- 1. 1. Melo ni gbogbo alifabeeti ede Yoruba?
A) Meedogbon B) Mokan le logun C) Meedogun
- 2. 4. Ewo ninu awon won yii ni ko si ninu alifabeeti ede Yoruba?
A) D B) P C) Q
- 3. 5. Ewo alifabeeti roboto ninu awon won yii?
A) T B) O C) S
- 4. 6.Ewo ni faweeli asenu perese ninu awọn oro won yii?
A) O B) E C) U
- 6. 8. Aadofa je....... ni figo
A) 140 B) 110 C) 130
A) Ookan din logojo B) Ookan din laadorun C) Ookan le logorin
- 8. 10. Oji leerugba ni figo je
A) 260 B) 250 C) 240
- 9. 11. Orin le nirinwo din mewa je
A) 480 B) 470 C) 490
- 10. 12. Oro wo ni o ni ihun oro FKF
A) Igba B) Omode C) Baba
- 11. 13. Batani ipile ihun oro melo ni o wa ninu ede Yoruba?
A) Meta B) Marun C) Merin
- 12. 14. Kini ihun oro yii "opalanba"
A) KFKFKFKF B) FKFKF(n)K F C) FKFKFKFK
- 13. 15. melo ni awon omo - omo Oduduwa?
A) Marun B) Meje C) Meta
- 14. 16. Kini oruko akobi Okanbi?
A) Orangun B) Onisabe C) Olowu
- 15. 17. Ewo ni ono Oduduwa ti o lowo ju?
A) Onisabe B) Alaketu C) Oranmiyan
- 16. 18. Tani o jogun ile ninu awọn omo Oduduwa?
A) Oranmiyan B) Olupopo C) Oba ibini
- 17. 19. Tani baba ifa ni ile ife?
A) Buraimo B) Okanbi C) Agbonmiregun
- 18. 20. Ewo ni kii se eya Yoruba ni apa oke-oya ninu awọn won yii?
A) Beriberi B) Tapa C) Yorubawa
|