Ede Yoruba Jss1:2nd term 3rd test
  • 1. 1. 45 ni onka Yoruba je
A) Aarun din laadota
B) Aarun din logbon
C) Aarun din logoji
D) Aarun din logun
E) Aarun din laadorin
  • 2. 2. Aadorun ni figo je
A) 70
B) 80
C) 90
D) 60
E) 50
  • 3. 3. Aadowa je
A) 190
B) 280
C) 240
D) 250
E) 260
  • 4. 4. Ogofa je
A) 1971
B) 160
C) 120
D) 146
E) 199
  • 5. 5. Ninu ewi 'Ore rere' ore relarela ki pe e
A) Ga
B) Saki
C) Reja
D) Mo iwe
E) Bimo
  • 6. 6. Ore rerunrerun kii pe
A) Lowo
B) Pupa
C) Lealee
D) sera won nibi
E) Re moto
  • 7. 7. Aroko ni
A) Ohun to a ro lokan to a si ko
B) Ohun to a ko ni Fe si
C) Ohun ti o ga ju
D) Ohun ti o ni emi
E) Bi o tileje pe
  • 8. 8. ...... ni ege oro ti eemi lee gbe jade leekan soso
A) Silebu
B) Konsonanti
C) Oro
D) Faweeli
E) Ohun
  • 9. 9. Kin ni ami ihun oro yii KF duro fun?
A) Konsonanti + Akoto
B) Konsonanti + ede
C) Konsonanti + Silebu
D) Konsonanti + Faweeli
E) Konsonanti + iro ohun
  • 10. 10. Pin oro yii si Silebu - igbale
A) Ig - ba - le
B) Igba - le
C) I- gba - le
D) Igb - a- le
E) Igbal -e
  • 11. 11. Silebu melo ni oro yii ni - agbalagba ?
A) Merin
B) Meta
C) Marun
D) Mefa
E) Meje
  • 12. 12. Pin oro yii si silebu - Alabahun
A) Al-a- ba -hu -n
B) A- la -bah -un
C) A -laba- hun
D) A -la -ba - hun
E) Al -a -ba -hun
  • 13. 13. Ohun akoko ti a ni lati ko ti a ba n ko aroko ni
A) Ipin afo
B) Ilapa ero
C) Ikadi
D) Ifaara
E) Akole
  • 14. 14. Introduction ni a n pe ni ....... ninu aroko Yoruba
A) Ifihan
B) Ero okan
C) Ikadi
D) Ifaara
E) Akole
  • 15. 15. Topic ninu aroko Yoruba ni.....
A) Akole
B) Aroko
C) Ilapa ero
D) Ifaara
E) Ipin afo
  • 16. 16. ..... ni o toka isele inu aroko
A) Ifaara
B) Ipin afo
C) Akole
D) Ikadi
E) Koko oro
  • 17. 17. Ki ni o maa n tele akole ti a ba n ko aroko oniroyin?
A) Awawi
B) Ifaara
C) Ikadi
D) Koko oro
E) Atako oro
  • 18. 18. Ohun ti a n ko aroko le lori ni......
A) Koko oro
B) Ifaara
C) Akole
D) Ikadi
E) Iwadi
  • 19. 19. Aroko oniroyin je iroyin ohun ti
A) ti ko sele
B) o sele loju wa
C) ti yoo sele lola
D) ti o je iro
E) a ko mo
  • 20. 20. Apeere aroko oniroyin nii __
A) Iresi data ju eba lo lowuro
B) Bi mo se Fe lo isimin ti o n bo lona
C) Ibeere
D) Ile eja kan ti o jona
E) Iwulo agbado data ju paki lo
  • 21. 21. Ewo ni oro oruko ninu gbolohun yii? Ade je pofupoofu
A) Je
B) Pofupoofu
C) Pofu
D) Ade
E) Si
  • 22. 22. Silebu melo ni o wa ninu oro yii- pofupoofu
A) Merin
B) Meta
C) Mefa
D) Meje
E) Marun
  • 23. 23. Ilapa ero tumo si
A) Conclusion
B) Outline of points
C) Paragraph
D) Introduction
E) Topic
  • 24. 24. Akaye ni
A) Oro siso
B) Ayoka ti o daru
C) Ala oju orun
D) Ayoka ti a ka ti o ye ni yekeyeke
  • 25. 25. Ki akaye Le ye ni
A) Ki aka nigba ogun
B) Ki a ka smoke laala
C) A ko gbodo kaa rara
D) FKF
E) A gbodo kaa bi Eemeji
  • 26. 26. E wo ni Kii see Ihun silebu
A) F
B) KFNKF
C) KF
D) KK
  • 27. 27. Gbangba je
A) NKfKf
B) KfkfN
C) Kfnkf
D) FFKFN
  • 28. 28 Silebu me lo ni ijakadi
A) Meji
B) Mefa
C) Merin
D) Meta
  • 29. 29.Ninu ewi"iwa ole" iwa ole
A) Mu ni rewa
B) Mu ni lowo
C) Gbe ni de bi gi ga
D) Kii se Iwa to ni laari
  • 30. 30. Ole fi Ile aye se
A) Lowo
B) Faari
C) Kole
D) Lore
E) Digereu lasan ni
  • 31. 31. Pin oro yii si silebu "Alangba"
A) Alan -gba
B) Al -a -n -gb -a
C) A -la -(n) -gba
D) A -lan -gba
E) A -la -n -g -b -a
  • 32. 32.Eya Ara ifo ni
A) Eya Ara to o side papo ti o so gbe iro ede jade ninu enu
B) Eya Ara tio mo fonifoni
C) Eya Ara to o doti
D) Eya Ara to o ba iro ede je
  • 33. 33. Eya Ara ifo pin so orisii ona
A) Meji
B) Ogun
C) Mejo
D) Igba
  • 34. 34. Eya Ara ifo ti a Le fi oju ri ni
A) Afase
B) Tanaa onafun
C) Olele
D) Erigi
  • 35. 35. Eya Ara ifo ti a Ko Le fi oju ri ni
A) Imu
B) Komookun
C) Eyin
D) Ahon
  • 36. 37. Ewo ni eya ara ifo ?
A) Edo-foro
B) Apa
C) Eti
D) Agbon
E) Ese
  • 37. 38. 141 ni
A) Merinlelokan
B) Okanatimerin
C) Ookanlemerin
D) Ookanlelogoje
  • 38. 39.ayeye ojo ibi mi je aroko
A) Isorongbesi
B) Alariyanjiyan
C) Alayojuran
D) Oniroyin
  • 39. 40. 150 ni onka Yoruba je
A) Ogoje
B) Aadoje
C) Aadofa
D) Ogojo
E) Aadojo
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — a math test site for students of all grade levels.