ThatQuiz Test Library Take this test now
Yoruba Jss2 3rd test 1st term 2026/27
Contributed by: College
  • 1. Ko onka yii ni ede Yoruba "110"
A) Aadofa
B) Ogota
C) Ogofa
D) Aadota
  • 2. "170"
A) Ogojemewa
B) Ogoje
C) Aadoje
D) Aadosan
  • 3. "240"
A) Eerinlenigba
B) Ojilenigba
C) Ojidinnigba
D) Igbaogoji
  • 4. "216"
A) Okolenigbalemefa
B) Okolenigbalemerin
C) Okolenigbadinmerin
D) Adowadinmefa
  • 5. "227"
A) Okolenigbadinmeta
B) Ogundinnigbalemeje
C) Mejelenigbalemeje
D) Okolenigbadinmeje
  • 6. Ki ni ojo "Monday"ni yoruba
A) Belu
B) Ibe
C) Aiku
D) Aje
  • 7. "Wednesday"
A) Sere
B) Ogoru
C) Ope
D) Ojoru
  • 8. Bawo ni a ṣe máa n ki awon onise owo wonyi
    "Awako"
A) E kú oko wiwa
B) E kú ere sisa
C) Awaye o
D) E kú moto gigun
  • 9. "Oluranso"
A) A mú ni da ra o
B) E kú aso riran
C) A tún ara se o
D) E kú aso gige
  • 10. "Agbe"
A) Eku wahala o
B) A roko bo dun De o
C) Eku imebi kuro
D) Agbe loba a
  • 11. Ba wo ni a ṣe ma ki eni ti o bá loyun
A) Ese a tele layo
B) E kú ẹrù omo
C) E kú atemora
D) E kú ọwọ lomi
  • 12. Eni tí ènìyàn ku
A) E kú a seyinde
B) E kú ẹkun sisun
C) E kú alejo
D) E kú idagbere
  • 13. E ni ti o n gba awe
A) E kú ipanumo
B) E ku ebi pipa
C) E kú Imenu duro
D) E kú igbadun
  • 14. Oríṣi gbólóhùn melo lowa
A) Mefa
B) Meji
C) Meta
D) Marun
  • 15. "Olu lo sí ọjà" iru gbólóhùn wo ni eyi?
A) Gbólóhùn penpele
B) Gbólóhùn alakanpo
C) Gbólóhùn alabode
D) Gbólóhùn ránpẹ́
  • 16. "Omo yii rẹwa"
A) Gbólóhùn alabode
B) Gbólóhùn kekeke
C) Gbólóhùn alakanpo
D) Gbólóhùn nla
  • 17. "Tope ati titi je ẹwà"
A) Gbogbo eleyo
B) Gbólóhùn onibo
C) Gbólóhùn alakanpo
D) Gbólóhùn olopo
  • 18. "Tosin wa sugbon ko jeun"
A) Gbólóhùn onibeji
B) Gbólóhùn eleyo
C) Gbólóhùn onibo
D) Gbólóhùn alakanpo
  • 19. "Iwe ti móra tí sọ nù"
A) Gbólóhùn eleyo
B) Gbólóhùn alakanpo
C) Gbólóhùn alalaye
D) Gbólóhùn onibo
  • 20. "Ilẹ tí wọn kò ti wo"
A) Gbólóhùn onibo
B) Gbólóhùn alabode
C) Gbólóhùn àkíyèsí
D) Gbólóhùn oloropupo
Created with That Quiz — the site for test creation and grading in math and other subjects.