ThatQuiz Test Library Take this test now
PES Ede Yoruba JS 2 3rd Term 3rd Test
Contributed by: School
  • 1. Adiresi melo ni a n ko si leta gbefe? Adiresi..........
A) eyo kan
B) meta
C) ko bi adiresi
D) meji
  • 2. Ewo ni kii se apeere ikini ibere ninu leta ninu awon gbolohun won yii?
A) Emi ni aburo re tooto
B) Baba mi tooto
C) Ore mi ataata
D) Iyawo mi owon
  • 3. Ibo ni deeti maa n wa ninu leta aigbefe? Abe
A) ikadi
B) ninu koko oro
C) adiresi akoleta
D) adiresi agbaleta
  • 4. Eni ti a ko leta si ni a n pe ni.... .
A) akoleta
B) agbaleta
C) alakowe
D) afiwe ranse
  • 5. Leta wo ni ko ni akole? Leta
A) gbefe
B) aigbefe
C) pajawiri
D) lesekese
  • 6. Ohun akoko ti a ni lati ko ti a ba n ko aroko oniroyin ni......
A) Ifaara
B) Oruko alaroko
C) Ipin afo
D) Akole
  • 7. Ipin afo ninu aroko tumo si....
A) Theme
B) Topic
C) Paragraph
D) Introduction
  • 8. Kin ni o n toka si isele inu aroko?
A) Koko oro
B) Ipin afo
C) Ifaara
D) Ilapa ero
  • 9. ........... ni o waye nigba ti a ba pa iro je ninu oro kan tabi laarin oro meji
A) Isunki
B) Iparoje
C) Aranmo
D) Idin oro ku
  • 10. Iro wo ni a pa je ninu oro yii "Ladele"? Iro
A) E
B) O
C) A
D) K
  • 11. Ewo ninu awon oro won yii ni iparoje ati isunki ko le waye laarin won?
A) Gba owo
B) ri Bayo
C) Ko ile
D) Mu omi
  • 12. Isori oro wo ni o je opomulero inu gbolohun? Oro
A) Aponle
B) Oruko
C) Atokun
D) Ise
  • 13. Ewo ninu awon oro won yii ni oro ise oni silebu kan?
A) Pana
B) Sun
C) Ounje
D) Joko
  • 14. Ewo ni oro ise elela ninu awon won yii?
A) jewo
B) pade
C) tuka
D) kiri
  • 15. Akojopo oro to di apa kan gbolohun ni a n pe ni......
A) Iparoje
B) Aranmo
C) Isunki
D) Apola
  • 16. Ewo ni apola oro aropo afarajoruko ninu gbolohun yii"Oun lo mo Olu" ?
A) Mo
B) Lo
C) Olu
D) Oun
  • 17. Ki ni itumo akanlo ede yii "Ta teru nipa"?
A) Lo
B) Ku
C) So
D) Wa
  • 18. 1900 ni onka yoruba je......
A) Eedegbje
B) Egbejo
C) Eedegberun
D) Eedegbewa
  • 19. 65 + 17 = ? Esi ni onka yoruba je....
A) Eeji din laadoje
B) Eeji le laadoje
C) Eeji din logorin
D) Eeji le logorin
  • 20. Pari owe yii " Aguntan to ba ba aja rin, .......
A) a mumi si i "
B) a bi "
C) a je gbe "
D) a yo daada "
  • 21. Ewo ninu awon oro won yii ni oro ayalo lati inu ede geesi?
A) Ada
B) Loya
C) Oloriire
D) Omode
  • 22. Ewo ninu ni kii se oro ayalo ninu awon oro won yii?
A) Paanu
B) Soja
C) Angeli
D) Tabili
  • 23. Pari owe yii "Ojo ti alakan ti n sepo,...........................
A) "epo re ko kun owo"
B) "epo re ko see ta loja"
C) "epo re ko to lati sebe"
D) "epo re ko pupa "
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the site for test creation and grading in math and other subjects.