Jss1 Yoruba third term exam
  • 1. Ni ile yoruba 6am--11am is
A) Oru
B) Idaji
C) Ale
D) Owuro
  • 2. 2am- 4am is
A) Aajin
B) Iyaleta
C) Osan
D) Ale
  • 3. Yoruba ni kiki fun awon igba yi ayafi
A) Isele
B) Ojo
C) Asiko
D) Oro
  • 4. "E ku ireju "wa fun
A) Someone relaxing
B) Someone fighting
C) Someone sleeping
D) Someone eating
  • 5. Eku ayeye"
A) For someone who farts
B) For party
C) For farmer
D) For hot weather
  • 6. Se aayan ogbufo oro yii: "culture"
A) Esin
B) Asa
C) Ore
D) Iwa
  • 7. Stage
A) Ori pepe
B) Ori itage
C) Aja
D) Ori apata
  • 8. Competition
A) Asayan
B) Iwadi
C) Apara
D) Idije
  • 9. Joke
A) Asa
B) Apara
C) Iwa
D) Esin
  • 10. He was ashamed of his behavior
A) Oju ti nitori iwa re
B) Oju re da
C) Ona ara re nitori iwa re
D) Iwa re da
  • 11. Aayan ogbufo ni
A) Kiko ede kan
B) Lilo ede kan
C) Pipa ede kan re
D) Tutu ede kan si omiran
  • 12. Aso wa fun
A) Sise afihan ara eni
B) Bibo asiri ara eni
C) Fi fa ya
D) Fifi nu le
  • 13. Aso wiwo pin si ona________
A) Marun un
B) Meta
C) Meji
D) Merin in
  • 14. E wo ni ki se aso obinrin
A) Gele
B) Dandogo
C) Buba
D) Iro
  • 15. E wo ni kii se Aso ode oni
A) Tai
B) Seeti
C) Gbariye
D) Kotu
  • 16. So oruko awon eranko wonyii ni ede yoruba: "Owl"
A) Owiwi
B) Aja
C) Ikoko
D) Igbin
  • 17. Cobra
A) Obo
B) Igala
C) Aparo
D) Sebe
  • 18. Peacock
A) Asa
B) Okin
C) Ogongo
D) Igun
  • 19. Bedbug
A) Idun
B) Idin
C) Okin
D) Eliri
  • 20. Gbolohun to ni eyo oro ise kan ni
A) Gbolohun to gbajumo
B) Gblohun onisekan
C) Gbolohun afarahe
D) Gbolohun abode
  • 21. Gbolohun _______ ni oni oro afarahe
A) Gbolohun gbajumo
B) Gbolohun onisekan
C) Gbolohun abode
D) Gbolohun onibo
  • 22. Bola fo aso, apeere gbolohun
A) Abode
B) Onisekan
C) Gbajumo
D) Onibo
  • 23. Mo pe sugbon ko gbo,
A) Gbolohun alakanpo
B) Gbolohun olowo
C) Golohun onisekan
D) Gbolohun abode
  • 24. Ki ni oro afarahe inu gbolohun yii: "Aso ti mo ra ti fa ya
A) Aso
B) Ti mo ra
C) Ra ti fa
D) Fa ya
  • 25. Ko awon onka yii ni ede Yoruba : 300
A) Oko
B) Egbeta
C) Oodunrun
D) Igba
  • 26. 600
A) Ogofa
B) Aadofa
C) Eedegbeta
D) Egbeta
  • 27. 400
A) Irinwo
B) Ogoji
C) Ogorin
D) Aadorin
  • 28. 1000
A) Egberun
B) Ogowa
C) Egbewa
D) Aadowa
  • 29. 500
A) Eedegbeta
B) Ogorun
C) Marun le lodo
D) Aadorun
  • 30. Okan lara Awon ise ti won ma n ran ra won lowo laye ati jo ni
A) Omi pipon
B) Aso fifo
C) Ounje sise
D) Ile kiko
  • 31. Asa iran ara eni lowo je ki ise
A) Won
B) Pe
C) Baje
D) Tete ma pari
  • 32. Agbe le ti ipase iran ara eni lowo di
A) Ole
B) Olojukokoro
C) Olosi
D) Olowo repete
  • 33. Okan ninu awon yii ni a n gba ran ara eni lowo
A) Ajo
B) Ija
C) Eke
D) Awin
  • 34. Eni be owe gbodo pese
A) Owo
B) Ile
C) Aso
D) Ounje
  • 35. Oruko miran fun alafowosowopo ni
A) Alajetan
B) Alayanjuran
C) Alamojuto
D) Alajeseku
  • 36. Egbe alafowosowopo fi anfaani
A) Lati ma da owo pada mo
B) Lati da owo pada nigba ti o ba wu e
C) Lati yaa owo lai dawo si nu egbe
D) Lati yaa ilopo meji owo ti o da
  • 37. ______ ni oba ile ife
A) AKire
B) Ooni
C) Olowo
D) Timi
  • 38. _______ ni oba Ibadan
A) Olowobadan
B) Onibadan
C) Olubadan
D) Alasebadan
  • 39. Bawo la se n ki "Oba"
A) Ki idi le mo aga
B) Ki ileke o kan ile
C) Ke se ko je bata
D) Ka de o pe lo ri
  • 40. Pari ori yii: "ore relarela kii________
A) Pe lo si ilu oyinbo
B) Pe re ja
C) Pe bimo
D) Pe lowo
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — where test making and test taking are made easy for math and other subject areas.