Yoruba Jss2 1st term exam 2026/27
  • 1. Ninu ewi ,"Dakun gba ìkìlọ" tani akéwì n ba wi
A) Onisowo
B) Awọn arugbo
C) Oluko
D) Awọn omode
  • 2. Pari awọn ọrọ wonyi ti o wa ninu ewi na. " Bi iya n ko o, ______
A) Ki o ma rerin
B) Dakun gbeko
C) Dakun gbọn eti
D) Ki o salo
  • 3. "Aja ti yi o sonu, ________
A) Ko ni gbo
B) Ko ni gbọ fere olode
C) Ko ni jegbe
D) Ko ni sun ile
  • 4. "Ọrẹ rerunrerun a má ___________
A) Mu ni lo ilu Oyinbo
B) Da bo bo eni
C) Fún ni lowo
D) Koba ni
  • 5. " ohun ti o ko mo, _______
A) Awọn Ọrẹ rẹ mo
B) Ma n mu ni gbon
C) Awọn Obi re mo
D) Ko le seku pa ni
  • 6. "Aigba ìkìlọ,________
A) A má mu ni gbon
B) O n so ni d'oga
C) A má seku pa ni
D) Ọlọre ninu
  • 7. _____ ni àyọkà tí a kà ti kọkọ ati èdè inú rẹ yè ni yékéyéké
A) Leta
B) Iroyin
C) Àròkọ
D) Akaye
  • 8. Akaye máa n ni ______ leyin
A) Orin
B) Idahun
C) Ibeere
D) Aalo
  • 9. Ninu ewi " Ẹwà wo àgúnfon" ta ni akewi n ba wi
A) Oluko
B) Awọn onisowo
C) Akeko
D) Awọn ode
  • 10. Pari awọn ọrọ wọnyi ni ni ewi na" ki lo de to n deju ______
A) Kahunkahun
B) Ran jú
C) Raurau
D) rekese
  • 11. "Olodo ọmọ, _________
A) Ranjú ran
B) Seranko seniyan
C) Ọlọrun gun
D) Seku seja
  • 12. "E ni ba fiṣe sere, _________
A) Yi te tẹ dagba
B) Yi o fiṣe sore
C) Yi o já fa fa
D) Yi o di olowo
  • 13. "Fi eko sawada ,_______
A) Ki o di at'ọrọ eko je
B) Ki ọkàn rẹ le ba le
C) Ki o lè yo bamubamu
  • 14. Ko onka yii ni ede Yoruba "110"
A) Ogofa
B) Aadofa
C) Aadota
D) Ogota
  • 15. "170"
A) Ogoje
B) Aadoje
C) Aadosan
D) Ogojemewa
  • 16. "240"
A) Eerinlenigba
B) Ojilenigba
C) Igbaogoji
D) Ojidinnigba
  • 17. "216"
A) Okolenigbadinmerin
B) Adowadinmefa
C) Okolenigbalemefa
D) Okolenigbalemerin
  • 18. "227"
A) Ogundinnigbalemeje
B) Okolenigbadinmeje
C) Okolenigbadinmeta
D) Mejelenigbalemeje
  • 19. Ki ni ojo "Monday"ni yoruba
A) Aiku
B) Belu
C) Ibe
D) Aje
  • 20. "Wednesday"
A) Ogoru
B) Ojoru
C) Ope
D) Sere
  • 21. Bawo ni a ṣe máa n ki awon onise owo wonyi
    "Awako"
A) Awaye o
B) E kú moto gigun
C) E kú oko wiwa
D) E kú ere sisa
  • 22. "Oluranso"
A) A mú ni da ra o
B) A tún ara se o
C) E kú aso riran
D) E kú aso gige
  • 23. "Agbe"
A) Eku wahala o
B) A roko bo dun De o
C) Eku imebi kuro
D) Agbe loba a
  • 24. Ba wo ni a ṣe ma ki eni ti o bá loyun
A) E kú ẹrù omo
B) Ese a tele layo
C) E kú ọwọ lomi
D) E kú atemora
  • 25. Eni tí ènìyàn ku
A) E kú idagbere
B) E kú alejo
C) E kú ẹkun sisun
D) E kú a seyinde
  • 26. E ni ti o n gba awe
A) E kú igbadun
B) E kú Imenu duro
C) E ku ebi pipa
D) E kú ipanumo
  • 27. Oríṣi gbólóhùn melo lowa
A) Mefa
B) Marun
C) Meji
D) Meta
  • 28. "Olu lo sí ọjà" iru gbólóhùn wo ni eyi?
A) Gbólóhùn alabode
B) Gbólóhùn penpele
C) Gbólóhùn ránpẹ́
D) Gbólóhùn alakanpo
  • 29. "Omo yii rẹwa"
A) Gbólóhùn alakanpo
B) Gbólóhùn nla
C) Gbólóhùn alabode
D) Gbólóhùn kekeke
  • 30. "Tope ati titi je ẹwà"
A) Gbogbo eleyo
B) Gbólóhùn olopo
C) Gbólóhùn onibo
D) Gbólóhùn alakanpo
  • 31. "Tosin wa sugbon ko jeun"
A) Gbólóhùn onibeji
B) Gbólóhùn onibo
C) Gbólóhùn eleyo
D) Gbólóhùn alakanpo
  • 32. "Iwe ti móra tí sọ nù"
A) Gbólóhùn eleyo
B) Gbólóhùn alakanpo
C) Gbólóhùn onibo
D) Gbólóhùn alalaye
  • 33. "Ilẹ tí wọn kò ti wo"
A) Gbólóhùn àkíyèsí
B) Gbólóhùn oloropupo
C) Gbólóhùn alabode
D) Gbólóhùn onibo
  • 34. "Bose wa sugbon ko joko", oro-ise melo lo wa ninu gbólóhùn yìí
A) Ko si rara
B) Meta
C) Oyokan
D) Meji
  • 35. "Oúnjẹ ti mo ṣe ti danu"ki ni àfibò inú gbólóhùn yii
A) Ti mo ra
B) Oúnjẹ
C) Ti da nu
D) Oúnjẹ ti danu
  • 36. "Oko ti ade ra naa wù mi" ki ni olori gbólóhùn
A) Ti ade ra
B) Oko naa wù mi
C) Ade wu mi
D) Ade ra naa
  • 37. "Bata ti mo wo tuutun" ki ni afibo gbólóhùn yii
A) Ti mo wo
B) Bata ti mo ra
C) Tuntun
D) Bata
  • 38. "Olu ati Ayo wo oríṣi aso kan naa", Oro oruko melo lowa ninu gbólóhùn yìí?
    "
A) Eyokan
B) Meta
C) Merin
D) Meji
  • 39. "Olu oun solà ni won je Isu ati epo "oro oruko melo lowa ninu gbólóhùn yii
A) Meta
B) Meji
C) Merin
D) Marun
  • 40. Gbólóhùn Onibo = ________ + ______
A) Abo gbólóhùn+ odidi gbólóhùn
B) Olori gbólóhùn+ àfibò gbólóhùn
C) Iwaju gbólóhùn + eyin gbolohun
D) Ilaji gbólóhùn+ ẹkun gbólóhùn
Created with That Quiz — the site for test creation and grading in math and other subjects.