PES Yoruba JS 2 (Obj) 3rd Term Exam 2026
  • 1. AKAYE

    Ka àyọkà ìsàlẹ̀ yìí, kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.

    Òjó jẹ́ ọmọ ilú Ìlọ́rọ̀, ọ̀rẹ́ rẹ̀ jẹ́ ọmọ Agbélé. Òjó fẹ́ràn ọ̀rẹ́ rẹ̀ púpọ̀ nítorí isu, tòmátì, ata, àgbàdo àti ọ̀sàn tí ó máa ń fún un. Lọ́títọ́, iṣẹ́ àgbẹ̀ ni iṣẹ́ Aládé ,ṣùgbọ́n Òjó tí ó jẹ́ ọmọ ode kì í fún ọ̀rẹ́ rẹ̀ ní ẹran tí ó bá fi ìbọn pa nínú igbó nítorí wí pé, o ni i ninu ero re pe, òun ṣe wahálà púpọ̀ kí òun tó pa erán ni.
    Ní ọjọ́ kan bí Òjó ṣe ń gbé ẹran ọ̀yà tí ó fi tàkúté pa lọ sí ọjà láti tà ni ó bá pàdé Aládé tí ó ń kó iṣu àti ẹ̀fọ́ bò wá fún un. Òjó kò fẹ́ kí Aládé mọ ohun tí ó wà nínú àpò náà, ṣùgbọ́n Aládé kó iṣu àti ẹ̀fọ́ tí òun mú wá fún un sínú àpò. Ìgbà tí Aládé wo àpò ọ̀rẹ́ rẹ̀ ó bá ọ̀yà nínú àpò tí ó gbé lọ́wọ́. Ojú ti Òjó púpọ̀, inú sì bí Aládé fún irú ìwà tí Òjó ń hù.

    Báwo ni Òjó ṣe jẹ́ sí Aládé?
A) Egbon
B) Baba
C) Alabagbe
D) Ore
  • 2. AKAYE

    Ka àyọkà ìsàlẹ̀ yìí, kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.

    Òjó jẹ́ ọmọ ilú Ìlọ́rọ̀, ọ̀rẹ́ rẹ̀ jẹ́ ọmọ Agbélé. Òjó fẹ́ràn ọ̀rẹ́ rẹ̀ púpọ̀ nítorí isu, tòmátì, ata, àgbàdo àti ọ̀sàn tí ó máa ń fún un. Lọ́títọ́, iṣẹ́ àgbẹ̀ ni iṣẹ́ Aládé ṣùgbọ́n Òjó tí ó jẹ́ ọmọ ode kì í fún ọ̀rẹ́ rẹ̀ ní ẹran tí ó bá fi ìbọn pa nínú igbó nítorí wí pé, o ni ero pe, òun ṣe wahálà púpọ̀ kí òun tó pa erán ni.
    Ní ọjọ́ kan bí Òjó ṣe ń gbé ẹran ọ̀yà tí ó fi tàkúté pa lọ sí ọjà láti tà ni ó bá pàdé Aládé tí ó ń kó iṣu àti ẹ̀fọ́ bò wá fún un. Òjó kò fẹ́ kí Aládé mọ ohun tí ó wà nínú àpò náà, ṣùgbọ́n Aládé kó iṣu àti ẹ̀fọ́ tí òun mú wá fún un sínú àpò. Ìgbà tí Aládé wo àpò ọ̀rẹ́ rẹ̀ ó bá ọ̀yà nínú àpò tí ó gbé lọ́wọ́. Ojú ti Òjó púpọ̀, inú sì bí Aládé fún irú ìwà tí Òjó ń hù.

    Ewo ninu awon won yii ni ko si ninu ohun ti Alade n gbin ni oko re?
A) Aya
B) Ogede
C) Tomati
D) Agbado
  • 3. AKAYE

    Ka àyọkà ìsàlẹ̀ yìí, kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.

    Òjó jẹ́ ọmọ ilú Ìlọ́rọ̀, ọ̀rẹ́ rẹ̀ jẹ́ ọmọ Agbélé. Òjó fẹ́ràn ọ̀rẹ́ rẹ̀ púpọ̀ nítorí isu, tòmátì, ata, àgbàdo àti ọ̀sàn tí ó máa ń fún un. Lọ́títọ́, iṣẹ́ àgbẹ̀ ni iṣẹ́ Aládé ṣùgbọ́n Òjó tí ó jẹ́ ọmọ ode kì í fún ọ̀rẹ́ rẹ̀ ní ẹran tí ó bá fi ìbọn pa nínú igbó nítorí wí pé, o ni ero pe, òun ṣe wahálà púpọ̀ kí òun tó pa erán ni.
    Ní ọjọ́ kan bí Òjó ṣe ń gbé ẹran ọ̀yà tí ó fi tàkúté pa lọ sí ọjà láti tà ni ó bá pàdé Aládé tí ó ń kó iṣu àti ẹ̀fọ́ bò wá fún un. Òjó kò fẹ́ kí Aládé mọ ohun tí ó wà nínú àpò náà, ṣùgbọ́n Aládé kó iṣu àti ẹ̀fọ́ tí òun mú wá fún un sínú àpò. Ìgbà tí Aládé wo àpò ọ̀rẹ́ rẹ̀ ó bá ọ̀yà nínú àpò tí ó gbé lọ́wọ́. Ojú ti Òjó púpọ̀, inú sì bí Aládé fún irú ìwà tí Òjó ń hù.

    ki ni Alade fe fun Ojo nigba ti o ri oya ninu apo re ?
A) Isu ati efo
B) Agbado ati tomati
C) Ogedee ati epa
D) Ata ati isu
  • 4. AKAYE

    Ka àyọkà ìsàlẹ̀ yìí, kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.

    Òjó jẹ́ ọmọ ilú Ìlọ́rọ̀, ọ̀rẹ́ rẹ̀ jẹ́ ọmọ Agbélé. Òjó fẹ́ràn ọ̀rẹ́ rẹ̀ púpọ̀ nítorí isu, tòmátì, ata, àgbàdo àti ọ̀sàn tí ó máa ń fún un. Lọ́títọ́, iṣẹ́ àgbẹ̀ ni iṣẹ́ Aládé ṣùgbọ́n Òjó tí ó jẹ́ ọmọ ode kì í fún ọ̀rẹ́ rẹ̀ ní ẹran tí ó bá fi ìbọn pa nínú igbó nítorí wí pé, o ni ero pe, òun ṣe wahálà púpọ̀ kí òun tó pa erán ni.
    Ní ọjọ́ kan bí Òjó ṣe ń gbé ẹran ọ̀yà tí ó fi tàkúté pa lọ sí ọjà láti tà ni ó bá pàdé Aládé tí ó ń kó iṣu àti ẹ̀fọ́ bò wá fún un. Òjó kò fẹ́ kí Aládé mọ ohun tí ó wà nínú àpò náà, ṣùgbọ́n Aládé kó iṣu àti ẹ̀fọ́ tí òun mú wá fún un sínú àpò. Ìgbà tí Aládé wo àpò ọ̀rẹ́ rẹ̀ ó bá ọ̀yà nínú àpò tí ó gbé lọ́wọ́. Ojú ti Òjó púpọ̀, inú sì bí Aládé fún irú ìwà tí Òjó ń hù.

    Kin ni ojo fi pa oya ti Alade ri ninu apo re?
A) Ada
B) Owo
C) Takute
D) Ibon
  • 5. AKAYE

    Ka àyọkà ìsàlẹ̀ yìí, kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.

    Òjó jẹ́ ọmọ ilú Ìlọ́rọ̀, ọ̀rẹ́ rẹ̀ jẹ́ ọmọ Agbélé. Òjó fẹ́ràn ọ̀rẹ́ rẹ̀ púpọ̀ nítorí isu, tòmátì, ata, àgbàdo àti ọ̀sàn tí ó máa ń fún un. Lọ́títọ́, iṣẹ́ àgbẹ̀ ni iṣẹ́ Aládé ṣùgbọ́n Òjó tí ó jẹ́ ọmọ ode kì í fún ọ̀rẹ́ rẹ̀ ní ẹran tí ó bá fi ìbọn pa nínú igbó nítorí wí pé, o ni ero pe, òun ṣe wahálà púpọ̀ kí òun tó pa erán ni.
    Ní ọjọ́ kan bí Òjó ṣe ń gbé ẹran ọ̀yà tí ó fi tàkúté pa lọ sí ọjà láti tà ni ó bá pàdé Aládé tí ó ń kó iṣu àti ẹ̀fọ́ bò wá fún un. Òjó kò fẹ́ kí Aládé mọ ohun tí ó wà nínú àpò náà, ṣùgbọ́n Aládé kó iṣu àti ẹ̀fọ́ tí òun mú wá fún un sínú àpò. Ìgbà tí Aládé wo àpò ọ̀rẹ́ rẹ̀ ó bá ọ̀yà nínú àpò tí ó gbé lọ́wọ́. Ojú ti Òjó púpọ̀, inú sì bí Aládé fún irú ìwà tí Òjó ń hù.

    Iru iwa wo ni iwa Ojo?
A) Ika
B) Ole
C) Ahun
D) Opuro
  • 6. AKAYE

    Oruko eran ti Alade ba ninu apo Ojo ni
A) ejo
B) igala
C) oya
D) igbin
  • 7. AKAYE

    Ka àyọkà ìsàlẹ̀ yìí, kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.

    Òjó jẹ́ ọmọ ilú Ìlọ́rọ̀, ọ̀rẹ́ rẹ̀ jẹ́ ọmọ Agbélé. Òjó fẹ́ràn ọ̀rẹ́ rẹ̀ púpọ̀ nítorí isu, tòmátì, ata, àgbàdo àti ọ̀sàn tí ó máa ń fún un. Lọ́títọ́, iṣẹ́ àgbẹ̀ ni iṣẹ́ Aládé ṣùgbọ́n Òjó tí ó jẹ́ ọmọ ode kì í fún ọ̀rẹ́ rẹ̀ ní ẹran tí ó bá fi ìbọn pa nínú igbó nítorí wí pé, o ni ero pe, òun ṣe wahálà púpọ̀ kí òun tó pa erán ni.
    Ní ọjọ́ kan bí Òjó ṣe ń gbé ẹran ọ̀yà tí ó fi tàkúté pa lọ sí ọjà láti tà ni ó bá pàdé Aládé tí ó ń kó iṣu àti ẹ̀fọ́ bò wá fún un. Òjó kò fẹ́ kí Aládé mọ ohun tí ó wà nínú àpò náà, ṣùgbọ́n Aládé kó iṣu àti ẹ̀fọ́ tí òun mú wá fún un sínú àpò. Ìgbà tí Aládé wo àpò ọ̀rẹ́ rẹ̀ ó bá ọ̀yà nínú àpò tí ó gbé lọ́wọ́. Ojú ti Òjó púpọ̀, inú sì bí Aládé fún irú ìwà tí Òjó ń hù.

    Kin ni ise Alade?
A) Awako
B) Oluko
C) Ademu
D) Ode
  • 8. AKAYE

    Omo ilu wo ni Alade?
A) Ikole
B) Iloro
C) Eko
D) Agbele
  • 9. AKAYE

    Omo ilu wo ni Ojo?
A) Agbele
B) Oyo
C) Eko
D) Iloro
  • 10. AKAYE

    Kin ni o mu Ojo nigba ti Alade ri oya ninu apo re?
A) Ebi pa a
B) Oju ti i
C) Inu bi i
D) Ori fo o
  • 11. Oodunrun ni figo je
A) 500
B) 200
C) 300
D) 400
  • 12. Okooleerugba o din mewaa ni
A) 212
B) 211
C) 209
D) 210
  • 13. Eeji din nigba ni onka geesi je.....
A) 189
B) 197
C) 188
D) 198
  • 14. 1100 ni onka je ni
A) egbefa
B) eedegbefa
C) egbesan
D) egbejo
  • 15. 2000 ni onka je
A) ogofa
B) oodunrun
C) egbewa
D) egbaafa
  • 16. Arolake omo Adeosun pupa ' FOO'. Isori oro wo ni a "FOO"?
A) Oro eyan
B) Oro oruko
C) Oro aponle
D) Oro ise
  • 17. Iwo ati Bola jeun. ' IWO' je
A) Oro aropo afarajoruko
B) Oro atokun
C) Oro apejuwe
D) Oro aponle
  • 18. Mo fi akara mu eko. 'MO' je
A) Oro apejuwe
B) Oro aropo oruko
C) Oro atokun
D) Oro aponle
  • 19. Opomulero ninu gbolohun ni oro....
A) aponle
B) ise
C) atokun
D) onibo
  • 20. 'O wa si ile-iwe'. Oro atokun ni inu gbolohun yi ni....
A) o
B) ile iwe
C) si ile
D) si
  • 21. "Olu lo si Eko" je apeere gbolohun ......
A) asebeere
B) ase
C) alakanpo
D) alabode
  • 22. Gbolohun alabode ni gbolohun......
A) eyan
B) onibo
C) eleyo oro ise
D) apola
  • 23. Apeere oro asopo ni
A) ati, sugbon
B) oun, iwo
C) ile, anbelentase
D) pelu, awa
  • 24. Gbolohun onibo le ni ju ---- lo ninu ihun gbolohun.
A) ibeere
B) eyan kan
C) apola ise
D) oro ise kan
  • 25. Orin ti a jogun lati enu awon baba nla wa ni orin......
A) ode-oni
B) juju
C) ibile
D) fuji
  • 26. Orin: ' Eko dara pupo' je orin fun awon ....
A) agba
B) elesin ibile
C) adelebo
D) ewe
  • 27. Orin 'Omo to mo iya re loju o ...' ko omode ni iwa ...
A) odale
B) igberaga si obi
C) yiyaju si iya
D) ibowo fun obi
  • 28. Isare to je mo esin ibile ni
A) Bolojo
B) ekun iyawo
C) apepe
D) iwi
  • 29. Orisa wo ni o korira adi?
A) Oya
B) Esu
C) Ogun
D) Sango
  • 30. Isare to je mo esin Oro ni....
A) arungbe
B) ijala
C) iremoje
D) Esa
  • 31. Ohun to maa n sele ni akoko ogun ni won yii, ayafi......
A) Wahala
B) Ifokanbale
C) Ede ayede
D) Ipaniyan
  • 32. Iwon yii ni o n fa ogun, ayafi.....
A) ,
B) Ojukokoro
C) Yiye adehun
D) Ede ayede
E) Ifowosowopo
  • 33. Ki ni eto akoko ni ibi isomoloruko ni ile Yoruba?
A) Fifun omo loruko
B) Ogundagba
C) Fifun awon alejo ni ounje
D) Sise adura fun omo
  • 34. Ewo ni ko si lara ohun elo isomoloruko ni ile Yoruba?
A) Ataare
B) Orogbo
C) Eyin
D) Aadun
  • 35. Ojo wo ni won maa n so omo obinrin ni oruko ni ile Yoruba? Ojo
A) Kewa
B) Kesan
C) Keje
D) Kejo
  • 36. Ni ori kini iwe ere onitan ti a ka, ta ni won pe ni "419" ninu iwe itan yii?
A) Dadi
B) Ejire
C) Faderera
D) Owolabi
  • 37. Ki ni won se apejuwe re bi "apekanuko, apesenuroboto" ninu ori kini iwe itan yii?
A) Ewa
B) Ola
C) Owo
D) Omo
  • 38. Kini oruko awon tokotaya ti o pe Owolabi pe Faderera je awon lowo? Tokotaya
A) Ogunsakin
B) Ogunrinde
C) Ogunaike
D) Ogunniyi
  • 39. Ki ni akole iwe ere onitan ti a ka ?
A) Oyin Inu Apata
B) Awo Fele
C) Eyin Lohun
D) Sisi Oloja
  • 40. Ta ni o ko iwe itan naa?
A) Kule Dagunro
B) Rukayat Afolabi
C) D.O Fagunwa
D) Bose Ilori
Created with That Quiz — where a math practice test is always one click away.