Yoruba Jss3 3rd test 1st term 2026/27
  • 1. ____ ni ija laarin awọn eniyan kan ni ilu tabi orilede
A) Ijamba
B) Agidi
C) Aigboran
D) Ogun
  • 2. _______ ma n sofo Ni igba ogun ayafi
A) Dukia
B) Emi
C) Ere oko
D) Ojo ori
  • 3. Awọn ohun ijagun ni iwọn yii ayafi
A) Ofa
B) Ibon
C) Omorogun
D) Obe
  • 4. Anfaani ogun jija ni
A) O n mu ni mo awon alagbara ilu
B) O n fa ki obinrin pọ ju ọkunrin lọ
C) On je ki eniyan lowo si
D) O je ki ilu di ahoro
  • 5. Awọn ohun ti o nfa ogun ni iwonyi ayafi
A) Irenije
B) Yiye adehun
C) Igbafunra eni
D) Ija lori ile
  • 6. ______ ni afi ti a fi ohun tó dùn ko,ti o sì dùn gbo leti ati kò sí ta
A) Ekun
B) Aro
C) Orin
D) Ofo
  • 7. Orin t a máa kó fún ìyàwó, omoge tabi Abileko la ti fi kọ wọn leko ni
A) Orin ijakadi
B) Orin Igbeyawo
C) Orin idagbere
D) Orin iremolekun
  • 8. Orin ti awọn oṣiṣẹ ma n ko lẹnu iṣẹ ni
A) Orin amuseya
B) Orin aajo
C) Orin ijakadi
D) Orin iremolekun
  • 9. Àpẹẹrẹ orin ìwà rere ni....
A) Omo to moya re loju o ,iṣẹ ni yi o tomo na pa
B) Ki ni nleje...... Leje n leje.....
C) Ile ọkọ ya o, ile ọkọ ya,keleda re sìn ọ dé bè, ile oko ya....
D) Ijo kin bá jó, ara kin bá dá.......
  • 10. Awọn ewi alohun arangbọ kikun ni iwonyi, ayaafi
A) Ofo
B) Ijala
C) Oriki
D) Ekun
  • 11. ___ ni ewi alohun ti a fín se aponle eniyan,igi,eranko , ounje,ilu ati beebeelo
A) Oriki
B) Ekun
C) Ofo
D) Orin
  • 12. Pari oriki yi. "agun_____________
A) Taso lo
B) To okun ifami
C) To igi ope
D) To ilẹkẹ di
  • 13. "A bi inu funfun _________
A) Bi burẹdi oyinbo
B) Bi iresi àkara dindin
C) Bi aha emu
D) Bi iyan ale
  • 14. Tani won man kii pe "Ibadi Aran"
A) Àrúgbo obinrin
B) Odomokunrin
C) Omoge
D) Eranko
  • 15. Ta ni a máa n ki bayii" omo bi iya le ku o ku, bi baba le lo o lọ......
A) Dada
B) Ige
C) Ibeji
D) Aina
  • 16. Oriki "Iyan" ni
A) O wewu ila, o de fila iru
B) O lẹ po bi iyepe amo
C) Kokoro funfun ona ofun
D) O soju tuetue
  • 17. Àpẹẹrẹ oriki eleyo oro kan ni
A) Èjì woroko loju iya re
B) Ẹni bẹ Adubi nise,ara re lo be
C) Ajadi
D) Okunrin gbongbonran bi ike
  • 18. Àwọn òrìṣà ilẹ yoruba ni iwonyi ayafi
A) Oduduwa
B) Ogun
C) Esu
D) Obatala
  • 19. Pataki esin láwùjọ ní.......
A) Esin n da ota sile lawujọ
B) Esin n fa ogun
C) Esin ko ni ni iwa janduku
D) Esin ko ni ni iwa rere
  • 20. Àwọn ọdún tí Musulumi ma n se ni iwọnyi, ayafi
A) Odun ileya
B) Odun ajinde
C) Odun itunu awe
D) Odun ijira
Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.