ThatQuiz Test Library Take this test now
PES Yoruba JS 1 (Obj) 3rd Term Exam 2025/2026
Contributed by: School
  • 1. AKÁYÉ

    Ọkùnrin àgbẹ́ kan gbìn iṣu sí oko rẹ̀. Àwọn olè máa ń wá jí isu re wa. Ni ojo kan, okunrin ole kan wa ji isu agbe yii , o wa isu ti o pọ̀ gan, kò sì lè dá à gbẹ́ ru. Gbogbo awon ti o ri i ni ko duro gbe ru u. Ó wá nibe fun igba pipe.
    Nígbà tí ó ṣe, òjìṣẹ́ Ọlọ́run kan dé ọ̀dọ̀ rẹ̀. Ó bẹ̀ ẹ́ kí ó ràn òun lọ́wọ́. Bí ọkùnrin òjìṣẹ́ Ọlọ́run yìí ti bẹ̀rẹ̀ kí ó gbé rú ú, olè yìí fi òṣùká le e lori, won si n ja le eru titi ti oloko fi yo lookan. Nigba ti o de odo won, o gba òjìṣẹ́ Ọlọ́run yìí létí ó sì mú awọ́n mejeeji lọ sí ọ̀dọ̀ ọlọ́pàá.
    Wọ́n yẹ ẹjọ́ wọ́n wo, wọ́n sì ju olè náà sí ẹ̀wọ̀n. Ṣùgbọ́n wọ́n dá Òjìṣẹ́ Ọlọ́run náà sílẹ̀, nitori Ọlọ́run gbéjà rẹ̀.

    Ta ni maa n ji isu agbe wa ni oko re?
A) Ojise Olorun
B) Àwọn ode
C) Awon ole
D) Awon agbe egbe re
  • 2. AKÁYÉ

    Ọkùnrin àgbẹ́ kan gbìn iṣu sí oko rẹ̀. Àwọn olè máa ń wá jí isu re wa. Ni ojo kan, okunrin ole kan wa ji isu agbe yii , o wa isu ti o pọ̀ gan, kò sì lè dá à gbẹ́ ru. Gbogbo awon ti o ri i ni ko duro gbe ru u. Ó wá nibe fun igba pipe.
    Nígbà tí ó ṣe, òjìṣẹ́ Ọlọ́run kan dé ọ̀dọ̀ rẹ̀. Ó bẹ̀ ẹ́ kí ó ràn òun lọ́wọ́. Bí ọkùnrin òjìṣẹ́ Ọlọ́run yìí ti bẹ̀rẹ̀ kí ó gbé rú ú, olè yìí fi òṣùká le e lori, won si n ja le eru titi ti oloko fi yo lookan. Nigba ti o de odo won, o gba òjìṣẹ́ Ọlọ́run yìí létí ó sì mú awọ́n mejeeji lọ sí ọ̀dọ̀ ọlọ́pàá.
    Wọ́n yẹ ẹjọ́ wọ́n wo, wọ́n sì ju olè náà sí ẹ̀wọ̀n. Ṣùgbọ́n wọ́n dá Òjìṣẹ́ Ọlọ́run náà sílẹ̀, nitori Ọlọ́run gbéjà rẹ̀.

    Iru iwa wo ni ole ti won ran lowo hu? Iwa
A) Odale
B) Opuro
C) Ọmọluabi
D) Ahun
  • 3. AKÁYÉ

    Ọkùnrin àgbẹ́ kan gbìn iṣu sí oko rẹ̀. Àwọn olè máa ń wá jí isu re wa. Ni ojo kan, okunrin ole kan wa ji isu agbe yii , o wa isu ti o pọ̀ gan, kò sì lè dá à gbẹ́ ru. Gbogbo awon ti o ri i ni ko duro gbe ru u. Ó wá nibe fun igba pipe.
    Nígbà tí ó ṣe, òjìṣẹ́ Ọlọ́run kan dé ọ̀dọ̀ rẹ̀. Ó bẹ̀ ẹ́ kí ó ràn òun lọ́wọ́. Bí ọkùnrin òjìṣẹ́ Ọlọ́run yìí ti bẹ̀rẹ̀ kí ó gbé rú ú, olè yìí fi òṣùká le e lori, won si n ja le eru titi ti oloko fi yo lookan. Nigba ti o de odo won, o gba òjìṣẹ́ Ọlọ́run yìí létí ó sì mú awọ́n mejeeji lọ sí ọ̀dọ̀ ọlọ́pàá.
    Wọ́n yẹ ẹjọ́ wọ́n wo, wọ́n sì ju olè náà sí ẹ̀wọ̀n. Ṣùgbọ́n wọ́n dá Òjìṣẹ́ Ọlọ́run náà sílẹ̀, nitori Ọlọ́run gbéjà rẹ̀.

    Ta ni won gba leti ninu ayoka yi i?
A) Ojise Olorun
B) Agbe
C) Ole
D) Ero to n koja lo
  • 4. AKÁYÉ

    Ọkùnrin àgbẹ́ kan gbìn iṣu sí oko rẹ̀. Àwọn olè máa ń wá jí isu re wa. Ni ojo kan, okunrin ole kan wa ji isu agbe yii , o wa isu ti o pọ̀ gan, kò sì lè dá à gbẹ́ ru. Gbogbo awon ti o ri i ni ko duro gbe ru u. Ó wá nibe fun igba pipe.
    Nígbà tí ó ṣe, òjìṣẹ́ Ọlọ́run kan dé ọ̀dọ̀ rẹ̀. Ó bẹ̀ ẹ́ kí ó ràn òun lọ́wọ́. Bí ọkùnrin òjìṣẹ́ Ọlọ́run yìí ti bẹ̀rẹ̀ kí ó gbé rú ú, olè yìí fi òṣùká le e lori, won si n ja le eru titi ti oloko fi yo lookan. Nigba ti o de odo won, o gba òjìṣẹ́ Ọlọ́run yìí létí ó sì mú awọ́n mejeeji lọ sí ọ̀dọ̀ ọlọ́pàá.
    Wọ́n yẹ ẹjọ́ wọ́n wo, wọ́n sì ju olè náà sí ẹ̀wọ̀n. Ṣùgbọ́n wọ́n dá Òjìṣẹ́ Ọlọ́run náà sílẹ̀, nitori Ọlọ́run gbéjà rẹ̀.

    Ta ni Olorun gbeja re ninu ayoka yi i?
A) Agbe
B) Ọkùnrin ole
C) Ojise Olorun
D) Olopa
  • 5. AKÁYÉ

    Ọkùnrin àgbẹ́ kan gbìn iṣu sí oko rẹ̀. Àwọn olè máa ń wá jí isu re wa. Ni ojo kan, okunrin ole kan wa ji isu agbe yii , o wa isu ti o pọ̀ gan, kò sì lè dá à gbẹ́ ru. Gbogbo awon ti o ri i ni ko duro gbe ru u. Ó wá nibe fun igba pipe.
    Nígbà tí ó ṣe, òjìṣẹ́ Ọlọ́run kan dé ọ̀dọ̀ rẹ̀. Ó bẹ̀ ẹ́ kí ó ràn òun lọ́wọ́. Bí ọkùnrin òjìṣẹ́ Ọlọ́run yìí ti bẹ̀rẹ̀ kí ó gbé rú ú, olè yìí fi òṣùká le e lori, won si n ja le eru titi ti oloko fi yo lookan. Nigba ti o de odo won, o gba òjìṣẹ́ Ọlọ́run yìí létí ó sì mú awọ́n mejeeji lọ sí ọ̀dọ̀ ọlọ́pàá.
    Wọ́n yẹ ẹjọ́ wọ́n wo, wọ́n sì ju olè náà sí ẹ̀wọ̀n. Ṣùgbọ́n wọ́n dá Òjìṣẹ́ Ọlọ́run náà sílẹ̀, nitori Ọlọ́run gbéjà rẹ̀.

    Ki ni agbe naa gbin si oko re gege bi ayoka yi se so?
A) Isu
B) Agbado
C) Tomati
D) Ata
  • 6. AKÁYÉ

    Ọkùnrin àgbẹ́ kan gbìn iṣu sí oko rẹ̀. Àwọn olè máa ń wá jí isu re wa. Ni ojo kan, okunrin ole kan wa ji isu agbe yii , o wa isu ti o pọ̀ gan, kò sì lè dá à gbẹ́ ru. Gbogbo awon ti o ri i ni ko duro gbe ru u. Ó wá nibe fun igba pipe.
    Nígbà tí ó ṣe, òjìṣẹ́ Ọlọ́run kan dé ọ̀dọ̀ rẹ̀. Ó bẹ̀ ẹ́ kí ó ràn òun lọ́wọ́. Bí ọkùnrin òjìṣẹ́ Ọlọ́run yìí ti bẹ̀rẹ̀ kí ó gbé rú ú, olè yìí fi òṣùká le e lori, won si n ja le eru titi ti oloko fi yo lookan. Nigba ti o de odo won, o gba òjìṣẹ́ Ọlọ́run yìí létí ó sì mú awọ́n mejeeji lọ sí ọ̀dọ̀ ọlọ́pàá.
    Wọ́n yẹ ẹjọ́ wọ́n wo, wọ́n sì ju olè náà sí ẹ̀wọ̀n. Ṣùgbọ́n wọ́n dá Òjìṣẹ́ Ọlọ́run náà sílẹ̀, nitori Ọlọ́run gbéjà rẹ̀.

    Ki ni ole naa be ojise Olorun lati se fun oun?
A) Ki o maa so oloko
B) Ki o ran an lowo
C) Ki o da moto duro fun un
D) Ki o na a gbe eru isu naa
  • 7. AKÁYÉ

    Ọkùnrin àgbẹ́ kan gbìn iṣu sí oko rẹ̀. Àwọn olè máa ń wá jí isu re wa. Ni ojo kan, okunrin ole kan wa ji isu agbe yii , o wa isu ti o pọ̀ gan, kò sì lè dá à gbẹ́ ru. Gbogbo awon ti o ri i ni ko duro gbe ru u. Ó wá nibe fun igba pipe.
    Nígbà tí ó ṣe, òjìṣẹ́ Ọlọ́run kan dé ọ̀dọ̀ rẹ̀. Ó bẹ̀ ẹ́ kí ó ràn òun lọ́wọ́. Bí ọkùnrin òjìṣẹ́ Ọlọ́run yìí ti bẹ̀rẹ̀ kí ó gbé rú ú, olè yìí fi òṣùká le e lori, won si n ja le eru titi ti oloko fi yo lookan. Nigba ti o de odo won, o gba òjìṣẹ́ Ọlọ́run yìí létí ó sì mú awọ́n mejeeji lọ sí ọ̀dọ̀ ọlọ́pàá.
    Wọ́n yẹ ẹjọ́ wọ́n wo, wọ́n sì ju olè náà sí ẹ̀wọ̀n. Ṣùgbọ́n wọ́n dá Òjìṣẹ́ Ọlọ́run náà sílẹ̀, nitori Ọlọ́run gbéjà rẹ̀.

    Ki ni ole ji ninu ayoka yi i?
A) Agbado
B) Igi
C) Isu
D) Ata
  • 8. AKÁYÉ

    Ọkùnrin àgbẹ́ kan gbìn iṣu sí oko rẹ̀. Àwọn olè máa ń wá jí isu re wa. Ni ojo kan, okunrin ole kan wa ji isu agbe yii , o wa isu ti o pọ̀ gan, kò sì lè dá à gbẹ́ ru. Gbogbo awon ti o ri i ni ko duro gbe ru u. Ó wá nibe fun igba pipe.
    Nígbà tí ó ṣe, òjìṣẹ́ Ọlọ́run kan dé ọ̀dọ̀ rẹ̀. Ó bẹ̀ ẹ́ kí ó ràn òun lọ́wọ́. Bí ọkùnrin òjìṣẹ́ Ọlọ́run yìí ti bẹ̀rẹ̀ kí ó gbé rú ú, olè yìí fi òṣùká le e lori, won si n ja le eru titi ti oloko fi yo lookan. Nigba ti o de odo won, o gba òjìṣẹ́ Ọlọ́run yìí létí ó sì mú awọ́n mejeeji lọ sí ọ̀dọ̀ ọlọ́pàá.
    Wọ́n yẹ ẹjọ́ wọ́n wo, wọ́n sì ju olè náà sí ẹ̀wọ̀n. Ṣùgbọ́n wọ́n dá Òjìṣẹ́ Ọlọ́run náà sílẹ̀, nitori Ọlọ́run gbéjà rẹ̀.

    Ibo ni won mu ole lo bi won se so ninu ayoka yi i ?
A) Odo olopa
B) Odo awon agbofinro
C) Ile ijosin
D) Odo ojise Olorun
  • 9. Aadorin ni onka Yoruba ni
A) 60
B) 40
C) 30
D) 70
  • 10. Ti a ba ro 20 + 10, o je
A) aadota
B) ogun
C) ogorino
D) ogbon
  • 11. 45 ni won n pe ni
A) aarundinlogoji
B) aarundinlaadota
C) aarundinlogbon
D) aarundinlogun
  • 12. Baba, iya ati omo meji je eniyan
A) meji
B) kan
C) merin
D) meta
  • 13. Konsonanti ... ko si ninu alifabeeti Yoruba.
A) b
B) s
C) t
D) z
  • 14. /r/ je konsonanti
A) aranmupe
B) arehon
C) afunupe
D) aseesetan
  • 15. Faweli akoko inu alifabeeti Yoruba ni
A) i
B) u
C) o
D) a
  • 16. Faweli ayanupe ni
A) i
B) u
C) a
D) e
  • 17. Oodunrun ni
A) 300
B) 400
C) 500
D) 200
  • 18. Okooleerugba-o-din-mewaa ni
A) 209
B) 213
C) 212
D) 210
  • 19. N400.00 je ... Naira
A) ogorin
B) ogoje
C) iinwo
D) igba
  • 20. 106 ni onka Yoruba ni
A) eerindinlogota
B) eerindinlogorun
C) eerindinlogun
D) eerindinlaadofa
  • 21. Odun wo ni ede Yoruba di kiko sile?
A) 1842
B) 1841
C) 1843
D) 1846
  • 22. .... ni o tumo Bibeli ede Oyinbo si ede Yoruba
A) John Raban
B) A. M, Thomas
C) Ajayi Crowther
D) Wilberforce
  • 23. Ilu ... ni won ti bi Alufaa Samuel Ajayi Crowther
A) Oyo
B) Osoogun
C) Saro
D) Ibadan
  • 24. ... ni oruko ti awon Oyinbo koko n pe awon Yoruba.
A) E ku
B) E pele
C) E n le
D) A ku
  • 25. Ijo to se iranlowo bi ede Yoruba se di kiko sile ni
A) Adulawo
B) Ridiimu
C) Siemeesi
D) Sele
  • 26. Odun wo ni awon Igbimo ede fi owo si lilo akoto Yoruba?
A) 1972
B) 1974
C) 1971
D) 1973
  • 27. 'Biotilejepe' ni a n ko bayii:
A) Bi o tile je pe
B) Bi otile jepe
C) Bio tile je pe
D) Biot ileje pe
  • 28. 'Ebute Metta' ni a n ko bayii
A) Ebute Meeta
B) Ebute Meta
C) Ebute Metaa
D) Ebute Metta
  • 29. 'Lailai' ni a ko ni akoto yii
A) laelae
B) leelee
C) lealea
D) lailai
  • 30. ... ni ege oro ti eemi le gbe jade leekan soso.
A) Faweli
B) Silebu
C) Akoto
D) Konsonanti
  • 31. Kin ni ami ihun silebu yii duro fun: KF? Apapo
A) Konsonanti + amin ohun
B) Konsonanti + faweli
C) Konsonanti + akoto
D) Konsonanti + silebu
  • 32. Pin oro yii si silebu: igbale
A) i-gbal-e
B) i-gba-le
C) igba-le
D) ig-ba-le
  • 33. A pin 'Alabahun' si silebu yii:
A) Ala-ba-hun
B) A-laba-hun
C) Alaba-hun
D) A-la-ba-hun
  • 34. Ohun akoko lati ko ti a ba n ko aroko ni
A) ifaara
B) ilapa eto
C) akole
D) ipin afo
  • 35. ... ni a fi n bere ipin afo ninu aroko
A) Koko oro
B) Ifaara
C) Ikadii
D) Akole
  • 36. Idi ti a fi n ko leta ni lati
A) so ohun ti a ni lokan fun elomiran
B) je omo rere
C) fi ri oro so
D) kede odun Keresimesi
  • 37. Igbese akoko ninu leta kiko ni
A) deeti
B) ikini ibere
C) adiresi akoleta
D) ikadii
  • 38. Oruko oye oba Ilu Saki ni
A) Okere
B) Olusaki
C) Orimolusi
D) Ooni
  • 39. Eya Yoruba Oyo ni
A) Ogbomoso
B) Ipetu-Jesa
C) Ado
D) Idimu
  • 40. Ewo ni igbese akoko ninu eto igbeyawo ibile.
A) Alarina
B) Itoro
C) Ifojusode
D) Idana
Created with That Quiz — where a math practice test is always one click away.