PES JS 2 Yoruba (Obj) 2nd Term Exam 2025/2026
  • 1. . . .. .ni awon ewi alohun ti a le fi oro inu won ti a gbo da won mo yato.
A) Aroko
B) Litireso
C) Arangbo
D) Isare
  • 2. Ona ti opo eniyan fi n pawopo ran eni kan lowo se ise ti o le gba asiko pipe lati se ni asa............
A) Idara - eni - lokowo
B) Ifowo-so-wopo
C) Ifara - eni - goke
D) Iranra - eni - lowo
  • 3. Ewo ni ona Iranra-eni - lowo ajemowo ninu awon won yii?
A) Arokodoko
B) Ajo
C) Aaro
D) Owe
  • 4. Anfaani iranra eni lowo ni......
A) O je ki ise ti o le gba akoko pupo lati se je sise kiakia
B) O je ki awon onise kan maa se imele
C) O n dina mo awon odo ilu lati se oriire
D) O mu ifaseyin ba opo eniyan
  • 5. Owo ti a n da jo titi ti yoo fi joju ki a to ko o ni.......
A) Ajo
B) Esusu
C) Aaro
D) Owe
  • 6. Anfaani esusu ni pe, ......
A) o n so eeyan di otosi
B) o n je ki eeyan ma mo ohun ti a n fowo se
C) kii je ki a nawo ni inakuna
D) o je ki eni ti o ti lowo tele di alaini
  • 7. Ti inawo pajawiri ba de, eeyan le gba....... lati fi bo asiri.
A) Owe
B) Aaro
C) Ajo
D) Esusu
  • 8. Awon ise ti a le be owe se ni won yii, ayafi......
A) Ile kiko
B) Ise oko
C) Ona oko yiye
D) Omi pipon
  • 9. Ewo ninu awon ona iranra - eni - lowo won yii ni o tumo si 'bami ro temi, ki n ba o ro tie '?
A) Esusu
B) Owe
C) Aaro
D) Arokodoko
  • 10. Awon wo ni o maa n be ni aaro sise?
A) Awon ore ti oko won jina si ara won
B) Awon ore ti oko won wa nitoosi ara won
C) Awon alagbaro fun agbe aladanla
D) Awon agbe aladanla
  • 11. Riro oko kiri gege bi ona ti awon agbe n gba lati fi ran ara won lowo ni........
A) Aaro
B) Arokodoko
C) Owe
D) Alupayida
  • 12. Ewo ninu ona Iranra-eni - lowo won yii ni won n seto eyawo onilopo meji iye ti omo egbe ti da si apo egbe?
A) Sogundogoji ti igbalode
B) Ifomosofa ti igbalode
C) Egbe alafowosowopo ode oni
D) Egbe alajeseku aye atijo
  • 13. Ewo ni ona Iranra-eni - lowo ajemose ninu awon won yii?
A) Sogundogoji
B) Ajo
C) Owe
D) Eesu
  • 14. Ewo ninu awon won yii ni kii se orisa ni ile Yoruba?
A) Sango
B) Obatala
C) Orunmila
D) Alapinni
  • 15. Ona Iranra-eni-lowo ti awon eniyan pawopo laarin ilu lati se, fun idagbasoke ilu ni.........
A) Arokodoko
B) Owe
C) Aaro
D) Ebese
  • 16. Orisa wo ni awon Yoruba n ki ni 'omoran ale Ife '?
A) Obatala
B) Ogun
C) Orunmila
D) Opon ifa
  • 17. Awon Yoruba timo Olodumare si.....
A) Oba awon orisa
B) Eni ti o da orun ati aye
C) Eni ti o tobi julo, ti titobi Re ko lopin
D) Eni ti o seda gbogbo e
  • 18. Eedegbeje ni figo je.....
A) 1700
B) 1300
C) 1900
D) 1500
  • 19. Orin le nirinwo je...
A) 380
B) 580
C) 780
D) 480
  • 20. 200 × 9=?, o je..... ni onka Yoruba.
A) Egbewa
B) Egbeta
C) Egbesan
D) Egberin
  • 21. 250 + 115 = ?, o je..... .....ni onka Yoruba.
A) Ota le nirinwo le marun
B) Oji le nirinwo le marun
C) Orin le nirinwo din marun
D) Oji le nirinwo din marun
  • 22. 2000 ÷ 5 =? ni onka Yoruba, o je........
A) Irinwo
B) Igba
C) Ogorun
D) Oodun
  • 23. Orisii meji ti arangbo pin si ni arangbo........ ati arangbo.....
A) Ode oni ati ti atijo
B) Wiwuwo ati fifuye
C) Kikun ati kekeke
D) Nla ati kekere
  • 24. Awon Yoruba gbagbo pe onigbowo awon lodo Olodumare ni awon........
A) Kirisiteni
B) Orisa
C) Aborisa
D) Muhamodu
  • 25. Awon elesin ibile maa n se gbogbo awon nnkan won yii, ayafi....
A) Ba ara won lo pelu ooto inu
B) Lile ipa alaafia
C) Ninfe ara won
D) Jija ija esin
  • 26. Ewo ni arangbo kikun ninu awon won yii?
A) Aro
B) Owe
C) Aalo apamo
D) Ese ifa
  • 27. Ewo ni arangbo kekere ninu awon won yii?
A) Ijala
B) Owe
C) Esa egungun
D) Ofo
  • 28. Awon won yii ni asa Iranra-eni- lowo ajemowo, ayafi.......
A) Aaro
B) Ifomo sofa
C) San an diedie
D) Sogundogoji
  • 29. Oriki Ogun saaba maa n jeyo ninu........
A) Iyere ifa
B) Sango pipe
C) Arungbe
D) Ijala ode
  • 30. Awon elesin oro lo ni......
A) Ijala ode
B) Arungbe
C) Iyere ifa
D) Esa egungun
  • 31. Ewo ni o yato ninu awon won yii?
A) Iyere ifa
B) Oya pipe
C) Ekun iyawo
D) Esu pipe
  • 32. A tun mo iwi si.....
A) Ijala ode
B) Iyere ifa
C) Arungbe
D) Esa egungun
  • 33. Ewo ninu awon orisa won yii ni a maa n ki ni 'Elerii-ipin, a tun ori eni ti o sunwon se'?
A) Obatala
B) Orunmila
C) Olodumare
D) Esu
  • 34. Ki ni eewo Esu?
A) Eko tutu
B) Epo pupa
C) Adi
D) Adie
  • 35. Ewo ni ko si ninu oriki ti Yoruba fi n pe Olodumare?
A) Adakedajo
B) Asenibanidaro
C) Alawilese
D) Gbanigbani
  • 36. Eya wo ni o pe Olorun ni Mawu?
A) Egun
B) Tapa
C) Hausa
D) Igbo
  • 37. Oriki wo lo fi han pe Olodumare maa n gbo oro?
A) Eletiigbaroye
B) Adaniwaye
C) Olumoran okan
D) Arinurode
  • 38. Ewo ni ko si lara ohun ti a fi n bo Obatala ?
A) Adie
B) Igbin
C) Obe - efo
D) Emu
  • 39. Ta ni Yoruba gba gege bi Olorun Airi tabi eni ti a ko le fi oju ri?
A) Olodumare
B) Ogun
C) Sango
D) Esu
  • 40. Orisa wo ni Yoruba gbagbo pe o seda ara eniyan ti Olodumare si fe emi si ara naa?
A) Obatala
B) Ogun
C) Sango
D) Esu
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — where test making and test taking are made easy for math and other subject areas.