- 1. Ka ayoka yi ni akaye ki o si fi dahun ibeere mewa akoko.
Ogungbe feran aja re pupo. Bi aja yi se n pa etu lo n pa odu - oya, bee ni o n pa agbonrin toun tiwo lori sasara. Bi Ogungbe ba ti n lo degbe, kii fi aja re sile nitori oun ni o maa n rugbo ti asiri awon eran fi n tu, ti Ogungbe si n raye yinbon pa won. Owo kekere ko ni aja yii n pa fun Ogungbe. Bi awon olounje se n ra eran lowo Ogungbe ni awon onile oti, alakowe ati onisowo miran n ra a. Egberun mejo naira ni o n ta odu - oya ti aja yii pa ni opin ose kan, bee ni o ta agbonrin ti aja yii kan naa pa ni egberun meedogun naira. Awon eran kekere bii ikun, ehoro, ati okere ni owo won kii koja egberun meji si egberun meta naira.
Dahun ibeere yi.
Ogungbe je....
A) Olounje B) Onisowo C) Ode
- 2. Ka ayoka yi ni akaye ki o si fi dahun ibeere mewa akoko.
Ogungbe feran aja re pupo. Bi aja yi se n pa etu lo n pa odu - oya, bee ni o n pa agbonrin toun tiwo lori sasara. Bi Ogungbe ba ti n lo degbe, kii fi aja re sile nitori oun ni o maa n rugbo ti asiri awon eran fi n tu, ti Ogungbe si n raye yinbon pa won. Owo kekere ko ni aja yii n pa fun Ogungbe. Bi awon olounje se n ra eran lowo Ogungbe ni awon onile oti, alakowe ati onisowo miran n ra a. Egberun mejo naira ni o n ta odu - oya ti aja yii pa ni opin ose kan, bee ni o ta agbonrin ti aja yii kan naa pa ni egberun meedogun naira. Awon eran kekere bii ikun, ehoro, ati okere ni owo won kii koja egberun meji si egberun meta naira.
Dahun ibeere yi.
Egberun mejo naira ni Ogungbe fi n ta....
A) Ikun B) Agbonrin C) Odu - oya
- 3. Ka ayoka yi ni akaye ki o si fi dahun ibeere mewa akoko.
Ogungbe feran aja re pupo. Bi aja yi se n pa etu lo n pa odu - oya, bee ni o n pa agbonrin toun tiwo lori sasara. Bi Ogungbe ba ti n lo degbe, kii fi aja re sile nitori oun ni o maa n rugbo ti asiri awon eran fi n tu, ti Ogungbe si n raye yinbon pa won. Owo kekere ko ni aja yii n pa fun Ogungbe. Bi awon olounje se n ra eran lowo Ogungbe ni awon onile oti, alakowe ati onisowo miran n ra a. Egberun mejo naira ni o n ta odu - oya ti aja yii pa ni opin ose kan, bee ni o ta agbonrin ti aja yii kan naa pa ni egberun meedogun naira. Awon eran kekere bii ikun, ehoro, ati okere ni owo won kii koja egberun meji si egberun meta naira.
Dahun ibeere yi.
Kin ni Ogungbe fi n pa eran?
A) Ofa B) Ada C) Ibon
- 4. Ka ayoka yi ni akaye ki o si fi dahun ibeere mewa akoko.
Ogungbe feran aja re pupo. Bi aja yi se n pa etu lo n pa odu - oya, bee ni o n pa agbonrin toun tiwo lori sasara. Bi Ogungbe ba ti n lo degbe, kii fi aja re sile nitori oun ni o maa n rugbo ti asiri awon eran fi n tu, ti Ogungbe si n raye yinbon pa won. Owo kekere ko ni aja yii n pa fun Ogungbe. Bi awon olounje se n ra eran lowo Ogungbe ni awon onile oti, alakowe ati onisowo miran n ra a. Egberun mejo naira ni o n ta odu - oya ti aja yii pa ni opin ose kan, bee ni o ta agbonrin ti aja yii kan naa pa ni egberun meedogun naira. Awon eran kekere bii ikun, ehoro, ati okere ni owo won kii koja egberun meji si egberun meta naira.
Dahun ibeere yi.
Tani o maa n tu asiri awon eran ti Ogungbe n pa?
A) Aja B) Etu C) Agbonrin
- 5. Ka ayoka yi ni akaye ki o si fi dahun ibeere mewa akoko.
Ogungbe feran aja re pupo. Bi aja yi se n pa etu lo n pa odu - oya, bee ni o n pa agbonrin toun tiwo lori sasara. Bi Ogungbe ba ti n lo degbe, kii fi aja re sile nitori oun ni o maa n rugbo ti asiri awon eran fi n tu, ti Ogungbe si n raye yinbon pa won. Owo kekere ko ni aja yii n pa fun Ogungbe. Bi awon olounje se n ra eran lowo Ogungbe ni awon onile oti, alakowe ati onisowo miran n ra a. Egberun mejo naira ni o n ta odu - oya ti aja yii pa ni opin ose kan, bee ni o ta agbonrin ti aja yii kan naa pa ni egberun meedogun naira. Awon eran kekere bii ikun, ehoro, ati okere ni owo won kii koja egberun meji si egberun meta naira.
Dahun ibeere yi.
Ewo ninu awon won yii ni alabasisepo Ogungbe?
A) Ore B) Omo C) Aja
- 6. Ka ayoka yi ni akaye ki o si fi dahun ibeere mewa akoko.
Ogungbe feran aja re pupo. Bi aja yi se n pa etu lo n pa odu - oya, bee ni o n pa agbonrin toun tiwo lori sasara. Bi Ogungbe ba ti n lo degbe, kii fi aja re sile nitori oun ni o maa n rugbo ti asiri awon eran fi n tu, ti Ogungbe si n raye yinbon pa won. Owo kekere ko ni aja yii n pa fun Ogungbe. Bi awon olounje se n ra eran lowo Ogungbe ni awon onile oti, alakowe ati onisowo miran n ra a. Egberun mejo naira ni o n ta odu - oya ti aja yii pa ni opin ose kan, bee ni o ta agbonrin ti aja yii kan naa pa ni egberun meedogun naira. Awon eran kekere bii ikun, ehoro, ati okere ni owo won kii koja egberun meji si egberun meta naira.
Dahun ibeere yi.
Iru awon eran wo ni Ogungbe maa n ta ni egberun mejl tabi meta? Eran
A) kekere B) gbogbo eran C) nla
- 7. Ka ayoka yi ni akaye ki o si fi dahun ibeere mewa akoko.
Ogungbe feran aja re pupo. Bi aja yi se n pa etu lo n pa odu - oya, bee ni o n pa agbonrin toun tiwo lori sasara. Bi Ogungbe ba ti n lo degbe, kii fi aja re sile nitori oun ni o maa n rugbo ti asiri awon eran fi n tu, ti Ogungbe si n raye yinbon pa won. Owo kekere ko ni aja yii n pa fun Ogungbe. Bi awon olounje se n ra eran lowo Ogungbe ni awon onile oti, alakowe ati onisowo miran n ra a. Egberun mejo naira ni o n ta odu - oya ti aja yii pa ni opin ose kan, bee ni o ta agbonrin ti aja yii kan naa pa ni egberun meedogun naira. Awon eran kekere bii ikun, ehoro, ati okere ni owo won kii koja egberun meji si egberun meta naira.
Dahun ibeere yi.
Iru ode wo ni Ogungbe je? Ode
A) alaja - nibon B) etile C) apefon
- 8. Ka ayoka yi ni akaye ki o si fi dahun ibeere mewa akoko.
Ogungbe feran aja re pupo. Bi aja yi se n pa etu lo n pa odu - oya, bee ni o n pa agbonrin toun tiwo lori sasara. Bi Ogungbe ba ti n lo degbe, kii fi aja re sile nitori oun ni o maa n rugbo ti asiri awon eran fi n tu, ti Ogungbe si n raye yinbon pa won. Owo kekere ko ni aja yii n pa fun Ogungbe. Bi awon olounje se n ra eran lowo Ogungbe ni awon onile oti, alakowe ati onisowo miran n ra a. Egberun mejo naira ni o n ta odu - oya ti aja yii pa ni opin ose kan, bee ni o ta agbonrin ti aja yii kan naa pa ni egberun meedogun naira. Awon eran kekere bii ikun, ehoro, ati okere ni owo won kii koja egberun meji si egberun meta naira.
Dahun ibeere yi.
Ewo ni eran abiwo ninu awon eran ti Ogungbe n pa?
A) Ikun B) Eti C) Agbonrin
- 9. Ka ayoka yi ni akaye ki o si fi dahun ibeere mewa akoko.
Ogungbe feran aja re pupo. Bi aja yi se n pa etu lo n pa odu - oya, bee ni o n pa agbonrin toun tiwo lori sasara. Bi Ogungbe ba ti n lo degbe, kii fi aja re sile nitori oun ni o maa n rugbo ti asiri awon eran fi n tu, ti Ogungbe si n raye yinbon pa won. Owo kekere ko ni aja yii n pa fun Ogungbe. Bi awon olounje se n ra eran lowo Ogungbe ni awon onile oti, alakowe ati onisowo miran n ra a. Egberun mejo naira ni o n ta odu - oya ti aja yii pa ni opin ose kan, bee ni o ta agbonrin ti aja yii kan naa pa ni egberun meedogun naira. Awon eran kekere bii ikun, ehoro, ati okere ni owo won kii koja egberun meji si egberun meta naira.
Dahun ibeere yi.
Eran wo ni Ogungbe maa n ta ni owo to po julo ninu awon eran to n pa?
A) Etu B) Agbonrin C) Odu - oya
- 10. Ka ayoka yi ni akaye ki o si fi dahun ibeere mewa akoko.
Ogungbe feran aja re pupo. Bi aja yi se n pa etu lo n pa odu - oya, bee ni o n pa agbonrin toun tiwo lori sasara. Bi Ogungbe ba ti n lo degbe, kii fi aja re sile nitori oun ni o maa n rugbo ti asiri awon eran fi n tu, ti Ogungbe si n raye yinbon pa won. Owo kekere ko ni aja yii n pa fun Ogungbe. Bi awon olounje se n ra eran lowo Ogungbe ni awon onile oti, alakowe ati onisowo miran n ra a. Egberun mejo naira ni o n ta odu - oya ti aja yii pa ni opin ose kan, bee ni o ta agbonrin ti aja yii kan naa pa ni egberun meedogun naira. Awon eran kekere bii ikun, ehoro, ati okere ni owo won kii koja egberun meji si egberun meta naira.
Dahun ibeere yi.
Eran wo ni Ogungbe n ta egberun meedogun ninu gbogbo eran to maa n pa?
A) Etu B) Odu - oya C) Agbonrin
- 11. Ogojo naira ni ede Yoruba je...
A) #500 B) #150.00 C) #160.00
- 12. Oji le leedegberun ni figo ni....
A) 840 B) 940 C) 1,040
- 13. Ki a ro aadota po mo ogoji, o je
A) Ogofa B) Ogorun C) Aadorun
- 14. Ti a ba pin ogofa si ona merin, Ida Kan yoo je.....
A) Ogoji B) Aadota C) Ogbon
- 15. Okoo ni onka Yoruba ni
A) 20 B) 60 C) 40
- 16. Ewo ninu awon won yii ni o tele ilana akoto ode - oni?
A) Ofa B) Shagamu C) Aiye
- 17. Ewo ni faweeli eyin, ti o je ayanudiepe ninu awon won yii?
A) e B) a C) i
- 18. Melo ni gbogbo konsonanti ede Yoruba?
A) Meji le logun B) Meji din logbon C) Meji din logun
- 19. Faweeli wo ni kii bere oro ninu ede Yoruba? Faweeli
A) B B) U C) T
- 20. Ewo ninu ori - oro won yii ni aroko alariyanjiyan?
A) Ewure je eran ile B) Igba otun C) Omobinrin dara ju omokunrin lo
- 21. Ninu leta aigbefe, adiresi agbaleta maa n wa ni.....
A) Ni ipari leta B) Apa - otun oju iwe C) Apa osi oju - iwe
- 22. Ege oro ti eemi le gbe jade leekan soso ni....
A) Isunki B) Silebu C) Mofiimu
- 23. "E ba mi ki gbogbo ara ile o". Je ipede ti a maa n ba pade ninu aroko.....
A) Asotan B) Oniroyoin C) Leta gbefe
- 24. "O foro sabe ahon so" tumo si.....
A) O doju ti i B) O paro C) O sofofo
- 25. "Igi to to kii pe nigbo", tumo si....
A) Gbogbo igi lo dara B) Igi eso kii pe wowe C) Eni rere kii pe ku
- 26. Ife mi si e po. "Ife" ninu gbolohun yi je apeere oro - oruko ....
A) eranko B) afoyemo C) asonka
- 27. Oruko oye oba Oyo ni....
A) Olubadan B) Awujale C) Alaafin
- 28. A maa n da ege, nigba ti a maa n ... orin
A) sun B) ko C) wi
- 29. Ewi alohun ti awon ode maa n pe ni....
A) Iwi B) Iyere ifa C) Ijala
- 30. Aso funfun ni mo wo lo si ikomo naa. "Funfun je oro...
A) Aropo - oruko B) Atokun C) Eyan
- 31. Iro konsonanti pin si .... ati....
A) Geere ati odidi B) Oke ati isale C) Akunyun ati aikunyun
- 32. Ewo ninu awon won yii ni iro aarin lori ate faweeli?
A) A B) O C) E
- 33. A kii toju onika mesan......
A) Ka a B) So o C) Ge e
- 34. Iya rabata laarin egun, kin ni o?
A) Enu B) Eyin C) Ahon
- 35. Osu kejila odun ni ede Yoruba ni....
A) Seere B) Ope C) Beelu
- 36. Osu Ebibi ni.... ede geesi ni ...
A) May B) March C) April
- 37. Ojo ni akoko ninu ose? Ojo
A) Aje B) Abameta C) Aiku
- 38. Friday ni ede Yoruba ni ojo ....
A) Eti B) Isegun C) Ojo bo
A) Orin ati egbe B) Itan ati aroso C) Ibeere ati idahun
- 40. Eni ti o tumo Bibeli si ede Yoruba ni.....
A) Samuel Ajayi Crowther B) Lord Luggard C) Chine Achibe
- 41. Owo sise tumo si......
A) Isowo B) Karakata C) Oja nina
- 42. Litireso ede Yoruba pin si litireso ......ati ......
A) Alohun ati apinleko B) Apinleko ati ewi C) Alohun ati itan aroso
- 43. A tun le pe iyawo tuntun ni iyawo........
A) Iyawo keji B) Iyaale C) Osingin
- 44. Tani babanla awon omo Yoruba?
A) Okanbi B) Oduduwa C) Lamurudu
- 45. Ewo ninu awon won yii ni kii se omo-omo Oduduwa?
A) Alaketu B) Orunmila C) Oranmiyan
- 46. Melo ni iro faweeli ti o wa ninu ede Yoruba?
A) Mejila B) Meje C) Mesan
- 47. Awon konsonanti asesilebu meji ti o wa ninu alifabeeti ede Yoruba ni.....
A) M ati U B) M ati N C) L ati N
- 48. "Emi ati ore mi lo si oja", ewo ni oro atokun ninu gbolohun yi?
A) Lo B) Si C) Ati
- 49. "Dide" , je apeere gbolohun......
A) ase B) Ibawi C) Ibeere
- 50. Ewo ninu awon won yii ni faweeli eyin ti o je ayanudiepe ni....
A) i B) e C) u
- 51. Lati inu iwe itan: Oogun Isoye:
Kin oruko baba Soji ?
A) Alabi B) Adeyemi C) Adeleke
- 52. Kin ni o n ba baba ati iya Soji ninu je? Nitori
A) Soji n jale B) Soji da lapa C) Soji ko mowe
- 53. Omo odun melo ni Soji?
A) Odun meedogun B) Odun mefa C) Odun mokanla
- 54. Kin ni idi ti iya Soji fi mi u lo sile babalawo? Lati lo
A) lati lo na babalawo se odun ifa B) lati ba babalawo ja C) se Oogun Isoye
A) Iyawo Soji B) Egbon Soji C) Iya Soji
- 56. Kim ni oruko egbon Soji?
A) Jelila B) Jemila C) Jenifa
- 57. Kin ni oruko ilu ti Soji ati awon obi re wa? Ilu
A) Igbeyinloju B) Igbalonigbanka C) Igbeyinadun
- 58. Kin ni idi ti Soji ko fi fe lo si ile iwe? Nitori
A) Baba re baa wi B) O so owo ounje re nu C) Ko se ise amurele re
- 59. Kin ni oruko oluko ti o n ko kilaasi awon Soji ni isiro?
A) Ogeni Ola B) Ogeni Segun C) Ogeni Ojo
- 60. Kin ni itumo oogun isoye?
A) Oogun ti yoo je ki eeyan maa poora B) Oogun ti yoo yi eniyan lori C) Oogun ti yoo je ki eeyan mo iwe
|