Yoruba JSS1 3rd test 1st term 2026/27
  • 1. Gbogbo Konsonanti ede Yoruba je ........
A) Marun din logun
B) meedogbon
C) meji din logun
D) meedogun
  • 2. Konsonanti ti o gbeyin alifabeeti ede Yoruba ni..........
A) B
B) D
C) T
D) Y
  • 3. Ewo ninu awon won yii ni ko si ninu alifabeeti ede Yoruba?
A) T
B) P
C) C
D) O
  • 4. 75 ni onka Yoruba je....
A) aarun le laadota
B) aarun din logorin
C) aarun din logoji
D) aarun din laadowa
  • 5. Ewo ninu awon oro won yii ni o ni faweeli aranmupe ninu?
A) Iyun
B) Baba
C) Odo
D) Ara
  • 6. Tani oba ati olori awon elesin iborisa ni ilu Meka?
A) Oduduwa
B) Agbonmiregun
C) Buraimo
D) Lamurudu
  • 7. Omo obinrin melo ni Okanbi bi?
A) Marun
B) Meta
C) Okan soso
D) Meji
  • 8. Ojo melo ni Oduduwa ati awon eeyan re lo ni ona nigba ti won kuro ni Meka lo si Ile Ife?
A) Ogoji ojo
B) Aadota odun
C) Aadorun odun
D) Aadorun ojo
  • 9. Ewo ninu awon omo Oduduwa ni o jogun ileke?
A) Okanbi
B) Olupopo
C) Orangun
D) Oranmiyan
  • 10. Ewo ninu awon won yii ni awon Yoruba gba gege bii babanla won?
A) Lamurudu
B) Okanbi
C) Oranmiyan
D) Oduduwa
  • 11. Iro faweeli ede Yoruba pin si iro
A) Airanmupe ati akunyun
B) Akunyun ati airanmupe
C) Aranmupe ati airanmupe
D) Afojuri ati aifojuri
  • 12. Ewo ni kii se iro faweeli aranmupe ninu awon won yii
A) In
B) Un
C) On
D) Mi
  • 13. Faweeli aranmupe inu alifabeeti ede Yoruba je
A) Marun
B) Meji
C) Mokanla
D) Meje
  • 14. Ewo ninu awon Konsonanti won yii ni a n fi ete mejeeji pe
A) S
B) D
C) B
D) T
  • 15. Iro.......... ni iro ti a n pe nigba ti ko si idiwo fun eemi ti a iro naa jade .
A) Silebu
B) Konsonanti
C) Faweeli
D) Ohun
  • 16. ______ ni a máa n ko dipo ọrọ oruko
A) Oro eyan
B) Oro ise
C) Oro asopo
D) Oro aropo oruko
  • 17. ________ ni o ma toka isele inu gbólóhùn
A) Oro oruko
B) Oro ise
C) Oro atokun
D) Oro aropo oruko
  • 18. Oro oruko le wa ní ipò wọnyi ayafi ______
A) Aarin
B) Oluwa
C) Eyan
D) Abo
  • 19. Àpẹẹrẹ ọrọ oropo afarajoruko
A) Awon
B) Mo
C) E
D) O
  • 20. Àpẹẹrẹ ọrọ àpèjúwe ni
A) Pupa
B) Jeun
C) Aja
D) Iwo
Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.