YORUBA JSS1 2ND TERM EXAM
  • 1. Alifabeeti èdè Yorùbá je
A) Àròpọ̀ faweeli meji
B) Konsonati nikan
C) Àròpọ̀ faweeli àti konsonati
D) Faweeli nikan
  • 2. " m àti n" je
A) Faweeli
B) Oro oruko
C) Oro asopo
D) Konsonati
  • 3. Oro oruko afoyemo ni
A) Ipade
B) Igbeyawo
C) Alaafia
D) Idanwo
  • 4. Oro oruko alailemi ni
A) Bolape
B) Eranko
C) Tabili
D) Igbadun
  • 5. Àwon wònyí le je oro oruko, a yà fi
A) Oruko eniyan
B) Iwa
C) Ibugbe
D) Eranko
  • 6. àti" je oro
A) Ise
B) Asopo
C) Oruko
D) Apejuwe
  • 7. "Èmi pẹlú iwo" ki ni ọrọ àsopọ
A) Pẹlú iwo
B) Iwo
C) Pelu
D) Emi
  • 8. Titi ti Ibadan dé lana, ki ni oro atokun inu gbólóhùn yi
A) Ti
B) Lana
C) Titi
D) De
  • 9. Wón lo sí Èkó, "sí" nínú gbólóhùn yìí je
A) Oro orukọ
B) Oro apejuwe
C) Oro atokun
D) Oro ise
  • 10. Mo lo sugbon wọn kò sí nílé, "ṣugbọn" nínú gbólóhùn yìí je oro
A) Asopo
B) Ise
C) Àpèjúwe
D) Oruko
  • 11. Ìsòrí òrò nínú èdè Yorùbá je melo
A) Mefa
B) Mejo
C) Mewa
D) Marun
  • 12. Kini oro oruko ni èdè geesi
A) Vowel
B) Pronoun
C) Adverb
D) Noun
  • 13. Àpẹẹrẹ oro oruko ni iwonyi ayafi
A) Mo
B) Aso
C) Owo
D) Alaafia
  • 14. Oro oruko ______ ni "afefe"
A) Afoyemo
B) Ibugbe
C) Alailemi
D) Afojuri
  • 15. Oro oruko afojuri ni
A) Igbadun
B) Ilaro
C) Aga
D) Tola
  • 16. Oro oruko oun alailemi ni
A) Oshodi
B) Oore
C) Okuta
D) Titi
  • 17. Okan nínú àwon wọnyii kò sì lara ìsòrí oro
A) Oro apejuwe
B) Oro atenumo
C) Oro ise
D) Oro asopo
  • 18. Oro oruko lé wa ni ipo wọnyi ayafi
A) Aarin
B) Abo
C) Eyan
D) Oluwa
  • 19. Mo fo aso, "aso " wa ni ipo
A) Eyin
B) Abo
C) Eeyan
D) Oluwa
  • 20. Seun jeun losan,"seun " wa ni ipo
A) Oluwa
B) Abo
C) Eeyin
D) Aarin
  • 21. Ejo eere ni ode pa, "eere" ni ni gbólóhùn yi wa ni ipo
A) Oke
B) Abo
C) Aarin
D) Eeyan
  • 22. Oro ti a ma n lo dipo oro oruko ni
A) Oro ise
B) Oro asopo
C) Oro atenumo
D) Ọrọ aropo oruko
  • 23. Àpẹẹrẹ oro aropo oruko ni
A) Tabi
B) Tosin
C) Awon
D) Sun
  • 24. A je eba,oro aropo oruko ni
A) Eba
B) A
C) Je
D) Mo je
  • 25. Ile wa dara,oro aropo oruko ni
A) Ile
B) Wa
C) Yin dara
D) Dara
  • 26. Tolu ri wọn,oro aropo oruko ni
A) Tolu
B) Rimi
C) Won
D) Ri
  • 27. _______ ni òun tọka ìṣẹlẹ inú gbolohun
A) Oro asopo
B) Oro ise
C) Oro atenumo
D) Oro oruko
  • 28. Kini ọrọ iṣẹ inu gbólóhùn yi,Tope gba ile lana
A) Tope
B) Lana
C) Gba
D) Ile
  • 29. Ganiyu we fun aja،ki ni ọrọ iṣẹ inu gbólóhùn yi
A) Aja
B) Ganiyu
C) We
D) Fun
  • 30. Ọmọ pupa"pupa" je oro
A) Oro atokun
B) Asopo
C) Atenumo
D) Apejuwe
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the site for test creation and grading in math and other subjects.