ThatQuiz Test Library Take this test now
Yoruba Jss2 1st term exam 2026/27
Contributed by: College
  • 1. Ninu ewi ,"Dakun gba ìkìlọ" tani akéwì n ba wi
A) Onisowo
B) Oluko
C) Awọn omode
D) Awọn arugbo
  • 2. Pari awọn ọrọ wonyi ti o wa ninu ewi na. " Bi iya n ko o, ______
A) Dakun gbọn eti
B) Ki o ma rerin
C) Ki o salo
D) Dakun gbeko
  • 3. "Aja ti yi o sonu, ________
A) Ko ni gbọ fere olode
B) Ko ni sun ile
C) Ko ni jegbe
D) Ko ni gbo
  • 4. "Ọrẹ rerunrerun a má ___________
A) Da bo bo eni
B) Koba ni
C) Mu ni lo ilu Oyinbo
D) Fún ni lowo
  • 5. " ohun ti o ko mo, _______
A) Ko le seku pa ni
B) Ma n mu ni gbon
C) Awọn Obi re mo
D) Awọn Ọrẹ rẹ mo
  • 6. "Aigba ìkìlọ,________
A) O n so ni d'oga
B) Ọlọre ninu
C) A má mu ni gbon
D) A má seku pa ni
  • 7. _____ ni àyọkà tí a kà ti kọkọ ati èdè inú rẹ yè ni yékéyéké
A) Iroyin
B) Leta
C) Àròkọ
D) Akaye
  • 8. Akaye máa n ni ______ leyin
A) Aalo
B) Orin
C) Ibeere
D) Idahun
  • 9. Ninu ewi " Ẹwà wo àgúnfon" ta ni akewi n ba wi
A) Awọn onisowo
B) Oluko
C) Awọn ode
D) Akeko
  • 10. Pari awọn ọrọ wọnyi ni ni ewi na" ki lo de to n deju ______
A) rekese
B) Kahunkahun
C) Ran jú
D) Raurau
  • 11. "Olodo ọmọ, _________
A) Ranjú ran
B) Ọlọrun gun
C) Seranko seniyan
D) Seku seja
  • 12. "E ni ba fiṣe sere, _________
A) Yi o já fa fa
B) Yi o di olowo
C) Yi te tẹ dagba
D) Yi o fiṣe sore
  • 13. "Fi eko sawada ,_______
A) Ki o di at'ọrọ eko je
B) Ki o lè yo bamubamu
C) Ki ọkàn rẹ le ba le
  • 14. Ko onka yii ni ede Yoruba "110"
A) Aadofa
B) Ogota
C) Aadota
D) Ogofa
  • 15. "170"
A) Aadoje
B) Ogoje
C) Aadosan
D) Ogojemewa
  • 16. "240"
A) Ojidinnigba
B) Igbaogoji
C) Ojilenigba
D) Eerinlenigba
  • 17. "216"
A) Okolenigbalemerin
B) Adowadinmefa
C) Okolenigbadinmerin
D) Okolenigbalemefa
  • 18. "227"
A) Okolenigbadinmeje
B) Ogundinnigbalemeje
C) Okolenigbadinmeta
D) Mejelenigbalemeje
  • 19. Ki ni ojo "Monday"ni yoruba
A) Belu
B) Ibe
C) Aje
D) Aiku
  • 20. "Wednesday"
A) Ojoru
B) Ope
C) Ogoru
D) Sere
  • 21. Bawo ni a ṣe máa n ki awon onise owo wonyi
    "Awako"
A) Awaye o
B) E kú moto gigun
C) E kú ere sisa
D) E kú oko wiwa
  • 22. "Oluranso"
A) E kú aso gige
B) A tún ara se o
C) E kú aso riran
D) A mú ni da ra o
  • 23. "Agbe"
A) Eku wahala o
B) Agbe loba a
C) A roko bo dun De o
D) Eku imebi kuro
  • 24. Ba wo ni a ṣe ma ki eni ti o bá loyun
A) E kú ọwọ lomi
B) Ese a tele layo
C) E kú atemora
D) E kú ẹrù omo
  • 25. Eni tí ènìyàn ku
A) E kú a seyinde
B) E kú idagbere
C) E kú ẹkun sisun
D) E kú alejo
  • 26. E ni ti o n gba awe
A) E kú igbadun
B) E ku ebi pipa
C) E kú Imenu duro
D) E kú ipanumo
  • 27. Oríṣi gbólóhùn melo lowa
A) Mefa
B) Meji
C) Meta
D) Marun
  • 28. "Olu lo sí ọjà" iru gbólóhùn wo ni eyi?
A) Gbólóhùn ránpẹ́
B) Gbólóhùn alabode
C) Gbólóhùn alakanpo
D) Gbólóhùn penpele
  • 29. "Omo yii rẹwa"
A) Gbólóhùn kekeke
B) Gbólóhùn alakanpo
C) Gbólóhùn alabode
D) Gbólóhùn nla
  • 30. "Tope ati titi je ẹwà"
A) Gbólóhùn olopo
B) Gbólóhùn onibo
C) Gbogbo eleyo
D) Gbólóhùn alakanpo
  • 31. "Tosin wa sugbon ko jeun"
A) Gbólóhùn alakanpo
B) Gbólóhùn eleyo
C) Gbólóhùn onibo
D) Gbólóhùn onibeji
  • 32. "Iwe ti móra tí sọ nù"
A) Gbólóhùn onibo
B) Gbólóhùn alalaye
C) Gbólóhùn alakanpo
D) Gbólóhùn eleyo
  • 33. "Ilẹ tí wọn kò ti wo"
A) Gbólóhùn alabode
B) Gbólóhùn onibo
C) Gbólóhùn àkíyèsí
D) Gbólóhùn oloropupo
  • 34. "Bose wa sugbon ko joko", oro-ise melo lo wa ninu gbólóhùn yìí
A) Meta
B) Oyokan
C) Ko si rara
D) Meji
  • 35. "Oúnjẹ ti mo ṣe ti danu"ki ni àfibò inú gbólóhùn yii
A) Ti da nu
B) Oúnjẹ ti danu
C) Ti mo ra
D) Oúnjẹ
  • 36. "Oko ti ade ra naa wù mi" ki ni olori gbólóhùn
A) Ade wu mi
B) Ade ra naa
C) Oko naa wù mi
D) Ti ade ra
  • 37. "Bata ti mo wo tuutun" ki ni afibo gbólóhùn yii
A) Bata
B) Tuntun
C) Bata ti mo ra
D) Ti mo wo
  • 38. "Olu ati Ayo wo oríṣi aso kan naa", Oro oruko melo lowa ninu gbólóhùn yìí?
    "
A) Meji
B) Eyokan
C) Meta
D) Merin
  • 39. "Olu oun solà ni won je Isu ati epo "oro oruko melo lowa ninu gbólóhùn yii
A) Meta
B) Merin
C) Meji
D) Marun
  • 40. Gbólóhùn Onibo = ________ + ______
A) Iwaju gbólóhùn + eyin gbolohun
B) Ilaji gbólóhùn+ ẹkun gbólóhùn
C) Olori gbólóhùn+ àfibò gbólóhùn
D) Abo gbólóhùn+ odidi gbólóhùn
Created with That Quiz — the site for test creation and grading in math and other subjects.