- 1. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.
Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá. Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà. Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.
Ohun ti awon eniyan so pe o pa Alade ni iwon yii, ayafi.....
A) Ogun ni ibi ise B) Iyawo re C) Ogun idile D) Aisan jedojedo
- 2. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.
Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá. Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà. Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.
Bawo ni eni ti o n se alaye yii se je si Alade ?
A) Egbon B) Alabagbe C) Aburo D) Ore
- 3. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.
Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá. Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà. Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.
Itumo "sokunkun" gege bi a se lo o ninu ayoka yi ni ki nnkan.......
A) farasin B) daamu C) dojuru D) ruju
- 4. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.
Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá. Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà. Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.
Ta ni o jebi iku ninu ayoka yi i?
A) Aburo Alade B) Awon agborandun C) Alade D) Iyawo Alade
- 5. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.
Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá. Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà. Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.
Itumo alakeji gege bi a ti lo o ninu ayoka yi ni......
A) Ajo B) Saare C) Orun D) Oke
- 6. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.
Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá. Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà. Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.
Ohun ti eni ti o ko ayoka yi ni o se pataki ju ni ki.......
A) iku ka ise rere mo wa lowo B) eeyan yago fun molebi C) aburo rere gbeyin eda D) awuyewuye maa n waye leyin iku eda eniyan
- 7. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.
Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá. Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà. Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.
Oro ti o dun eni ti o ko ayoka yi ni.....
A) iku ojiji ti Alade ku B) ebi ti awon eniyan n da Alade leyin iku re C) gbigba esin ajoji D) aibikita fun oogun Ibile
- 8. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.
Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá. Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà. Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.
Ta ni o maa n jebi leyin iku?
A) Iyawo eni to ku B) Ore oloogbe C) Molebi alaisi D) Eni to ku
- 9. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.
Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá. Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà. Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.
"Ohun ti o sokunkun si eda, kedere ni o han si Olorun". Ki ni gbolohun yi tumo si ninu ayoka oke yii?
A) Ore ni o pa a B) Iyawo Alade ni o pa a C) Iku ti o pa Alade, o ye Olorun D) Ogun ibi ise ni o pa a
- 10. Ka àkàyè yìí dáadára kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.
Ọ̀run dákẹ́ rọ́rọ́ bí ẹni tí kò ní rọ̀jò, ọjọ́ bàbá tútù bíi àmì ìyẹ́yẹ. Ìbá ṣe pé ọ̀run kò jìnna, ń bá a lọ láàrọ̀ kí n sì dé láalẹ́. Gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń dun mi lọ́kàn ni ń bà lọ sọ fún ẹ̀gbọ́n mi Àlàdé ọmọ Agbólúajé ní alákẹ́jì. Lẹ́yìn ìkú ọmọlúwàbí yìí, orísìírísìí awuyewuye ni ó ń lọ lénu àwọn ọmọ adáríhùnrùn lórí ohun tó ṣẹ̀ okùnfà ìkú òjijì. Se òkú ni ó kú màa ń jẹbi tẹ́lẹ̀. Ibi elẹ́kùn sí ti ń sunkún ni aláyọ̀ ti ń yọ. Ohun tí ó ṣẹ̀ epo kò ṣe òrá. Àwọn kan ní ìwà àìbíkítà fún òògùn ìbílẹ̀ nítorí ẹ̀sìn àjèjì tí ó yàn láàyọ̀ ni ó ṣe ìkú pa á. Àwọn agbọ̀ràn-dùn kan ní ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ ogun ìdílé ìyá tàbí ti bàbá rẹ̀. Ẹyí tí ó jọ mi lójú jù ni pé àwọn ọmọràn tí ó mọ oyún ìmú ìgbín, tí ó tọ́ka sí ìyàwó bí apokojẹ. Àwọn kan sì tún ní ibi ìṣe gan-an ni ó ti kan ẹ̀ẹ̀mọ̀. Ayé tóótó! Àkámàrà. Ohun tí ó ṣòkùnkùn sí ẹ̀dá, kedere ni hàn sí Olórun. Ewé kan kò sì lè jábọ lára igi ki Eléédùà o mà mọ̀ sí i. Àwàyééku kan kò sí. Orun ma kanju, gbogbo wa la n bo. Ki Olodumare saa je ki iku ka ise rere mo wa lowo.
Akole wo ni o ba ayoka yi mu ninu awon won yii?
A) Alagborandun B) Iku ojiji C) Ta lo pa enire D) Eni Olorun o pa kii ku
- 11. "Ijoba alagbada dara ju ijoba oloogun lo", je aroko........
A) oniroyin B) alariyanjiyan C) asotan D) alalaye
- 12. "Ile eko mi " je apeere ori oro fun aroko......
A) Alapejuwe B) Oniroyin C) Onisorongbesi D) Asotan
- 13. Ewo ni konsonanti airanmupe ninu awon won yii?
A) T B) H C) W D) M
- 14. Faweeli 'U' je faweeli.....
A) aarin B) egbe C) iwaju D) eyin
- 15. Ewo ni faweeli arehon ninu awon won yii?
A) R B) M C) T D) P
- 16. Konsonanti/F/ je konsonanti.......
A) afunnupe B) afeyinpe C) arehon D) ayanupe
- 17. Batani silebu wo lo wa ninu 'olongbo'?
A) FKFKF B) FK(n)KF C) FKK(n)KF D) FKF(n)KF
- 18. Oro ti o n se afikun itumo oro oruko ni .........
A) apejuwe B) atokun C) eyan D) ise
- 19. Silebu melo lo wa ninu " agidingbi"?
A) Merin B) Meje C) Mefa D) Marun
- 20. Eedegberin ni figo je.....
A) 500 B) 900 C) 800 D) 700
A) 2008 B) 2800 C) 2080 D) 208
- 22. Ki a ro oodun ati irinwo Papo, esi re je......
A) Eedegbeta B) Eedegbefa C) Eedegberin D) Eedegberun
- 23. Ti a ba pin egberun si ona merin,ipin kan je.......
A) Orin leerugba din mewa B) Ota le nigba din mewa C) Oji leerugba le mewa D) Ookan le nigba
- 24. Ki ni aropo awon figo won yii ni onka Yoruba,?
35 + 17. = ?
A) Eeta din logoji B) Eeji le laadota C) Eerin din logbon D) Aarun din logota
- 25. Melo ni faweeli ede Yoruba?
A) Mefa B) Meje C) Marun D) Mesan
- 26. Oro ti a n lo dipo oro - oruko ni oro........
A) ise B) afarajoruko C) aropo - oruko D) asopo
- 27. Iya Titi lo ata olowo. 'Titi' ninu gbolohun yi je eyan
A) asapejuwe B) asonka C) asaponle D) oruko
- 28. Mo ti jeun, amo n ko yo. Ki ni oro - asopo ti o wa ninu gbolohun yi i?
A) jeun B) yo C) amo D) ko
- 29. Iwe meta ni Bola mu wa si ile iwe loni. 'Meta' ninu gbolohun je eyan.......
A) asapejuwe B) onibatan C) asonka D) asafihan
- 30. Bi a a ba da meedogbon mo eeta le logoji, esi je
.............
A) Meta le logowa B) Meji le logorin C) Meji din laadorin D) Marun din laadota
- 31. Ewo ni faweeli ayanudiepe ninu awon won yii?
A) A B) Y C) T D) D
- 32. Ile yen ni Kola ra. 'yen' ninu gbolohun yi je eyan.....
A) asaponle B) asonka C) asapejuwe D) asafihan
- 33. Baba je amala, gbegiri 'ati' eran - igbe. 'Ati' ninu gbolohun yi je oro ........
A) asopo B) atokun C) aponle D) afihan
- 34. Ewo ni konsonanti asesilebu ninu awon won yii?
A) g B) f C) b D) n
- 35. Okunrin naa ga fiofio. 'fiofio' je isori oro......
A) aponle B) asafihan C) apejuwe D) atokun
- 36. 'Eniyan laso mi ' tumo si.....
A) Aso imurode mi B) Iyi ati eye mi C) Aso ibora mi D) Ore mi
- 37. O na papa bora timo si ......
A) O fi koriko bora B) O salo C) O wo inu igbo lo D) O n sa fun awon eniyan
- 38. Akojopo oro ti o ni itumo ni .........
A) Apola oro oruko B) Silebu C) gbolohun D) Oro oruko
- 39. Oro ti a n lo lati fi so oro tabi gbolohun meji papo ni......
A) isunki B) isori oro C) oro oruko D) eyan
- 40. Olu wa ni faranda. Ise wo ni 'ni' n se ninu gbolohun yi i?
A) Apejuwe B) Atokun C) Aponle D) Eyan
- 41. Omo meji ti a bi papo lojo Kan naa ni a n pe ni.....
A) Ibeji B) Alaba C) Eta - oko D) Ige
- 42. Ise ajose ti ko ni owo tabi sise ise pada ni......
A) Aaro B) Arokodoko C) Ajo D) Owe
- 43. Iru igi wo ni a fi n gbe gbedu? Igi
A) Iroko B) Gedu C) Ose D) Omo
- 44. Osu Beelu ninu onka osu je osu .......
A) kokanla B) Kejo C) Keta D) Keji
- 45. Ojo Isegun ni....... ni ede geesi .
A) Thursday B) Tuesday C) Sunday D) Saturday
- 46. Ewi alohun ti o wopo laarin awon ode ni......
A) Ijala B) Arungbe C) Dadakuada D) Bolojo
- 47. Pelu igbagbo Yoruba, 'sekere ki i rode.......'
A) Ijo B) Ibanuje C) Ija D) Iyawo
- 48. Orisa ti o lana fun awon orisa to ku lati orun wa si aye ni.....
A) Osanyin B) Esu C) Ogun D) Obatala
- 49. Lara iwa omoluabi ni...
A) Ibowo - fagba B) Arifin C) Iro - pipa D) Afojudi
- 50. Afoju feni ma fokan feni ni......
A) omo araye B) ara ile eni C) omo iya eni D) ota eni
- 51. Pari owe yi " Oju ti yoo bani kale, .........."
A) kii sun B) ko nii fi aaro sepin C) yoo la sile kedere D) ko ni yun eeyan laaro
- 52. Owo genge ni i saaju......
A) ejo B) ijo C) ija D) eke
- 53. Omo kan soso ti Oduduwa bi ni.....
A) Alaketu B) Agbonmiregun C) Okanbi D) Oranmiyan
- 54. Ja alo yi: " Iya repete to joko laarin egun". Ki ni o?
A) Osupa B) Oorun C) Osumare D) Irawo
- 55. Omo ti a bi, ti o wa ninu apo ni Yoruba n pe ni......
A) Ajayi B) Oke C) Idogbe D) Idowu
- 56. Omo ti o ni ika mefa ni a n pe ni....
A) Olugbodi B) Ige C) Ojo D) Okanran
- 57. Onise wo ni a n ki ni "Aredu o"?
A) Agbe B) Ode C) Apeja D) Alaro
- 58. A se efe, nigba ti a n da......
A) iyere B) ege C) ofo D) orin
- 59. Ewo ni oruko amutorunwa ninu awon won yii?
A) Omowumi B) Sangodeyi C) Adetola D) Taye
- 60. Ti a ba ki onidiri ni - Oju gbooro o, won a si dahun pe -------
A) Ogun a gbe o o B) Ase o C) Iyamapo a gbe o o D) Ooya o yaa o.
|