PES Yoruba JS 2 Term 1 Test 3
  • 1. Eedegbeta ni figo je....
A) 600
B) 500
C) 800
  • 2. 250 ni onka je
A) Ota din nigba
B) Ota le loodun
C) Ota leerugba din mewa
D) Ota din nigba le mewa
  • 3. 25 + 46 = ? Kin ni esi aropo awon figo yii ni onka Yoruba?
A) Ookan din laadorin
B) Ookan le logorin
C) Ookan le laadorin
  • 4. Onise wo ni a n ki ni " Aredu o"?
A) Alagbede
B) Akope
C) Alaro
  • 5. Bawo ni a se n ki awako?
A) Awaye o
B) Aroko bodunde o
C) Aroye o
  • 6. Bawo ni a se n ki eni ti o sese bimo tuntun ni ile Yoruba?
A) E ku oju lona o
B) E ku ijade oni o
C) E ku owo lomi o
  • 7. Iru orin wo ni eyi-
    " ile oko ya,
    Ile oko ya,
    Keleda iya re sin o lo
    Ile oko ya". Orin
A) Isile
B) Igbeyawo
C) Amuseya
  • 8. Ewo ni kii se orisii orin ninu awon won yii?
A) Orin ijala
B) Orin eremode
C) Orin onka
  • 9. Ohun pipe ti awon baba-nla wa n lo nibi ayeye ti ko jemo esin orisa tabi eyi ti won n ko nibi ti won n ti n bo orisa kan ni a n pe ni........
A) Iyere ifa
B) Isare
C) Arangbo
  • 10. Ewo ninu awon won ni kii se isare Ajemesin?
A) Ijala
B) Rara
C) Arungbo
  • 11. Awon ilu wo ni o maa n su ekun iyawo?
A) Egbs
B) Ondo
C) Oyo
  • 12. Awon...... ni o n sun iyere ifa
A) babalowo
B) Onisango
C) Olosun
  • 13. Ewo ni kii se ohun eelo fun orin ifa ninu awon nnkan won yii?
A) Obi
B) Ilu agere
C) Agogo
  • 14. Won maa n pe ESA nigba ti won maa n ..... Ijala
A) so
B) wi
C) sun
  • 15. Tani olori awon elesin Sango?
A) Abore
B) Babalowo
C) Adosu
  • 16. Iru ilu wo ni awon onisango maa n lu ti won ba n sodun won?
A) Ilu dundun
B) Ilu bembe
C) Ilu bata
  • 17. Awon wo ni o ni o maa n pe Esu? Awon
A) Aworo
B) Olosun
C) Onifa
  • 18. Tani iyawo Sango?
A) Esu
B) Oya
C) Osun
  • 19. Ewo ninu awon won yii ni eewo orisa Esu?
A) Adi ati omi
B) Adi ati obi
C) obi ati epo
  • 20. Ewo ninu awon orisa won yii ni obinrin ko gbodo ri?
A) Oro
B) Egungun
C) Sango
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — where test making and test taking are made easy for math and other subject areas.