Adiresi
D) Akole
  • 15. 15. Konsonati aranmupe asesilebu ni....
A) O
B) N
C) B
D) D
  • 16. 16. Bola sun lo fonfon." fonfon" je isori Oro.....
A) Ise
B) Atokun
C) Asopo
D) Aponle
  • 17. 17. Osu okudu ni
A) October
B) May
C) June
D) July
  • 18. 18. Ewo ninu awọn won yii ni isare ajemesin?
A) Ogun pipe
B) Ijala
C) Ekun Iyawo
D) Obintu
  • 19. 19. Ewo ninu awọn won yii ni oriki?
A) Adesina
B) Adisa
C) Afolasade
D) Omolewa
  • 20. 20. Ewi alohun ti a fi n se apole eniyan ni......
A) Ofo
B) Oriki
C) Orin
D) Arangbo
  • 21. 21. A maa n ko orin, a si maa n ... ege
A) wi
B) sun
C) ko
D) da
  • 22. 22. Osu keji odun ni.....
A) Irele
B) Seere
C) Ope
D) Okudu
  • 23. 23. Appere iwa omoluabi ni iwon yii, ayafi
A) Aforiti
B) Aanu
C) Ole jija
D) Ikini
  • 24. 24. Pari owe yii "aja ti yoo sonu, ko ni .............
A) sare jina"
B) je ki enikeni rii"
C) gbo fere olode"
D) dahun si ipe
  • 25. 25." Ile oba to jo, ........
A) ewa lo bu kun un"
B) awon ara ilu n pariwo "
C) won ko tete bomi paa ni "
D) oba a ko omiran"
  • 26. 26. Ewo ni abigbeyin Okanbi ninu awọn won yii?
A) Osunyemi
B) Oranmiyan
C) Orangun
D) Esubiyi
  • 27. 27. "Baba wulo ju iya lo" je akole aroko.....
A) Alariyanjiyan
B) Ajosipaya
C) Onisorongbesi
D) Alapejuwe
  • 28. 28. Ewo ni igbese ti o keyin ninu aroko alariyanjiyan?
A) Ikini
B) Ifaara
C) Ikadi
D) Deeti
  • 29. 29. Omo to ni ika owo mefa ni Yoruba n pe ni.,..
A) Ige
B) Idoha
C) Olugbodi
D) Ilori
  • 30. 30. Bawo ni a se n ki onidiri ni Ile Yoruba?
A) Apaye o
B) E ku idirun o
C) E o ta o
D) Ojugbooro o
  • 31. 31. Olori awọn onisango ni.......
A) Onisango
B) Adosu
C) Alawo
D) Abore
  • 32. 32. Omo ti a bi tele awọn Ibeji ni
A) Idore
B) Idoha
C) Idowu
D) Idogbe
  • 33. 33. Ewi alohun ti o maa n so itan idile, eewo, esin tabi orirun eni ni.....
A) Orin
B) Oriki idile
C) Afose
D) Arangbo
  • 34. 34. Omo melo ni Okanbi bi?
A) Meje
B) Mejila
C) Mefa
D) Mesan
  • 35. 35. Ewo ni o je ode, ti o si lowo julo ninu awọn omo Okanbi?
A) Oranmiyan
B) Orangun
C) Alaketu
D) Onipopo
  • 36. 36. Ewo ninu awọn orisa ile Yoruba ni obinrin ko gbodo foju ri? Orisa
A) Oro
B) Ogun
C) Obatala
D) Osun
  • 37. 37. Awon eya Yoruba wo lo maa n da ege?
A) Ibarapa
B) Egba
C) Osun
D) Oyo
  • 38. 38. Litireso alohun to je mo ere omode
A) Esa
B) Iwerende
C) Ijala
D) Iwi
  • 39. 39. Eni ti o tumo Bibeli oyinbo si ede Yoruba ni.....
A) Adebayo Faleti
B) Obafemi Awolowo
C) Orisayemi Elebubon
D) Samuel Ajayi Crowther
  • 40. 40. Ewo ninu awọn won yii ni akoto ode oni?
A) Aye
B) Otta
C) Pepeiye
D) Shokoto
  • 41. 41. Ninu iwe onitan Igba Otun, kini oruko eni ti o n so nnkan to sele sii?
A) Eegunleti
B) Tayelolu
C) Ejire ara Isoku
D) Alabi
  • 42. 42. Kini oruko inagije ti won n pe onsotan ni Ile iwe re?
A) Kukute
B) Kukuru sanbe
C) Kerebete
D) Ageku ejo
  • 43. 43. Kini o mu ki inu onsotan yii dun gidigidi leyin ti oun ati baba re mu lo si ile eko ? Nitori pe
A) Baba re je oloye
B) O je okunrin
C) O kuro nile
D) O bere ile eko
  • 44. 44. Omo odun melo ni onkowe yii nigba ti o bere ile iwe? Odun
A) Mewa
B) Mejila
C) Mejo
D) Mefa
  • 45. 45. Iru ere idaraya wo ni awọn odokunrin ilu Apewo feran lati maa se ni odoodun?
A) Ere boolu
B) Ere sisa
C) Ijakadi
D) Ayo tita
  • 46. 46. Iru ise wo ni o so Aduke di olokiki ni ilu Apewo? Ise
A) Alagbafo
B) Aponmita
C) Onidiri
D) Akole
  • 47. 47. Oruko wo ni awọn ara ilu tun maa n pe Aduke onidiri laarin ilu Apewo?
A) Alabaro
B) Onirun
C) Alamo
D) Atorise
  • 48. 48. So ipari oro yii "alakowe to de tai morun, ebi ni ko...... " .
A) Soro fun
B) Paa
C) Muu
D) Moo
  • 49. 49. Ise wo ni o lokiki julo nilu Apewo?
A) Ise Oluko
B) Ise agbe
C) Ise onidiri
D) Ise akowe
  • 50. 50. Pari owe yii "Tebi ba ti kuro ninu oro,...."
A) Ise n po sii
B) Ise farapamo
C) Ise lo
D) Ise buse
  • 51. 51. Tani onkowe iwe ere onise "Obinrin Sowa Nu"
A) Kareem Adepoju
B) Adeniyi Adepeju
C) Taiwo Idowu
D) Ganiyu Idowu
  • 52. 52. Ninu iwe ere onise "Obinrin Sowa Nu", kini oruko iya Asake?
A) Amoke
B) Mojere
C) Amope
D) Folasade
  • 53. 53. Kini o n fa ibanuje fun baba Asake?
A) Iwa buruku ti Iyawo re n hu ninu ile ati nita
B) Iyawo re loyun fun elomiran
C) Iyawo re bimo ku
D) Iwa ole ti o n hu
  • 54. 54. Omo melo ni iya Asake bi fun baba Asake?
A) Mefa
B) Marun
C) Merin
D) Meji
  • 55. 55. Ikini o faa ti iya Asake fi ko awọn omo re kuro ni ile-iwe ti oko re fiwon si?
A) Tori pe ko San owo ile iwe awọn omo naa fun taamu meta
B) Awon tisa ibe n gba abetele
C) O ba oga ile iwe naa ja
D) Ikan ninu awọn omo re jale
  • 56. 56. Kini oruko ile eko ti iya Asake pada ko awọn omo re lo? Ile eko
A) Adara Lola Sukuu
B) Ajanlekooko kileoasinmi Sukuu
C) Adarisapa Abela Sukuu
D) Olorunsogo Hayi Sukuu
  • 57. 57. Ewo ninu awọn omo iya Asake lo maa n hu iwa daadaa?
A) Asake
B) Adeola
C) Folake
D) Sule
  • 58. 58. Kini oruko baba Asake?
A) Adigun
B) Akanbi
C) Alani
D) Alabi
  • 59. 59. Ninu igbagbo awọn Yoruba, Ibo ni a mo si ile Ogun?
A) Ilu lEko
B) Ilu bIwo
C) Ile ife
D) Ile Aro
  • 60. 60. Bawo ni a se n ki awọn babalawo ni ile Yoruba?
A) E ku ise o
B) E ku awọn o
C) Arinpa ni togun o
D) Aboruboye o
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — a math test site for students of all grade levels.