JS 2 Ede Yoruba 1st Term Exam
  • 1. 1.ohun pipe ti awon babanla wa n lo ni idi esin orisa ni won n pe ni.......
A) Ohun pipe
B) Ofo
C) Arugbo
D) Isare
E) Afose
  • 2. 2. Awon wo ni o maa n sun ijala?
A) Babalawo
B) Onifa
C) Onilu
D) Ode
E) ologbojo
  • 3. 3. Awon........ ni o maa n pe esa
A) elesin guru
B) elesin Sango
C) elesin kanka
D) eleegun
E) olorisa ila
  • 4. 4. Olori awon onisango ni.....
A) elegbara
B) adosu
C) onisango
D) elesu
E) olota
  • 5. 5. Ewo ninu awon orisa wonyii ni iyawo orisa Sango? Orisa
A) Oya
B) Orisaala
C) Yemoja
D) Sanpona
E) Eelu
  • 6. 6. Orisa wo ni won n ki bayii" a bani wa Oran ba o ri da "?
A) Ogun
B) Oya
C) Ifa
D) Esu
E) Obatala
  • 7. 7. Ounje ti awon olusin oya maa n je ni
A) amala,gbegiri ati ewedu
B) iyan ewu ati obe isapa
C) eba ati obe egusi
D) amala ati obe ila
E) amala ati obe ilasa
  • 8. 8. Ki ni eewo orisa oro?
A) Obinrin ko gbodo rii
B) Awon eniyan ko gbodo soro
C) Oloro ko gbodo jeun
D) Ara ilu ko gbodo jade
E) Okunrin' ko gbodo soro
  • 9. 9. Tani olori oloro?
A) Alapinni
B) Eleegun
C) Adosu
D) Ajana
E) Elegun
  • 10. 10. Ki ni eewo adosu Sango? Kii je
A) Eran esuro
B) Eran ekute
C) Eran agbo
D) Eran adiye
E) Eran eja
  • 11. 11. Nigba wo ni won maa n ki iyere? Nigba
A) Odun ifa
B) Ti iyan ba mu
C) Ti ode ba ku
D) Odun oro
E) Apeje
  • 12. 12. Iru awon oro wo ni o maa n wa ninu ijala?
A) Ijuba ati orin
B) Oriki eye tabi igi ati adura
C) Orin eebu ati oriki
D) Awada ati eebu
E) Oro awada ati egun
  • 13. 13. Ewo ninu awon wonyii ni apeere isare ajemayeye
A) Ijala
B) Iyere
C) Iwi
D) Bolojo
E) Arungbe
  • 14. 14. Ki ni won n pe awon ti o n pe esu? Awon
A) alapini
B) oloosa
C) elesa
D) aworo
E) elegun
  • 15. 15. Orisa wo ni won tun n pe ni "Olukoso"
A) Esu
B) Sango
C) Yemoja
D) Ogun
E) Oya
  • 16. 16. Orisa wo ni o ni ami edun ara funfun
A) Ogun
B) Obatala
C) Sanpona
D) Oya
E) Esu
  • 17. 17. Ewo ninu awon wonyii ni ko si ninu isori oro ede Yoruba? Oro
A) Asopo
B) Oriki
C) Asapejuwe
D) Ise
E) Oruko
  • 18. 18. Okoo leerugba ni onka je
A) 118
B) 125
C) 220
D) 120
E) 330
  • 19. 19. Ookan le laadorin je
A) 101
B) 91
C) 71
D) 49
E) 21
  • 20. 20. Ki ni eerinla ni Figo?
A) 14
B) 16
C) 19
D) 12
E) 13
  • 21. 21. Ki ni ookan le logorun je?
A) 110
B) 411
C) 201
D) 111
E) 101
  • 22. 22. 137 ni onka je
A) eeta le loodunrun
B) eeta din loodunrun
C) eeta le legbeta
D) eeta din logoje
E) eeta le logoje
  • 23. 23. 110 je
A) Oodun
B) Ogofa
C) Aadofa
D) Ogowa
E) Ogota
  • 24. 24. Ro ogoji papo mo aadota, esi re je
A) Ogofa
B) Ogota
C) Ogorun
D) Aadorin
E) Aadorun
  • 25. 25. Baba, iya ati awon omo mejo je eniyan
A) Mewa
B) Merinla
C) Ogbon
D) mejila
E) meedogun
  • 26. 26. Meedogun + metadinlogbon je
A) Meta le logun
B) Meedogbon
C) Meji le logbon
D) aadorin
E) Merin din llogoi
  • 27. 27. Mewa Lona mewa je
A) Ogorin
B) Ogosan
C) Ogowa
D) Ogota
E) Ogorun
  • 28. 28. Aadosan ni figo je
A) 130
B) 130
C) 150
D) ,190
E) 170
  • 29. 29. Aadojo je
A) 350
B) 150
C) 250
D) 450
E) 550
  • 30. 30. Ookan leerugba
A) 201
B) 138
C) 129
D) 109
E) 149
  • 31. 31. Oro ti o n sise oluwa, abo atieeyan ninu gbolohun ede Yoruba ni oro
A) aropo oruko
B) ise
C) asapejuwe
D) Oruko
E) aponle
  • 32. 32. Oro ti a n lo ropo oro oruko ni oro
A) aropo oruko
B) asopo
C) apejuwe
D) aponle
E) oruko
  • 33. 33. Oro ti a fi n so oro meji papo ninu gbolohun ni oro
A) aropo
B) aponle
C) ise
D) oruko
E) asopo
  • 34. 34. Ki ni itumo noun no ede Yoruba? Oro
A) Aponle
B) Asopo
C) Aropo
D) Ise
E) oruko
  • 35. 35. Pronoun ni ede Yoruba ni oro
A) aropo oruko
B) asopo
C) abo
D) ise
E) eyan
  • 36. 36. Adjective ni ede Yoruba ni oro
A) asapejuwe
B) aponle
C) aropo oruko
D) asopo
E) asotan
  • 37. 37. Oro ise ni ........
A) adverb
B) pronoun
C) adjective
D) verb
E) Conjunction
  • 38. 38. Preposition ni ede Yoruba ni oro
A) asopo
B) ise
C) atokun
D) asotan
E) asoadun
  • 39. 39. Ewo ni oro oruko ninu gbolohun you?" Aja digbolugi lo bu Kola je
A) digbolugi ati Kola
B) Aja ati digbolugi
C) Digbolugi ati je
D) Aja ati bu
E) Aja ati Kola
  • 40. 40. Ewo ni o je oro aropo oruko ninu gbolohun you?" Ilu Ibini ni mo ti wa"
A) mo
B) ti
C) Ibini
D) ilu
E) wa
Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.