PES JSS 2 Yoruba 3rd Test 2024/25
- 1. 1. Apeere isaare ajemesin ni
A) Ekun Iyawo B) Iyere ifa C) Obintu
A) Eedegbejo B) Eedegberin C) Eedegbefa
A) Egbefa B) Eedegberin C) eedegbeta
A) Eeji le nigba B) Eeji din logosan C) Eeji din legbeta
- 6. 6. Tani olori awọn to n bo sango?
A) Abore B) Alapata C) Adosu
- 8. 8. Ewo ni eewo orisa esu ninu awọn won yii?
A) Eja B) Omi C) Adi
- 9. 9. Iru eniyan wo ni o n sun ekun Iyawo?
A) Iya Iyawo B) Omobinrin ti o n lo sile oko C) Obintin to bimo ku
- 10. 10. Ewo ni isaare ajemesin ninu awọn won yii
A) Sango pipe B) ijala C) Bolojo
- 11. 11. Ewo ni kii se ona Iran ra eni lowo ni aye atijo ninu awọn ona Iran ra eni lowo won yii?
A) Owe B) Itufu C) Aaro
- 12. 12. Ewo ni oro oruko ti o sise abo ninu gbolohun yii "Kola je eja"
A) Eja B) Je C) Kola
- 13. 13. Kini oro ise ti o wa ninu gbolohun yii "Ade lo si Abuja"
A) si B) Abuja C) lo
- 14. 14. Ewo ni oro aropo oruko ninu gbolohun yii "Mo ra aso aran"
A) Mo B) ra C) aran
- 15. 15. Kini akole iwe litireso ti a n ka ni kilaasi fun saa yi?
A) Olori Asake B) Igba Otun C) Owo Agbaraa
- 16. 16. Tani onkowe iwe itan naa ?
A) Abiodun Alabama Aina B) Wasiu Akinpelu Ganiyu C) Olaleye Rukayat Adeyemi
- 17. 17. Kini oruko baba Kofo ninu iwe itan naa?
A) Ifasina B) Alade C) Kuponu
- 18. 18. Kini oruko inagije ti awọn eniyan maa n pe Alabi?
A) Olohunyo B) Olowookere C) Olowonjo
- 19. 19. Kini idi to Kofo ko fi nife lati kawe, kose tabi se owo kankan? Nitori pe,
A) O ti dagba ju ile iwe lo B) O gboju le owo to baba re C) Awọn okunrin n yoo lenu
- 20. 20. Iyawo melo ni o wa ni ile Alabi bayi?
A) Merin B) Eyo kan C) Meta
|
Students who took this test also took :