Yoruba Jss2 3rd test 1st term 2026/27
  • 1. Ko onka yii ni ede Yoruba "110"
A) Ogofa
B) Ogota
C) Aadofa
D) Aadota
  • 2. "170"
A) Aadoje
B) Ogoje
C) Ogojemewa
D) Aadosan
  • 3. "240"
A) Ojidinnigba
B) Eerinlenigba
C) Ojilenigba
D) Igbaogoji
  • 4. "216"
A) Okolenigbalemerin
B) Okolenigbadinmerin
C) Adowadinmefa
D) Okolenigbalemefa
  • 5. "227"
A) Mejelenigbalemeje
B) Okolenigbadinmeje
C) Ogundinnigbalemeje
D) Okolenigbadinmeta
  • 6. Ki ni ojo "Monday"ni yoruba
A) Ibe
B) Aje
C) Belu
D) Aiku
  • 7. "Wednesday"
A) Sere
B) Ogoru
C) Ojoru
D) Ope
  • 8. Bawo ni a ṣe máa n ki awon onise owo wonyi
    "Awako"
A) Awaye o
B) E kú oko wiwa
C) E kú ere sisa
D) E kú moto gigun
  • 9. "Oluranso"
A) A mú ni da ra o
B) A tún ara se o
C) E kú aso gige
D) E kú aso riran
  • 10. "Agbe"
A) A roko bo dun De o
B) Eku imebi kuro
C) Agbe loba a
D) Eku wahala o
  • 11. Ba wo ni a ṣe ma ki eni ti o bá loyun
A) Ese a tele layo
B) E kú ọwọ lomi
C) E kú ẹrù omo
D) E kú atemora
  • 12. Eni tí ènìyàn ku
A) E kú ẹkun sisun
B) E kú alejo
C) E kú idagbere
D) E kú a seyinde
  • 13. E ni ti o n gba awe
A) E ku ebi pipa
B) E kú Imenu duro
C) E kú igbadun
D) E kú ipanumo
  • 14. Oríṣi gbólóhùn melo lowa
A) Meta
B) Mefa
C) Marun
D) Meji
  • 15. "Olu lo sí ọjà" iru gbólóhùn wo ni eyi?
A) Gbólóhùn alabode
B) Gbólóhùn penpele
C) Gbólóhùn ránpẹ́
D) Gbólóhùn alakanpo
  • 16. "Omo yii rẹwa"
A) Gbólóhùn kekeke
B) Gbólóhùn alakanpo
C) Gbólóhùn nla
D) Gbólóhùn alabode
  • 17. "Tope ati titi je ẹwà"
A) Gbólóhùn alakanpo
B) Gbogbo eleyo
C) Gbólóhùn onibo
D) Gbólóhùn olopo
  • 18. "Tosin wa sugbon ko jeun"
A) Gbólóhùn onibo
B) Gbólóhùn eleyo
C) Gbólóhùn alakanpo
D) Gbólóhùn onibeji
  • 19. "Iwe ti móra tí sọ nù"
A) Gbólóhùn eleyo
B) Gbólóhùn onibo
C) Gbólóhùn alalaye
D) Gbólóhùn alakanpo
  • 20. "Ilẹ tí wọn kò ti wo"
A) Gbólóhùn alabode
B) Gbólóhùn àkíyèsí
C) Gbólóhùn onibo
D) Gbólóhùn oloropupo
Created with That Quiz — the site for test creation and grading in math and other subjects.