- 1. AKAYE
Ka àyọkà ìsàlẹ̀ yìí, kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e. Òjó jẹ́ ọmọ ilú Ìlọ́rọ̀, ọ̀rẹ́ rẹ̀ jẹ́ ọmọ Agbélé. Òjó fẹ́ràn ọ̀rẹ́ rẹ̀ púpọ̀ nítorí isu, tòmátì, ata, àgbàdo àti ọ̀sàn tí ó máa ń fún un. Lọ́títọ́, iṣẹ́ àgbẹ̀ ni iṣẹ́ Aládé ,ṣùgbọ́n Òjó tí ó jẹ́ ọmọ ode kì í fún ọ̀rẹ́ rẹ̀ ní ẹran tí ó bá fi ìbọn pa nínú igbó nítorí wí pé, o ni i ninu ero re pe, òun ṣe wahálà púpọ̀ kí òun tó pa erán ni. Ní ọjọ́ kan bí Òjó ṣe ń gbé ẹran ọ̀yà tí ó fi tàkúté pa lọ sí ọjà láti tà ni ó bá pàdé Aládé tí ó ń kó iṣu àti ẹ̀fọ́ bò wá fún un. Òjó kò fẹ́ kí Aládé mọ ohun tí ó wà nínú àpò náà, ṣùgbọ́n Aládé kó iṣu àti ẹ̀fọ́ tí òun mú wá fún un sínú àpò. Ìgbà tí Aládé wo àpò ọ̀rẹ́ rẹ̀ ó bá ọ̀yà nínú àpò tí ó gbé lọ́wọ́. Ojú ti Òjó púpọ̀, inú sì bí Aládé fún irú ìwà tí Òjó ń hù.
Báwo ni Òjó ṣe jẹ́ sí Aládé?
A) Baba B) Egbon C) Ore D) Alabagbe
- 2. AKAYE
Ka àyọkà ìsàlẹ̀ yìí, kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.
Òjó jẹ́ ọmọ ilú Ìlọ́rọ̀, ọ̀rẹ́ rẹ̀ jẹ́ ọmọ Agbélé. Òjó fẹ́ràn ọ̀rẹ́ rẹ̀ púpọ̀ nítorí isu, tòmátì, ata, àgbàdo àti ọ̀sàn tí ó máa ń fún un. Lọ́títọ́, iṣẹ́ àgbẹ̀ ni iṣẹ́ Aládé ṣùgbọ́n Òjó tí ó jẹ́ ọmọ ode kì í fún ọ̀rẹ́ rẹ̀ ní ẹran tí ó bá fi ìbọn pa nínú igbó nítorí wí pé, o ni ero pe, òun ṣe wahálà púpọ̀ kí òun tó pa erán ni. Ní ọjọ́ kan bí Òjó ṣe ń gbé ẹran ọ̀yà tí ó fi tàkúté pa lọ sí ọjà láti tà ni ó bá pàdé Aládé tí ó ń kó iṣu àti ẹ̀fọ́ bò wá fún un. Òjó kò fẹ́ kí Aládé mọ ohun tí ó wà nínú àpò náà, ṣùgbọ́n Aládé kó iṣu àti ẹ̀fọ́ tí òun mú wá fún un sínú àpò. Ìgbà tí Aládé wo àpò ọ̀rẹ́ rẹ̀ ó bá ọ̀yà nínú àpò tí ó gbé lọ́wọ́. Ojú ti Òjó púpọ̀, inú sì bí Aládé fún irú ìwà tí Òjó ń hù.
Ewo ninu awon won yii ni ko si ninu ohun ti Alade n gbin ni oko re?
A) Aya B) Agbado C) Ogede D) Tomati
- 3. AKAYE
Ka àyọkà ìsàlẹ̀ yìí, kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.
Òjó jẹ́ ọmọ ilú Ìlọ́rọ̀, ọ̀rẹ́ rẹ̀ jẹ́ ọmọ Agbélé. Òjó fẹ́ràn ọ̀rẹ́ rẹ̀ púpọ̀ nítorí isu, tòmátì, ata, àgbàdo àti ọ̀sàn tí ó máa ń fún un. Lọ́títọ́, iṣẹ́ àgbẹ̀ ni iṣẹ́ Aládé ṣùgbọ́n Òjó tí ó jẹ́ ọmọ ode kì í fún ọ̀rẹ́ rẹ̀ ní ẹran tí ó bá fi ìbọn pa nínú igbó nítorí wí pé, o ni ero pe, òun ṣe wahálà púpọ̀ kí òun tó pa erán ni. Ní ọjọ́ kan bí Òjó ṣe ń gbé ẹran ọ̀yà tí ó fi tàkúté pa lọ sí ọjà láti tà ni ó bá pàdé Aládé tí ó ń kó iṣu àti ẹ̀fọ́ bò wá fún un. Òjó kò fẹ́ kí Aládé mọ ohun tí ó wà nínú àpò náà, ṣùgbọ́n Aládé kó iṣu àti ẹ̀fọ́ tí òun mú wá fún un sínú àpò. Ìgbà tí Aládé wo àpò ọ̀rẹ́ rẹ̀ ó bá ọ̀yà nínú àpò tí ó gbé lọ́wọ́. Ojú ti Òjó púpọ̀, inú sì bí Aládé fún irú ìwà tí Òjó ń hù.
ki ni Alade fe fun Ojo nigba ti o ri oya ninu apo re ?
A) Isu ati efo B) Ata ati isu C) Ogedee ati epa D) Agbado ati tomati
- 4. AKAYE
Ka àyọkà ìsàlẹ̀ yìí, kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.
Òjó jẹ́ ọmọ ilú Ìlọ́rọ̀, ọ̀rẹ́ rẹ̀ jẹ́ ọmọ Agbélé. Òjó fẹ́ràn ọ̀rẹ́ rẹ̀ púpọ̀ nítorí isu, tòmátì, ata, àgbàdo àti ọ̀sàn tí ó máa ń fún un. Lọ́títọ́, iṣẹ́ àgbẹ̀ ni iṣẹ́ Aládé ṣùgbọ́n Òjó tí ó jẹ́ ọmọ ode kì í fún ọ̀rẹ́ rẹ̀ ní ẹran tí ó bá fi ìbọn pa nínú igbó nítorí wí pé, o ni ero pe, òun ṣe wahálà púpọ̀ kí òun tó pa erán ni. Ní ọjọ́ kan bí Òjó ṣe ń gbé ẹran ọ̀yà tí ó fi tàkúté pa lọ sí ọjà láti tà ni ó bá pàdé Aládé tí ó ń kó iṣu àti ẹ̀fọ́ bò wá fún un. Òjó kò fẹ́ kí Aládé mọ ohun tí ó wà nínú àpò náà, ṣùgbọ́n Aládé kó iṣu àti ẹ̀fọ́ tí òun mú wá fún un sínú àpò. Ìgbà tí Aládé wo àpò ọ̀rẹ́ rẹ̀ ó bá ọ̀yà nínú àpò tí ó gbé lọ́wọ́. Ojú ti Òjó púpọ̀, inú sì bí Aládé fún irú ìwà tí Òjó ń hù.
Kin ni ojo fi pa oya ti Alade ri ninu apo re?
A) Ibon B) Takute C) Ada D) Owo
- 5. AKAYE
Ka àyọkà ìsàlẹ̀ yìí, kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.
Òjó jẹ́ ọmọ ilú Ìlọ́rọ̀, ọ̀rẹ́ rẹ̀ jẹ́ ọmọ Agbélé. Òjó fẹ́ràn ọ̀rẹ́ rẹ̀ púpọ̀ nítorí isu, tòmátì, ata, àgbàdo àti ọ̀sàn tí ó máa ń fún un. Lọ́títọ́, iṣẹ́ àgbẹ̀ ni iṣẹ́ Aládé ṣùgbọ́n Òjó tí ó jẹ́ ọmọ ode kì í fún ọ̀rẹ́ rẹ̀ ní ẹran tí ó bá fi ìbọn pa nínú igbó nítorí wí pé, o ni ero pe, òun ṣe wahálà púpọ̀ kí òun tó pa erán ni. Ní ọjọ́ kan bí Òjó ṣe ń gbé ẹran ọ̀yà tí ó fi tàkúté pa lọ sí ọjà láti tà ni ó bá pàdé Aládé tí ó ń kó iṣu àti ẹ̀fọ́ bò wá fún un. Òjó kò fẹ́ kí Aládé mọ ohun tí ó wà nínú àpò náà, ṣùgbọ́n Aládé kó iṣu àti ẹ̀fọ́ tí òun mú wá fún un sínú àpò. Ìgbà tí Aládé wo àpò ọ̀rẹ́ rẹ̀ ó bá ọ̀yà nínú àpò tí ó gbé lọ́wọ́. Ojú ti Òjó púpọ̀, inú sì bí Aládé fún irú ìwà tí Òjó ń hù.
Iru iwa wo ni iwa Ojo?
A) Ole B) Opuro C) Ika D) Ahun
- 6. AKAYE

Oruko eran ti Alade ba ninu apo Ojo ni
A) igbin B) oya C) igala D) ejo
- 7. AKAYE
Ka àyọkà ìsàlẹ̀ yìí, kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lé e.
Òjó jẹ́ ọmọ ilú Ìlọ́rọ̀, ọ̀rẹ́ rẹ̀ jẹ́ ọmọ Agbélé. Òjó fẹ́ràn ọ̀rẹ́ rẹ̀ púpọ̀ nítorí isu, tòmátì, ata, àgbàdo àti ọ̀sàn tí ó máa ń fún un. Lọ́títọ́, iṣẹ́ àgbẹ̀ ni iṣẹ́ Aládé ṣùgbọ́n Òjó tí ó jẹ́ ọmọ ode kì í fún ọ̀rẹ́ rẹ̀ ní ẹran tí ó bá fi ìbọn pa nínú igbó nítorí wí pé, o ni ero pe, òun ṣe wahálà púpọ̀ kí òun tó pa erán ni. Ní ọjọ́ kan bí Òjó ṣe ń gbé ẹran ọ̀yà tí ó fi tàkúté pa lọ sí ọjà láti tà ni ó bá pàdé Aládé tí ó ń kó iṣu àti ẹ̀fọ́ bò wá fún un. Òjó kò fẹ́ kí Aládé mọ ohun tí ó wà nínú àpò náà, ṣùgbọ́n Aládé kó iṣu àti ẹ̀fọ́ tí òun mú wá fún un sínú àpò. Ìgbà tí Aládé wo àpò ọ̀rẹ́ rẹ̀ ó bá ọ̀yà nínú àpò tí ó gbé lọ́wọ́. Ojú ti Òjó púpọ̀, inú sì bí Aládé fún irú ìwà tí Òjó ń hù.
Kin ni ise Alade?
A) Oluko B) Awako C) Ademu D) Ode
- 8. AKAYE

Omo ilu wo ni Alade?
A) Iloro B) Agbele C) Eko D) Ikole
- 9. AKAYE

Omo ilu wo ni Ojo?
A) Eko B) Agbele C) Oyo D) Iloro
- 10. AKAYE

Kin ni o mu Ojo nigba ti Alade ri oya ninu apo re?
A) Oju ti i B) Ori fo o C) Ebi pa a D) Inu bi i
- 12. Okooleerugba o din mewaa ni
A) 212 B) 211 C) 209 D) 210
- 13. Eeji din nigba ni onka geesi je.....
A) 189 B) 188 C) 197 D) 198
A) eedegbefa B) egbesan C) egbejo D) egbefa
A) ogofa B) egbewa C) egbaafa D) oodunrun
- 16. Arolake omo Adeosun pupa ' FOO'. Isori oro wo ni a "FOO"?
A) Oro eyan B) Oro ise C) Oro oruko D) Oro aponle
- 17. Iwo ati Bola jeun. ' IWO' je
A) Oro apejuwe B) Oro aponle C) Oro atokun D) Oro aropo afarajoruko
- 18. Mo fi akara mu eko. 'MO' je
A) Oro atokun B) Oro apejuwe C) Oro aropo oruko D) Oro aponle
- 19. Opomulero ninu gbolohun ni oro....
A) onibo B) ise C) atokun D) aponle
- 20. 'O wa si ile-iwe'. Oro atokun ni inu gbolohun yi ni....
A) si B) ile iwe C) o D) si ile
- 21. "Olu lo si Eko" je apeere gbolohun ......
A) alabode B) alakanpo C) ase D) asebeere
- 22. Gbolohun alabode ni gbolohun......
A) apola B) eyan C) onibo D) eleyo oro ise
A) ile, anbelentase B) oun, iwo C) ati, sugbon D) pelu, awa
- 24. Gbolohun onibo le ni ju ---- lo ninu ihun gbolohun.
A) ibeere B) eyan kan C) oro ise kan D) apola ise
- 25. Orin ti a jogun lati enu awon baba nla wa ni orin......
A) juju B) ibile C) ode-oni D) fuji
- 26. Orin: ' Eko dara pupo' je orin fun awon ....
A) adelebo B) agba C) elesin ibile D) ewe
- 27. Orin 'Omo to mo iya re loju o ...' ko omode ni iwa ...
A) odale B) yiyaju si iya C) ibowo fun obi D) igberaga si obi
- 28. Isare to je mo esin ibile ni
A) Bolojo B) apepe C) ekun iyawo D) iwi
- 29. Orisa wo ni o korira adi?
A) Sango B) Ogun C) Oya D) Esu
- 30. Isare to je mo esin Oro ni....
A) iremoje B) ijala C) Esa D) arungbe
- 31. Ohun to maa n sele ni akoko ogun ni won yii, ayafi......
A) Ifokanbale B) Ede ayede C) Ipaniyan D) Wahala
- 32. Iwon yii ni o n fa ogun, ayafi.....
A) Yiye adehun B) , C) Ojukokoro D) Ede ayede E) Ifowosowopo
- 33. Ki ni eto akoko ni ibi isomoloruko ni ile Yoruba?
A) Ogundagba B) Fifun omo loruko C) Fifun awon alejo ni ounje D) Sise adura fun omo
- 34. Ewo ni ko si lara ohun elo isomoloruko ni ile Yoruba?
A) Aadun B) Orogbo C) Ataare D) Eyin
- 35. Ojo wo ni won maa n so omo obinrin ni oruko ni ile Yoruba? Ojo
A) Kejo B) Kesan C) Keje D) Kewa
- 36. Ni ori kini iwe ere onitan ti a ka, ta ni won pe ni "419" ninu iwe itan yii?
A) Faderera B) Owolabi C) Dadi D) Ejire
- 37. Ki ni won se apejuwe re bi "apekanuko, apesenuroboto" ninu ori kini iwe itan yii?
A) Ola B) Omo C) Owo D) Ewa
- 38. Kini oruko awon tokotaya ti o pe Owolabi pe Faderera je awon lowo? Tokotaya
A) Ogunniyi B) Ogunsakin C) Ogunrinde D) Ogunaike
- 39. Ki ni akole iwe ere onitan ti a ka ?
A) Sisi Oloja B) Oyin Inu Apata C) Eyin Lohun D) Awo Fele
- 40. Ta ni o ko iwe itan naa?
A) Rukayat Afolabi B) D.O Fagunwa C) Kule Dagunro D) Bose Ilori
|