ThatQuiz Test Library Take this test now
PES Yoruba JS 2 First Term Exam 2025
Contributed by: School
  • 1. Ewo ninu awon gbolohun won yii ni kii se gbolohun Ase?
A) Omo ilu Eko ni mi
B) Bola ti jeun tan
C) Jade sita
D) Omo tuntun, alejo aye
  • 2. Ewo ni kii se orisii gbolohun ninu awon won yii? Gbolohun
A) Alakanpo
B) Onibo
C) Alapetan
D) Alabode
  • 3. Oro asopo ninu gbolohun :" Baba mi ti ba oko mi soro, amo ko gboran si won lenu" ni
A) amo
B) oko mi
C) soro
D) baba
  • 4. Ewo ni gbolohun ase ibeere ninu awon gbolohun won yii?
A) Ta lo pe o?
B) Mo ti de sile o
C) Ise Oluwa,awamaridi ni
D) Ojogbon ni mi
  • 5. "Eran ti mo ra ti salo "- iru eya gbolohun wo ni yii? Gbolohun
A) Asafihan
B) Alabode
C) Alakanpo
D) Onibo
  • 6. Ewo ni gbolohun afihan ninu awon gbolohun won yii?
A) E kuro ni ile wa
B) Emi ni akobi baba mi
C) E ku oju lona o
D) Ni iranti mama mi
  • 7. Iru orin wo ni eyi-
    " Omo to moya re loju o osi ni yoo ta omo naa pa, Iya to jiya pupo lori re, Omo to jiya pupo" Orin
A) Imototo
B) Amuseya
C) Iwa rere
D) Isile
  • 8. Ewo ni kii se orisii orin ninu awon won yii?
A) Orin amuto
B) Orin onka
C) Orin eremode
D) Orin Igbeyawo
  • 9. Ohun pipe ti awon baba-nla wa n lo nibi ayeye ti ko jemo esin orisa tabi eyi ti won n ko nibi ti won n ti n bo orisa kan ni a n pe ni........
A) Iyere ifa
B) Isare
C) Arangbo
  • 10. Ewo ninu awon won ni kii se isare Ajemesin?
A) Arungbo
B) Alamo
C) Iwi
D) Ijala
  • 11. Awon ilu wo ni o maa n ko orin obintu?
A) Ondo
B) Egbs
C) Ilaje
D) Oyo
  • 12. Awon...... ni o n sun iyere ifa
A) Oloya
B) babalowo
C) Onisango
D) Olosun
  • 13. Ewo ni kii se ohun eelo fun orin ifa ninu awon nnkan won yii?
A) Ilu agere
B) Fere
C) Agogo
D) Ilu bata
  • 14. Won maa n pe oku nigba ti won maa n ..... olele
A) ko
B) so
C) wi
D) mu
  • 15. Tani olori awon elesin Sango?
A) Adosu
B) Babalowo
C) Abore
  • 16. Iru ilu wo ni awon onisango maa n lu ti won ba n sodun won?
A) Ilu bembe
B) Ilu gangan
C) Ilu dundun
D) Ilu bata
  • 17. Awon wo ni o ni o maa n pe Esu? Awon
A) Onifa
B) Olosun
C) Aworo
  • 18. Ewo ninu awon nnkan won yii ni kii se ami orisa Oya?
A) Edun ara funfun
B) Irun agbo
C) Iwo efon
D) Igba ademu
  • 19. Ewo ninu awon won yii ni eewo orisa Esu?
A) obi ati epo
B) Adi ati obi
C) Adi ati omi
  • 20. Ewo ninu awon orisa won yii ni obinrin ko gbodo ri?
A) Sango
B) Egungun
C) Oro
  • 21. Oji le leedegbeta ni figo je....
A) 580
B) 540
C) 504
D) 450
  • 22. 170 ni onka je
A) Ogojo din mewa
B) Aadoje din mewa
C) Ogosan din mewa
D) Ogofa din mewa
  • 23. 35 + 76 = ? Kin ni esi aropo awon figo yii ni onka Yoruba?
A) Ookan le logofa
B) Ookan le laadofa
C) Ookan le loodunrun
D) Ookan din loodunrun
  • 24. Onise wo ni a n ki ni " Oju gbooro o"?
A) "Olode"
B) "Onisegun"
C) "Onidiri"
D) "Awako"
  • 25. Bawo ni a se n ki awako?
A) "Asokale anfaani o"
B) "Owo a de o "
C) "Awaye o "
D) "Ese a tele layo o "
  • 26. Bawo ni a se n ki awon eniyan nibi isinku?
A) "E ku ijomo "
B) "E ku oriire o "
C) "E ku asedinde o"
D) "E ku olojojo
  • 27. Egberun ni figo je
A) 1000
B) 3000
C) 2000
D) 4000
  • 28. Ki ni ihun oro KF duro fun?
A) Faweeli+Konsonanti
B) Foniimu + Faweeli
C) Konsonanti+ Foniimu
D) Konsonanti+ Faweeli
  • 29. Olu sun je ihun oro oruko ati.......
A) oro ise
B) apola atokun
C) aponle
D) alakanpo
  • 30. Gbolohun Alabode maa n ni
A) oro ise ati eyan
B) ibeere ati idahun
C) eyo oro ise kan soso
D) oro ise pupo
  • 31. Orisii gbolohun inu ede Yoruba ni : Gbolohun
A) Alaye, alapeere ati onibeere
B) Onibo ,kukuru, at igogun
C) Alakanpo, onoboafi ati
D) Alabode, Onibo , Alakanpo
  • 32. Ewo ninu awon igbese won yii ni ko si ninu Igbeyawo kootu?
A) Ikede
B) Idanileko
C) Igbeyawo ninu yara kootu
D) Fifi oruko sile
  • 33. Iru Igbeyawo wo ni kii se ti ode oni? Igbeyawo
A) Ibile
B) Kootu
C) Mosalasi
D) Soosi
  • 34. Ofin Igbeyawo kootu ni pe
A) Oko lee ko iyawo sile pelu ase awon obi tie
B) Oko ko lee ko iyawo sile ni ilana to yato si ofin ijoba
C) Oko ko lee ko iyawo sile ayafi to ba fe iyawo miran
D) Oko ko lee ko iyawo sile ni ilana ti ko yato si ti ofin soosi
  • 35. Iru Igbeyawo wo ni oko gbodo san sadaki? Igbeyawo
A) Kootu
B) Mosalasi
C) Ibile
D) Soosi
  • 36. Awon onise wo ni Yoruba maa n ki pe " Arinpa ni togun o" ?
A) Ode
B) Alagbede
C) Awako
D) Agbe
  • 37. Asiko wo ni a maa nki awon eniyan bayii ? " E ku ogbele yi o".
A) Ni asiko oye
B) Ni asiko ojo
C) Ni asiko ooru
D) Ni asiko odun
  • 38. Iru orin wo ni awon ewe maa n ko nigba ti won ba n sere osupa? Orin
A) Eremode
B) Idupe fun obi
C) Iwa rere
D) Idaraya
  • 39. Ewo ninu awon isare won yii ni akoonu re ni oriki/oro nipa Orunmila ninu?
A) Ijala ode
B) Esu pipe
C) Olele
D) Iyere ifa
  • 40. Nigba wo ni won maa n ko orin gelede? Nigba
A) odun egungun
B) odun isu
C) odun keresi
D) odun ifa
Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.