jss2 yoruba 3rd test 2nd term
  • 1. Ere ti a ma n se lẹyin isẹ ọjọ wa ni
A) Ere idaraya
B) Ere kanpakanpa
C) Ere ija
D) Ere takasufe
  • 2. Apere ere ìdárayá ni iwọnyi ayafi
A) Ere ijakadi
B) Ere gbetigbeti
C) Ere oṣupa
D) Ere bojuboju
  • 3. Ipa ti orin kó nínu ere idaraya ni
A) Ebu bibu
B) Eke sise
C) Ole
D) Ẹkọ asa
  • 4. Pa ri owe yii, "ile la wo,_________",
A) Ki a to bimo
B) Ki a to Lu omo
C) Ki a to ṣọmọ loruko
D) Ki a to gbe omo
  • 5. Àwon nkan ti a man wo fun Omo loruko ni iwonyi , aya fi
A) Aso
B) Ile
C) Ise
D) Ipo
  • 6. "Yetunde " je apeere oruko
A) Abiso
B) Inagije
C) Oriki
D) Amutorunwa
  • 7. Taye àti kehinde je oruko
A) Oriki
B) Asopo
C) Abiso
D) Amutorunwa
  • 8. Ìdòwú je oruko ọmọ ti ọ tẹlẹ
A) Alaba
B) Ige
C) Ibeji
D) Ojo
  • 9. Eta oko ni ọmọ
A) Inu igi
B) Orí omi
C) Ti o tele ojo
D) Ti A bi sè iketa ibeji
  • 10. Ọmọ ti o wetabi ẹsẹ ni
A) Ojo
B) Olugbodi
C) Erinle
D) Abiona
  • 11. Ọmọ ti o dójú bọlé ni
A) Ajayi
B) Amope
C) Odu
D) ilori
  • 12. Ọmọ ti o yí ra mọ apo ni
A) Ola
B) Oke
C) Ilori
D) Odu
  • 13. Ọmọ ti ìya rè ko se nkan osu ti wọn fí bi ni
A) Aina
B) Iyabo
C) Yewande
D) Ilori
  • 14. Ewo ni kii se oruko oriki nínú iwonyii
A) Ajao
B) Adio
C) Ajayi
D) Akanji
  • 15. Àpẹẹrẹ oruko abiku ni iwọnyi ayafi
A) Bamidele
B) Bantale
C) Bamiji
D) Banjoko
  • 16. E wo ni oruko ìdílé onilu nínú iwonyii
A) Okewale
B) Ayanwale
C) Olawale
D) Adewale
  • 17. E wo ni oruko ìdílé eleegun nínú àwon oruko wonyi
A) Olorode
B) Ogunyemi
C) Ifabunmi
D) Ojelade
  • 18. Osù + oṣù =
A) Osoosu
B) Osuusu
C) Osousu
D) Osuosu
  • 19. Osan +Osan
A) Osoosan
B) Osunsun
C) Osonson
D) Osansan
  • 20. Pe eja + pe eja
A) Peejapeeja
B) Pejaapejaa
C) Pajápajá
D) Pejapeja
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the site for test creation and grading in math and other subjects.