PES Yoruba JS 2 First Term Exam 2025
  • 1. Ewo ninu awon gbolohun won yii ni kii se gbolohun Ase?
A) Omo ilu Eko ni mi
B) Omo tuntun, alejo aye
C) Jade sita
D) Bola ti jeun tan
  • 2. Ewo ni kii se orisii gbolohun ninu awon won yii? Gbolohun
A) Alapetan
B) Onibo
C) Alabode
D) Alakanpo
  • 3. Oro asopo ninu gbolohun :" Baba mi ti ba oko mi soro, amo ko gboran si won lenu" ni
A) oko mi
B) baba
C) soro
D) amo
  • 4. Ewo ni gbolohun ase ibeere ninu awon gbolohun won yii?
A) Mo ti de sile o
B) Ise Oluwa,awamaridi ni
C) Ojogbon ni mi
D) Ta lo pe o?
  • 5. "Eran ti mo ra ti salo "- iru eya gbolohun wo ni yii? Gbolohun
A) Alabode
B) Onibo
C) Asafihan
D) Alakanpo
  • 6. Ewo ni gbolohun afihan ninu awon gbolohun won yii?
A) Ni iranti mama mi
B) E ku oju lona o
C) E kuro ni ile wa
D) Emi ni akobi baba mi
  • 7. Iru orin wo ni eyi-
    " Omo to moya re loju o osi ni yoo ta omo naa pa, Iya to jiya pupo lori re, Omo to jiya pupo" Orin
A) Isile
B) Imototo
C) Iwa rere
D) Amuseya
  • 8. Ewo ni kii se orisii orin ninu awon won yii?
A) Orin onka
B) Orin amuto
C) Orin eremode
D) Orin Igbeyawo
  • 9. Ohun pipe ti awon baba-nla wa n lo nibi ayeye ti ko jemo esin orisa tabi eyi ti won n ko nibi ti won n ti n bo orisa kan ni a n pe ni........
A) Isare
B) Iyere ifa
C) Arangbo
  • 10. Ewo ninu awon won ni kii se isare Ajemesin?
A) Iwi
B) Arungbo
C) Alamo
D) Ijala
  • 11. Awon ilu wo ni o maa n ko orin obintu?
A) Oyo
B) Ondo
C) Egbs
D) Ilaje
  • 12. Awon...... ni o n sun iyere ifa
A) babalowo
B) Olosun
C) Oloya
D) Onisango
  • 13. Ewo ni kii se ohun eelo fun orin ifa ninu awon nnkan won yii?
A) Fere
B) Ilu agere
C) Agogo
D) Ilu bata
  • 14. Won maa n pe oku nigba ti won maa n ..... olele
A) ko
B) mu
C) so
D) wi
  • 15. Tani olori awon elesin Sango?
A) Adosu
B) Babalowo
C) Abore
  • 16. Iru ilu wo ni awon onisango maa n lu ti won ba n sodun won?
A) Ilu bembe
B) Ilu gangan
C) Ilu bata
D) Ilu dundun
  • 17. Awon wo ni o ni o maa n pe Esu? Awon
A) Aworo
B) Olosun
C) Onifa
  • 18. Ewo ninu awon nnkan won yii ni kii se ami orisa Oya?
A) Edun ara funfun
B) Irun agbo
C) Igba ademu
D) Iwo efon
  • 19. Ewo ninu awon won yii ni eewo orisa Esu?
A) Adi ati omi
B) Adi ati obi
C) obi ati epo
  • 20. Ewo ninu awon orisa won yii ni obinrin ko gbodo ri?
A) Sango
B) Egungun
C) Oro
  • 21. Oji le leedegbeta ni figo je....
A) 450
B) 504
C) 580
D) 540
  • 22. 170 ni onka je
A) Aadoje din mewa
B) Ogojo din mewa
C) Ogofa din mewa
D) Ogosan din mewa
  • 23. 35 + 76 = ? Kin ni esi aropo awon figo yii ni onka Yoruba?
A) Ookan le logofa
B) Ookan le loodunrun
C) Ookan din loodunrun
D) Ookan le laadofa
  • 24. Onise wo ni a n ki ni " Oju gbooro o"?
A) "Onisegun"
B) "Awako"
C) "Olode"
D) "Onidiri"
  • 25. Bawo ni a se n ki awako?
A) "Awaye o "
B) "Asokale anfaani o"
C) "Ese a tele layo o "
D) "Owo a de o "
  • 26. Bawo ni a se n ki awon eniyan nibi isinku?
A) "E ku asedinde o"
B) "E ku oriire o "
C) "E ku olojojo
D) "E ku ijomo "
  • 27. Egberun ni figo je
A) 3000
B) 2000
C) 1000
D) 4000
  • 28. Ki ni ihun oro KF duro fun?
A) Faweeli+Konsonanti
B) Konsonanti+ Foniimu
C) Foniimu + Faweeli
D) Konsonanti+ Faweeli
  • 29. Olu sun je ihun oro oruko ati.......
A) aponle
B) oro ise
C) alakanpo
D) apola atokun
  • 30. Gbolohun Alabode maa n ni
A) eyo oro ise kan soso
B) oro ise ati eyan
C) oro ise pupo
D) ibeere ati idahun
  • 31. Orisii gbolohun inu ede Yoruba ni : Gbolohun
A) Alabode, Onibo , Alakanpo
B) Alakanpo, onoboafi ati
C) Alaye, alapeere ati onibeere
D) Onibo ,kukuru, at igogun
  • 32. Ewo ninu awon igbese won yii ni ko si ninu Igbeyawo kootu?
A) Ikede
B) Fifi oruko sile
C) Idanileko
D) Igbeyawo ninu yara kootu
  • 33. Iru Igbeyawo wo ni kii se ti ode oni? Igbeyawo
A) Mosalasi
B) Ibile
C) Soosi
D) Kootu
  • 34. Ofin Igbeyawo kootu ni pe
A) Oko ko lee ko iyawo sile ni ilana to yato si ofin ijoba
B) Oko ko lee ko iyawo sile ayafi to ba fe iyawo miran
C) Oko lee ko iyawo sile pelu ase awon obi tie
D) Oko ko lee ko iyawo sile ni ilana ti ko yato si ti ofin soosi
  • 35. Iru Igbeyawo wo ni oko gbodo san sadaki? Igbeyawo
A) Kootu
B) Soosi
C) Ibile
D) Mosalasi
  • 36. Awon onise wo ni Yoruba maa n ki pe " Arinpa ni togun o" ?
A) Ode
B) Agbe
C) Alagbede
D) Awako
  • 37. Asiko wo ni a maa nki awon eniyan bayii ? " E ku ogbele yi o".
A) Ni asiko ooru
B) Ni asiko ojo
C) Ni asiko oye
D) Ni asiko odun
  • 38. Iru orin wo ni awon ewe maa n ko nigba ti won ba n sere osupa? Orin
A) Idupe fun obi
B) Eremode
C) Idaraya
D) Iwa rere
  • 39. Ewo ninu awon isare won yii ni akoonu re ni oriki/oro nipa Orunmila ninu?
A) Ijala ode
B) Olele
C) Esu pipe
D) Iyere ifa
  • 40. Nigba wo ni won maa n ko orin gelede? Nigba
A) odun egungun
B) odun keresi
C) odun ifa
D) odun isu
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.