ThatQuiz Test Library Take this test now
PES Yoruba JS 2 Third Term Exam 2025
Contributed by: School
  • 1. Adiresi melo ni a n ko si leta gbefe? Adiresi..........
A) meta
B) ko bi adiresi
C) eyo kan
D) meji
  • 2. Ewo ni kii se apeere ikini ibere ninu leta ninu awon gbolohun won yii?
A) Iyawo mi owon
B) Ore mi ataata
C) Baba mi tooto
D) Emi ni aburo re tooto
  • 3. Ibo ni deeti maa n wa ninu leta aigbefe? Abe
A) ikadi
B) adiresi akoleta
C) adiresi agbaleta
D) ninu koko oro
  • 4. Eni ti a ko leta si ni a n pe ni.... .
A) alakowe
B) agbaleta
C) akoleta
D) afiwe ranse
  • 5. Leta wo ni ko ni akole? Leta
A) gbefe
B) pajawiri
C) aigbefe
D) lesekese
  • 6. Ohun akoko ti a ni lati ko ti a ba n ko aroko oniroyin ni......
A) Akole
B) Ipin afo
C) Ifaara
D) Oruko alaroko
  • 7. Ipin afo ninu aroko tumo si....
A) Theme
B) Topic
C) Paragraph
D) Introduction
  • 8. Kin ni o n toka si isele inu aroko?
A) Ilapa ero
B) Ipin afo
C) Ifaara
D) Koko oro
  • 9. ........... ni o waye nigba ti a ba pa iro je ninu oro kan tabi laarin oro meji
A) Idin oro ku
B) Aranmo
C) Iparoje
D) Isunki
  • 10. Iro wo ni a pa je ninu oro yii "Ladele"? Iro
A) A
B) E
C) K
D) O
  • 11. Ewo ninu awon oro won yii ni iparoje ati isunki ko le waye laarin won?
A) Gba owo
B) Mu omi
C) Ko ile
D) ri Bayo
  • 12. Isori oro wo ni o je opomulero inu gbolohun? Oro
A) Atokun
B) Aponle
C) Ise
D) Oruko
  • 13. Ewo ninu awon oro won yii ni oro ise oni silebu kan?
A) Joko
B) Sun
C) Pana
D) Ounje
  • 14. Ewo ni oro ise elela ninu awon won yii?
A) jewo
B) tuka
C) kiri
D) pade
  • 15. Akojopo oro to di apa kan gbolohun ni a n pe ni......
A) Aranmo
B) Apola
C) Iparoje
D) Isunki
  • 16. Ewo ni apola oro aropo afarajoruko ninu gbolohun yii"Oun lo mo Olu" ?
A) Oun
B) Lo
C) Mo
D) Olu
  • 17. Ki ni itumo akanlo ede yii "Ta teru nipa"?
A) Wa
B) Ku
C) Lo
D) So
  • 18. 1900 ni onka yoruba je......
A) Eedegberun
B) Eedegbewa
C) Egbejo
D) Eedegbje
  • 19. 65 + 17 = ? Esi ni onka yoruba je....
A) Eeji le logorin
B) Eeji din laadoje
C) Eeji din logorin
D) Eeji le laadoje
  • 20. Pari owe yii " Aguntan to ba ba aja rin, .......
A) a je gbe "
B) a mumi si i "
C) a yo daada "
D) a bi "
  • 21. Orisii ami ohun meta inu ede Yoruba ni...... ....... .ati....
A) Ohun isele, foniimu ati toniimu
B) Ohun oke, foniimu ati aarin
C) Ohun oke, isale ati aarin
D) Ohun oke, foniimu ati toniimu
  • 22. Iro ......... ni a le fi ami ohun si lori ninu oro ?
A) foniimu
B) faweeli
C) konsonanti
D) mofiimu
  • 23. Egbeta ni figo ni ......
A) 700
B) 500
C) 600
D) 900
  • 24. "Iwo ati Bola jeun", "ati" ninu gbolohun yii isori oro
A) asopo
B) aponle
C) aropo oruko
D) oruko
  • 25. Gbolohun alabode maa n ni ......
A) ibeere ati idahun
B) eyo oro -ise kan
C) eyo oro -ise pupo
D) orin ati egbe
  • 26. Ewo ni kii se orisii orin ninu awon yii? Orin
A) eremode
B) Igbeyawo
C) oloja
D) Isinku
  • 27. Orin "boju boju o" je apeere orin
A) eremode
B) Igbeyawo
C) amuseya
D) oye jije
  • 28. Isare to je mo esin ibile ni......
A) apepe
B) ogun pipe
C) aalo
D) ekun iyawo
  • 29. Orisa wo ni o korira adi? Orisa.....
A) Ogun
B) Oya
C) Esu
D) Obatala
  • 30. Tani o maa n sun ekun iyawo ninu awon won yii?
A) Okunrin ti o fe fe iyawo
B) Iya iyawo
C) Omobinrin ti o n lo si ile oko
D) Majesin
  • 31. Iyato to wa laarin alo apamo ati alo apagbe ni pe.
A) Aalo apamo maa n ni orin ninu
B) Aalo apagbe maa n ni orin ati egbe ninu
C) Aalo apagbe maa n ni idahun soki
D) Aalo apagbe maa n ni idahun ati ibeere
  • 32. Ewo ninu awon won yii ni kii se apeere arangbo kekeke?
A) Aalo apamo
B) Oriki
C) Aro
D) Owe
  • 33. Ewo ninu awon won yii ni kii se orisa ni ile Yoruba?
A) Obatala
B) Oduduwa
C) Esu
D) Oya
  • 34. Ewo ninu awon nnkan won yii ni kii eelo isomolruko ni ile Yoruba?
A) Eja
B) Aadun
C) Oyin
D) Ata
  • 35. Ewo ni oruko abiso ninu awon oruko won yii?
A) Taiwo
B) Zaynab
C) Adewale
D) John
  • 36. Omo meji ti mama kan bi ni ojo kan naa ni akoko kan naa?
A) Ibefa
B) Ibeta
C) Ibeji
D) Iberin
  • 37. Egbe to n da owo jo lati fi ran ara won lowo lode oni ni egbe.....
A) esusu
B) aaro
C) owe
D) alajeseku
  • 38. Ewo ninu ni kii se oro ayalo ninu awon oro won yii?
A) Paanu
B) Angeli
C) Soja
D) Tabili
  • 39. Pari owe yii "Ojo ti alakan ti n sepo,..........................."
A) epo re ko dun"
B) "epo re ko kunwo"
C) epo re ko pupa"
D) epo re ko jo epo"
  • 40. Ewo ninu awon oro won yii ni oro ayalo lati inu ede geesi?
A) Loya
B) Omode
C) Alangba
D) Ada
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.