ThatQuiz Test Library Take this test now
PES JSS 1 Yoruba revision questions 2024/25
Contributed by: School
  • 1. 1. Melo ni gbogbo alifabeeti ede Yoruba?
A) Meedogbon
B) Mokan le logun
C) Meedogun
  • 2. 4. Ewo ninu awon won yii ni ko si ninu alifabeeti ede Yoruba?
A) P
B) D
C) Q
  • 3. 5. Ewo alifabeeti roboto ninu awon won yii?
A) T
B) S
C) O
  • 4. 6.Ewo ni faweeli asenu perese ninu awọn oro won yii?
A) O
B) U
C) E
  • 5. 7. Okoo le loodun je
A) 340
B) 360
C) 320
  • 6. 8. Aadofa je....... ni figo
A) 130
B) 110
C) 140
  • 7. 9. 35 + 54 =
A) Ookan le logorin
B) Ookan din logojo
C) Ookan din laadorun
  • 8. 10. Oji leerugba ni figo je
A) 250
B) 260
C) 240
  • 9. 11. Orin le nirinwo din mewa je
A) 480
B) 490
C) 470
  • 10. 12. Oro wo ni o ni ihun oro FKF
A) Omode
B) Baba
C) Igba
  • 11. 13. Batani ipile ihun oro melo ni o wa ninu ede Yoruba?
A) Meta
B) Marun
C) Merin
  • 12. 14. Kini ihun oro yii "opalanba"
A) FKFKF(n)K F
B) FKFKFKFK
C) KFKFKFKF
  • 13. 15. melo ni awon omo - omo Oduduwa?
A) Meje
B) Meta
C) Marun
  • 14. 16. Kini oruko akobi Okanbi?
A) Olowu
B) Orangun
C) Onisabe
  • 15. 17. Ewo ni ono Oduduwa ti o lowo ju?
A) Onisabe
B) Alaketu
C) Oranmiyan
  • 16. 18. Tani o jogun ile ninu awọn omo Oduduwa?
A) Oranmiyan
B) Olupopo
C) Oba ibini
  • 17. 19. Tani baba ifa ni ile ife?
A) Agbonmiregun
B) Okanbi
C) Buraimo
  • 18. 20. Ewo ni kii se eya Yoruba ni apa oke-oya ninu awọn won yii?
A) Beriberi
B) Tapa
C) Yorubawa
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.