AIC YORUBA JSS2 3rd TERM EXAM 2026
  • 1. _________ ni itunmo ede kan si omiran
A) Iranra eni lowo
B) Ibanisoro
C) Aayan ogbufo
D) Isunki
  • 2. Eni ti o n tumo ede kan si omiran ni a n pe ni
A) Alalaye
B) Elejo
C) Alaroye
D) Ogbufo
  • 3. E ni fe tunmo oro gbodo____
A) Buru
B) Lohun
C) Gbo ede mejeeji daradara
D) Lowo
  • 4. Ni nu aayan ogbufo,a gbodo fun oro ni
A) Itunmo ti o jin na si
B) Itunmo ti ko ye rara
C) Itunmo ti o tobi
D) Itunmo ti o bamu
  • 5. Itunmo 'happinness' ni
A) Idunnu
B) Iforiti
C) Ironu
D) Ibinu
  • 6. Itunmo 'faith' ni
A) Ìgbàgbọ
B) Iwa
C) Itiju
D) Ikorira
  • 7. Itunmo 'secret' ni
A) Asiri
B) Asise
C) Akínkanjú
D) Anfaani
  • 8. 'He was slapped' tunmo si
A) Eti n dun
B) O gba wón leti
C) Won Gba leti
D) Eti ti jabo
  • 9. ________ ni a fi n ke ' Ewi'
A) Oju
B) Enu
C) Imu
D) Emi
  • 10. A ma n lo 'Ewi' nibi ________
A) Ija
B) Ayeye
C) Oro aje
D) Ogun
  • 11. Tumo èdè yìí "the woman was capable
A) Obinrin naa kún oju osunwon
B) Obinrin naa jebi
C) Obinrin naa ko lagbara
D) Obinrin naa buru
  • 12. O salo nítorí iwa re
A) He was shy because of his life
B) He ran away because of his behavior
C) He didn't want to run
D) He was guilty of the offence
  • 13. My boss sacked me
A) Oga mi bù mi
B) Oga mi yo mi ni nise
C) Mo le oga mi danu
D) Oga mi fe na mi
  • 14. Ni ile yoruba 6am--11am is
A) Oru
B) Ale
C) Owuro
D) Idaji
  • 15. A ma n ki awon "onidiri" pe
A) Inu dun o
B) Enu gbe o
C) Oju le o
D) O jù gbórò o
  • 16. Yoruba ma n fi kiki_____________
A) Bù ẹní yan
B) Re eni Yan je
C) Gbe asa laruge
D) Di olowo
  • 17. "E ku ireju "wa fun
A) Someone relaxing
B) Someone fighting
C) Someone sleeping
D) Someone eating
  • 18. Eku ayeye"
A) For hot weather
B) For someone who farts
C) For farmer
D) For party
  • 19. Se aayan ogbufo oro yii: "struggle"
A) Iwa
B) Ijakadi
C) Igbiyanju
D) Ibinu
  • 20. Contentment
A) Itelorun
B) Ori pipe
C) Ibinu
D) Inu bibi
  • 21. Pride
A) Iwadi
B) Apara
C) Asayan
D) Iwuri
  • 22. Hatred
A) Asa
B) Esin
C) Ikorira
D) Iwa
  • 23. He was scared of the animal
A) Eranko na buru
B) Eranko búburú wa
C) Eranko na bá leru
D) Io buru nitori eranko naa
  • 24. Aayan ogbufo ni
A) Kiko ede kan
B) Lilo ede kan
C) Pipa ede kan re
D) Tutu ede kan si omiran
  • 25. 400
A) Aadorin
B) Ogoji
C) Ogorin
D) Irinwo
  • 26. 1000
A) Egbewa
B) Aadowa
C) Ogowa
D) Egberun
  • 27. 500
A) Ogorun
B) Eedegbeta
C) Marun le lodo
D) Aadorun
  • 28. Nínú iwe Iitan "ODAJU" kini orukọ ọmọ obinrin ti a n so nipa rẹ nínú iwe yii
A) Bolanle
B) Adeola
C) Adesola
D) Janet
  • 29. Irú ènìyàn wo ni ará birin náà jee
A) Oniranu
B) Elejowewe
C) Ole
D) Alakikanju
  • 30. Ọmọ ìlú bò ni arabinrin naa
A) Kwara
B) Oke ogun
C) Ogbomosho
D) Ibadan
  • 31. Iṣẹ wo ni ọyàn layọ, ti o sí gba iwe ẹrí lẹ lori
A) Adajo
B) Dokita
C) Agbero
D) Olukoni
  • 32. Ọmọ ọdún melo ni arabinrin naa
A) Aadota odun
B) Ogorun odun
C) Igba odun
D) Ogoji odun
  • 33. Ilu wo ni o padà sí nigba ti o kuro ni ilé oko re
A) Saki
B) Kebbi
C) Aha
D) Okeho
  • 34. Ọmọ melo lo bi fún ọkọ re
A) Mefa
B) Merin
C) Meta
D) Meji
  • 35. Kini yoruba fín ka aago ni Aye atijo
A) Irawo
B) Owo
C) Osupa
D) Oorun
  • 36. E wo ni ko sí nínu asiko ojo
A) Iyaleta
B) Aajin
C) Afemoju
D) Oroorun
  • 37. Kini a fín ka osu ni Aye atijo
A) Oorun
B) Ila kiko
C) Osupa
D) Owo kika
  • 38. Ko aago yii ni èdè yorùbá"9:30 am"
A) Aago meta le aadọrun iṣẹju owuro
B) Aago mesan din ogbon iseju owuro
C) Aago ọgbọn le mesan iseju owurọ
D) Aago mesan le ogbon iseju owuro
  • 39. 4:15pm ni yoruba
A) Aago mẹrin le àádọta iseju
B) Aago marun le l'ogijo iseju
C) Aago mẹrin le meedogun iseju
D) Aago meedogun le merin iseju
  • 40. 2:45 pm ni yoruba
A) Aago meji le ogbon iseju
B) Aago meta kù isẹju meedogun
C) Aago marun le l'ogoji ati meji
D) Aago meji din ogbon iseju
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.