Yoruba Second Term Basic 3
  • 1. Faweli Yoruba nii
A) a,e,i,o,u
B) e,I,o,u,a
C) a ,e ,e,I,o,o,u
  • 2. Alifabeeti Yoruba pin si ona meloo
A) Marun
B) Meji
C) Meta
  • 3. Faweli airanmupe je meloo _____
A) Meji
B) Marun
C) Meje
  • 4. 100 ni ede yoruba ni ______
A) Ogun
B) Aadorin
C) Ogorun-un
  • 5. _____ ni apeere Oro kekeekee
A) ewe igi eso igi
B) Dayo ya iwe
C) Ola ko iwe
  • 6. Konsonanti Yoruba nii _____
A) b,d,f,g,gb,h,j,k,l,m,n,p,r,s,s,t,w,y
B) b,o,f,g,a,gb,h,j,k,l,m,n,p,r,s,s,t,w,y
C) b,e,u,d,f,g,gb,h,j,k,l,m,n
  • 7. ______ ni o maa n so ohun ti o sele ninu gbolohun
A) Oro iwa
B) Oro ise
C) Oro oruko
  • 8. Apeere Oro ise nii_____
A) Ola
B) Iwe
C) Je
  • 9. Apeere Oro oruko ni ______
A) Ya
B) Iru
C) Shola
  • 10. Ale seda Oro onisilebu kan nipa Lilo konsonanti ati faweli(k+f)
A) Beeni
B) Mi o mon
C) Beeko
  • 11. Apeere Oro onisilebu kan ni ______
A) J+u
B) Fa+we+li
C) a+g+a
  • 12. 50 ni Yoruba nii______
A) Adoje
B) Ogorun-un
C) Aadorin
  • 13. Apeere Oro onisilebu meji nii_____
A) K+o=ko
B) I+y+a=iya
C) Si+Le+bu=silebu
  • 14. Apeere Oro onisilebu meta nii____
A) J+e=je
B) K+a+n=kan
C) O+ni+se=onise
  • 15. Ni ede yoruba 20 je_______
A) Ogun
B) Meta
C) Mewa
  • 16. Faweli Yoruba lapaapo je meloo
A) Marun
B) Meje
C) Mejo
  • 17. Konsonanti Yoruba ni apapo je meloo
A) Okandinlogun
B) Aarundinlogun
C) Ogun
  • 18. Apeere Oro oni silebu kan ni _____
A) O+r+o=Oro
B) B+a=ba
C) A+p+a=apa
  • 19. Apeere Oro ise nii _____
A) Oluko
B) Dara
C) Mu
  • 20. Faweli ni awon wonyi ayaafi
A) A
B) K
C) E
D) I
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.