ThatQuiz Test Library Take this test now
Yoruba Jss3 3rd test 1st term 2026/27
Contributed by: College
  • 1. ____ ni ija laarin awọn eniyan kan ni ilu tabi orilede
A) Agidi
B) Ijamba
C) Aigboran
D) Ogun
  • 2. _______ ma n sofo Ni igba ogun ayafi
A) Ojo ori
B) Ere oko
C) Dukia
D) Emi
  • 3. Awọn ohun ijagun ni iwọn yii ayafi
A) Obe
B) Omorogun
C) Ofa
D) Ibon
  • 4. Anfaani ogun jija ni
A) O je ki ilu di ahoro
B) O n mu ni mo awon alagbara ilu
C) O n fa ki obinrin pọ ju ọkunrin lọ
D) On je ki eniyan lowo si
  • 5. Awọn ohun ti o nfa ogun ni iwonyi ayafi
A) Yiye adehun
B) Ija lori ile
C) Igbafunra eni
D) Irenije
  • 6. ______ ni afi ti a fi ohun tó dùn ko,ti o sì dùn gbo leti ati kò sí ta
A) Ekun
B) Ofo
C) Orin
D) Aro
  • 7. Orin t a máa kó fún ìyàwó, omoge tabi Abileko la ti fi kọ wọn leko ni
A) Orin ijakadi
B) Orin idagbere
C) Orin iremolekun
D) Orin Igbeyawo
  • 8. Orin ti awọn oṣiṣẹ ma n ko lẹnu iṣẹ ni
A) Orin ijakadi
B) Orin aajo
C) Orin amuseya
D) Orin iremolekun
  • 9. Àpẹẹrẹ orin ìwà rere ni....
A) Ile ọkọ ya o, ile ọkọ ya,keleda re sìn ọ dé bè, ile oko ya....
B) Ki ni nleje...... Leje n leje.....
C) Ijo kin bá jó, ara kin bá dá.......
D) Omo to moya re loju o ,iṣẹ ni yi o tomo na pa
  • 10. Awọn ewi alohun arangbọ kikun ni iwonyi, ayaafi
A) Ekun
B) Ijala
C) Ofo
D) Oriki
  • 11. ___ ni ewi alohun ti a fín se aponle eniyan,igi,eranko , ounje,ilu ati beebeelo
A) Ofo
B) Orin
C) Ekun
D) Oriki
  • 12. Pari oriki yi. "agun_____________
A) To okun ifami
B) To igi ope
C) To ilẹkẹ di
D) Taso lo
  • 13. "A bi inu funfun _________
A) Bi aha emu
B) Bi iyan ale
C) Bi iresi àkara dindin
D) Bi burẹdi oyinbo
  • 14. Tani won man kii pe "Ibadi Aran"
A) Eranko
B) Omoge
C) Àrúgbo obinrin
D) Odomokunrin
  • 15. Ta ni a máa n ki bayii" omo bi iya le ku o ku, bi baba le lo o lọ......
A) Ige
B) Aina
C) Dada
D) Ibeji
  • 16. Oriki "Iyan" ni
A) O lẹ po bi iyepe amo
B) Kokoro funfun ona ofun
C) O soju tuetue
D) O wewu ila, o de fila iru
  • 17. Àpẹẹrẹ oriki eleyo oro kan ni
A) Èjì woroko loju iya re
B) Ẹni bẹ Adubi nise,ara re lo be
C) Okunrin gbongbonran bi ike
D) Ajadi
  • 18. Àwọn òrìṣà ilẹ yoruba ni iwonyi ayafi
A) Obatala
B) Oduduwa
C) Esu
D) Ogun
  • 19. Pataki esin láwùjọ ní.......
A) Esin n da ota sile lawujọ
B) Esin ko ni ni iwa janduku
C) Esin n fa ogun
D) Esin ko ni ni iwa rere
  • 20. Àwọn ọdún tí Musulumi ma n se ni iwọnyi, ayafi
A) Odun ileya
B) Odun itunu awe
C) Odun ajinde
D) Odun ijira
Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.