PES Yoruba JSS 3 Mock 2 Exam (Obj) 2025/2026
  • 1. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.

    Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá.
    Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà.
    Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.

    Ohun ti awon eniyan so pe o pa Alade ni iwon yii, ayafi.....
A) Ogun ni ibi ise
B) Aisan jedojedo
C) Iyawo re
D) Ogun idile
  • 2. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.

    Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá.
    Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà.
    Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.

    Bawo ni eni ti o n se alaye yii se je si Alade ?
A) Alabagbe
B) Egbon
C) Aburo
D) Ore
  • 3. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.

    Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá.
    Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà.
    Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.

    Itumo "sokunkun" gege bi a se lo o ninu ayoka yi ni ki nnkan.......
A) farasin
B) daamu
C) ruju
D) dojuru
  • 4. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.

    Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá.
    Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà.
    Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.

    Ta ni o jebi iku ninu ayoka yi i?
A) Awon agborandun
B) Aburo Alade
C) Iyawo Alade
D) Alade
  • 5. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.

    Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá.
    Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà.
    Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.

    Itumo alakeji gege bi a ti lo o ninu ayoka yi ni......
A) Ajo
B) Oke
C) Saare
D) Orun
  • 6. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.

    Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá.
    Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà.
    Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.

    Ohun ti eni ti o ko ayoka yi ni o se pataki ju ni ki.......
A) eeyan yago fun molebi
B) awuyewuye maa n waye leyin iku eda eniyan
C) aburo rere gbeyin eda
D) iku ka ise rere mo wa lowo
  • 7. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.

    Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá.
    Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà.
    Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.

    Oro ti o dun eni ti o ko ayoka yi ni.....
A) iku ojiji ti Alade ku
B) aibikita fun oogun Ibile
C) gbigba esin ajoji
D) ebi ti awon eniyan n da Alade leyin iku re
  • 8. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.

    Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá.
    Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà.
    Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.

    Ta ni o maa n jebi leyin iku?
A) Iyawo eni to ku
B) Molebi alaisi
C) Ore oloogbe
D) Eni to ku
  • 9. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.

    Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá.
    Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà.
    Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.

    "Ohun ti o sokunkun si eda, kedere ni o han si Olorun". Ki ni gbolohun yi tumo si ninu ayoka oke yii?
A) Iyawo Alade ni o pa a
B) Ore ni o pa a
C) Iku ti o pa Alade, o ye Olorun
D) Ogun ibi ise ni o pa a
  • 10. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.

    Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá.
    Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà.
    Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.

    Akole wo ni o ba ayoka yi mu ninu awon won yii?
A) Alagborandun
B) Iku ojiji
C) Eni Olorun o pa kii ku
D) Ta lo pa enire
  • 11. "Ijoba alagbada dara ju ijoba oloogun lo", je aroko........
A) alalaye
B) alariyanjiyan
C) asotan
D) oniroyin
  • 12. "Ile eko mi " je apeere ori oro fun aroko......
A) Alapejuwe
B) Asotan
C) Onisorongbesi
D) Oniroyin
  • 13. Ewo ni konsonanti airanmupe ninu awon won yii?
A) T
B) W
C) M
D) H
  • 14. Faweeli 'U' je faweeli.....
A) iwaju
B) egbe
C) aarin
D) eyin
  • 15. Ewo ni faweeli arehon ninu awon won yii?
A) R
B) P
C) T
D) M
  • 16. Konsonanti/F/ je konsonanti.......
A) afunnupe
B) arehon
C) afeyinpe
D) ayanupe
  • 17. Batani silebu wo lo wa ninu 'olongbo'?
A) FK(n)KF
B) FKF(n)KF
C) FKFKF
D) FKK(n)KF
  • 18. Oro ti o n se afikun itumo oro oruko ni .........
A) eyan
B) apejuwe
C) atokun
D) ise
  • 19. Silebu melo lo wa ninu " agidingbi"?
A) Meje
B) Marun
C) Merin
D) Mefa
  • 20. Eedegberin ni figo je.....
A) 500
B) 800
C) 700
D) 900
  • 21. Orin le logowa
A) 2008
B) 208
C) 2080
D) 2800
  • 22. Ki a ro oodun ati irinwo Papo, esi re je......
A) Eedegberin
B) Eedegberun
C) Eedegbefa
D) Eedegbeta
  • 23. Ti a ba pin egberun si ona merin,ipin kan je.......
A) Ookan le nigba
B) Ota le nigba din mewa
C) Orin leerugba din mewa
D) Oji leerugba le mewa
  • 24. Ki ni aropo awon figo won yii ni onka Yoruba,?
    35 + 17. = ?
A) Aarun din logota
B) Eerin din logbon
C) Eeta din logoji
D) Eeji le laadota
  • 25. Melo ni faweeli ede Yoruba?
A) Marun
B) Meje
C) Mefa
D) Mesan
  • 26. Oro ti a n lo dipo oro - oruko ni oro........
A) aropo - oruko
B) ise
C) afarajoruko
D) asopo
  • 27. Iya Titi lo ata olowo. 'Titi' ninu gbolohun yi je eyan
A) asonka
B) asaponle
C) oruko
D) asapejuwe
  • 28. Mo ti jeun, amo n ko yo. Ki ni oro - asopo ti o wa ninu gbolohun yi i?
A) ko
B) yo
C) jeun
D) amo
  • 29. Iwe meta ni Bola mu wa si ile iwe loni. 'Meta' ninu gbolohun je eyan.......
A) asafihan
B) asapejuwe
C) onibatan
D) asonka
  • 30. Bi a a ba da meedogbon mo eeta le logoji, esi je
    .............
A) Marun din laadota
B) Meji le logorin
C) Meta le logowa
D) Meji din laadorin
  • 31. Ewo ni faweeli ayanudiepe ninu awon won yii?
A) D
B) T
C) Y
D) A
  • 32. Ile yen ni Kola ra. 'yen' ninu gbolohun yi je eyan.....
A) asafihan
B) asapejuwe
C) asaponle
D) asonka
  • 33. Baba je amala, gbegiri 'ati' eran - igbe. 'Ati' ninu gbolohun yi je oro ........
A) atokun
B) aponle
C) asopo
D) afihan
  • 34. Ewo ni konsonanti asesilebu ninu awon won yii?
A) b
B) g
C) f
D) n
  • 35. Okunrin naa ga fiofio. 'fiofio' je isori oro......
A) asafihan
B) apejuwe
C) aponle
D) atokun
  • 36. 'Eniyan laso mi ' tumo si.....
A) Ore mi
B) Aso ibora mi
C) Iyi ati eye mi
D) Aso imurode mi
  • 37. O na papa bora timo si ......
A) O fi koriko bora
B) O n sa fun awon eniyan
C) O wo inu igbo lo
D) O salo
  • 38. Akojopo oro ti o ni itumo ni .........
A) Silebu
B) Oro oruko
C) gbolohun
D) Apola oro oruko
  • 39. Oro ti a n lo lati fi so oro tabi gbolohun meji papo ni......
A) oro oruko
B) isori oro
C) isunki
D) eyan
  • 40. Olu wa ni faranda. Ise wo ni 'ni' n se ninu gbolohun yi i?
A) Apejuwe
B) Aponle
C) Atokun
D) Eyan
  • 41. Omo meji ti a bi papo lojo Kan naa ni a n pe ni.....
A) Alaba
B) Eta - oko
C) Ige
D) Ibeji
  • 42. Ise ajose ti ko ni owo tabi sise ise pada ni......
A) Owe
B) Ajo
C) Arokodoko
D) Aaro
  • 43. Iru igi wo ni a fi n gbe gbedu? Igi
A) Ose
B) Iroko
C) Gedu
D) Omo
  • 44. Osu Beelu ninu onka osu je osu .......
A) kokanla
B) Keji
C) Kejo
D) Keta
  • 45. Ojo Isegun ni....... ni ede geesi .
A) Thursday
B) Sunday
C) Tuesday
D) Saturday
  • 46. Ewi alohun ti o wopo laarin awon ode ni......
A) Ijala
B) Dadakuada
C) Bolojo
D) Arungbe
  • 47. Pelu igbagbo Yoruba, 'sekere ki i rode.......'
A) Ija
B) Ijo
C) Ibanuje
D) Iyawo
  • 48. Orisa ti o lana fun awon orisa to ku lati orun wa si aye ni.....
A) Osanyin
B) Esu
C) Ogun
D) Obatala
  • 49. Lara iwa omoluabi ni...
A) Ibowo - fagba
B) Arifin
C) Afojudi
D) Iro - pipa
  • 50. Afoju feni ma fokan feni ni......
A) ota eni
B) omo iya eni
C) ara ile eni
D) omo araye
  • 51. Pari owe yi " Oju ti yoo bani kale, .........."
A) ko ni yun eeyan laaro
B) kii sun
C) ko nii fi aaro sepin
D) yoo la sile kedere
  • 52. Owo genge ni i saaju......
A) eke
B) ijo
C) ejo
D) ija
  • 53. Omo kan soso ti Oduduwa bi ni.....
A) Okanbi
B) Alaketu
C) Oranmiyan
D) Agbonmiregun
  • 54. Ja alo yi: " Iya repete to joko laarin egun". Ki ni o?
A) Oorun
B) Irawo
C) Osupa
D) Osumare
  • 55. Omo ti a bi, ti o wa ninu apo ni Yoruba n pe ni......
A) Ajayi
B) Idowu
C) Oke
D) Idogbe
  • 56. Omo ti o ni ika mefa ni a n pe ni....
A) Olugbodi
B) Ojo
C) Ige
D) Okanran
  • 57. Onise wo ni a n ki ni "Aredu o"?
A) Alaro
B) Ode
C) Apeja
D) Agbe
  • 58. A se efe, nigba ti a n da......
A) ofo
B) iyere
C) ege
D) orin
  • 59. Ewo ni oruko amutorunwa ninu awon won yii?
A) Sangodeyi
B) Adetola
C) Taye
D) Omowumi
  • 60. Ti a ba ki onidiri ni - Oju gbooro o, won a si dahun pe -------
A) Iyamapo a gbe o o
B) Ogun a gbe o o
C) Ooya o yaa o.
D) Ase o
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — a math test site for students of all grade levels.