Ede Yoruba Jss2: 2nd term 3rd CA test
  • 1. 1. Melo ni batani ipinle ihun oro?
A) Marun
B) Mefa
C) Meta
D) Meji
E) Merin
  • 2. 2. Oro wo lo ba ihun oro yii mu - F- KF ?
A) Sun
B) Irun
C) Naa
D) Je
E) Mo
  • 3. 3. Ki ni ihun oro yii - gbangba
A) KFKKF
B) KF(n)KF
C) KK(n)FKF
D) KFKF
E) KKFF
  • 4. 4. Ewo ni oro ise ninu gbolohun yii: Ade lo si Abuja
A) Ti
B) Abuja
C) Si
D) Ade
E) Lo
  • 5. 5. Aja je eran, eran ninu gbolohun yii ni....
A) Abo
B) Oro ise
C) Oro asopo
D) Oro oruko
E) Eyan
  • 6. 6. Ewo ni oro asopo ninu awon won yii:
A) awon
B) Ode
C) Mo
D) Lo
E) Ati
  • 7. 7. ...... ni a fi lee da gbolohun alakanpo mo
A) Oro asopo
B) Oro oruko
C) Oro aponle
D) Oro ise
E) Oro atokun
  • 8. 8. O wa........ko ba mi, Oro asopo wo ni o to lati lo?
A) Nitori
B) Pelu
C) Ati
D) Nigba ti
E) Sugbon
  • 9. 9. Apeere Oro aropo oruko ni
A) Tola
B) Dudu
C) Mo
D) Jade
  • 10. 10. Tobi fo aso," fo " je
A) Oro ise
B) Oro oruko
C) Oro asopo
D) Oro afarajo oruko
  • 11. 10. Opomulero inu gbolohun ni,.....,
A) Oro oruko
B) Oro ise
C) Oro aropo oruko
D) Oro atokun
E) Oro apejuwe
  • 12. Aso funfun ni mo wo, "funfun" je
A) Oro apejuwe
B) Oro ise
C) Oro asopo
D) Oro oruko
  • 13. 12. Igi naa ga fiofio, "fiofio je
A) Oro aponle
B) Oro oruko
C) Oro afarajoruko
D) Oro asopo
  • 14. 13.ninu ewi "Eko Ile", Eko ile _______
A) Le fa ija
B) Ko ni iwulo
C) Se pataki
D) Buru pupo
  • 15. 14. Eko ______ ni Eko ile
A) Omo ikose
B) Adayeba
C) Ode oni
D) Arrugbo
  • 16. 15 Omo to Ko ba leko Ile ,Ko Le _____
A) Lowo
B) Ja
C) Begbe mu
D) Eesu
E) Mowe
  • 17. 16. Emi ni oga won , "Emi ni je
A) Oro aropo afarajoruko
B) Oro ise
C) Oro oruko
D) Oro asopo
E) Oko won wa leti odo
  • 18. 17. Oro ti a n lo dipo Oro oruko ni oro.....
A) asopo
B) atokun
C) ise
D) apejuwe
E) aropo-oruko
  • 19. 18. Oro ti a fi n so oro meji po ninu gbolohun ni oro......
A) atokun
B) abo
C) ise
D) asopo
E) eyan
  • 20. 19. Ewo ni oro oruko ninu gbolohun yii 'Ronke se obe egusi '
A) Je
B) Se
C) Egusi
D) Ronke
E) Obe
  • 21. 20. 70 ni onka Yoruba je
A) Aadoje
B) Aadorin
C) Aadorun
D) Aadofa
E) Aadowa
  • 22. 21. Omolewa pupa foo, foo ninu gbolohun yii ni oro
A) Apejuwe
B) Ise
C) Eyan
D) Atokun
E) Alabode
  • 23. 22. Ki ni batani ihun oro yii KF duro fun ?
A) Konsonanti + Faweeli + Konsonanti
B) Faweeli + Konsonanti
C) Konsonanti + konsonanti
D) Faweeli + Faweeli
E) Konsonanti + Faweeli
  • 24. 23. Aadofa ni figo je
A) 110
B) 320
C) 109
D) 210
E) 90
  • 25. 24.kiko " Aiya " ni akoto ode oni ni
A) Ayaa
B) Aeya
C) Aaya
D) Aya
  • 26. 25." Papa" ni akoto ode oni ni
A) Paapa
B) Paapaa
C) Papaa
D) Papapa
  • 27. 26. Ninu Ewi "Iwulo Eko, iwulo Eko o _____
A) O ni itunmo
B) Legbe
C) Se koko
D) Da
  • 28. 27. Silebu melo ni o wa ninu oro yii 'olongbo' ?
A) Mefa
B) Merin
C) Meje
D) Meji
E) Marun
  • 29. 27. 250 + 250 = ?, ni onka Yoruba
A) Egbeta
B) Eedegberin
C) Egberin
D) Eedegbeta
E) Eedegberin
  • 30. 28. Iye Silebu melo ni gogogongo
A) Marun
B) Mejo
C) Mefa
D) Meji
  • 31. 29. Eko wulo ju Ile Kiko lo
A) Beeko
B) Mi o mo
C) Beeni
D) Iro ni
  • 32. 30. Eko n so ni di ____
A) Ole
B) Were
C) Ogorun
D) Arugbo
E) Ilumoka
  • 33. ______ ni afo ti afi ohun didun Ko, ti osi dun Ko sita
A) Ija
B) Orin
C) Ariwo
D) Asa
  • 34. Orin igbeyawo he Orin ti won fin Ko awon ______ logbon
A) Olomoge
B) Agbalagba
C) Omode
D) Arugbo
  • 35. Orin igbeyawo tun je ki obinrin mo _____
A) Awon ale oko e
B) Mo eebu bu
C) Ojuse Nile oko
D) Mo ijo jo
  • 36. Orisi Orin ni iwonyi ayafi
A) Orin onje jije
B) Orin igbeyawo
C) Orin eremode
D) Orin Eko Iwa rere
  • 37. Apeere Orin Iwa rere ni
A) Tani ba mi lo mo wi o, adendekun dekun o
B) Baba mo n lo, iya mo n lo
C) Ibi olomo ba n re, ka di Jo lo
D) Omo to moya re loju o
  • 38. Orin ikomojade je ka mo pataki
A) Ile kiko
B) Iro pipa
C) Omo bibi
D) Ijakadi
  • 39. Orin wulo fun
A) Gbigbe asa laruge
B) Fifa asa wale
C) Ija eyameya
D) Ebu bibu
  • 40. Orin Eko Iwa mu ki
A) Omode mo Iwa toto
B) Omode mo ijaja
C) Agbalagba ma re omode je
  • 41. Orin iremolekun mu ki omode ____
A) maa sunkun ni gbogb igba
B) Maa tobi si
C) Dake ekun
D) Ma gbe
  • 42. Lailai ni ode oni ni
A) Laelaa
B) Laelae
C) Loiloi
D) Laalaa
  • 43. Agadagodo je Oro onihun
A) Fkfkfkfkf
B) Ffkfkfn
C) Fnkfkfn
D) Kfnkfnkf
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — where test making and test taking are made easy for math and other subject areas.