- 1. 1. Isori oro melo ni a ni ninu ede Yoruba?
A) Meje B) Mejo C) Mẹta D) Mẹfa
- 2. 2. Ewo ni isori oro ti o n toka isele ninu gbolohun? Oro
A) Aponle B) Oruko C) Asopo D) Ise
- 3. 3. ....... jẹ ọkan lára awọn abala ìhun gbólóhùn ede yoruba
A) Apola B) Mofiimu C) Ọrọ orukọ D) Silebu
- 4. 4. Lara awọn iṣọri ọrọ ti àtòjọ láti hun gbólóhùn ede Yorùbá ni........
A) Ọrọ ise B) Fonọ́lọ́jì C) Silebu D) Mofiimu
- 5. 5. Àpólà inú ede yoruba jẹ melo
A) Merin B) Meji C) Marun D) Mẹta
- 6. 6. Lara awọn oríṣi Iro kọnsonanti ni awọn wọnyi ayafi.........
A) Kọnsonanti aranmupe B) Kọnsonanti akunyun C) Kọnsonanti aikunyun D) Konsonanti ayinmupe
- 7. 7. ......... Lo jẹmọ́ ètò Iro ede Yorùbá ati bí a ṣe n lo Iro ede Yorùbá
A) Fonọ́lọ́jì B) Mofiimu C) Silebu D) Gbólóhùn
- 8. 8. ......... Ni Iro ti a gbé jade nígbàtí idiwọ wá fún eemi
A) Kọnsonanti B) Mofiimu C) Silebu D) Fawẹẹli
- 9. 9. ....... Ni ọna ti a n Gba pa ìró jẹ nínú ọrọ tabi àpólà laiyan pipa Iro fawẹẹli tàbí kọnsonanti jẹ nínú ọrọ
A) Isunki B) Gbólóhùn C) Silebu D) Mofiimu
- 10. 10. Lara awọn àpẹẹrẹ isunki ni.....
A) Adua B) Ile iwe C) Oluwa D) Olodumare
- 11. 11. Gbólóhùn ọrọ LAYELAYE yóò di.........ti a ba pa ìró jẹ
A) Laelae B) Lailai C) Layeelayee D) Laylay
- 12. 12. ........ Ni ohun ini ẹni tí o ku, eyi tọka si dukia bíi ilẹ,oko owó ẹrú ati awọn nkán miran
A) Ogun B) Inawo C) Ọrọ sisọ D) Isinku
- 13. 13. Ọna melo ni yorúbá ma n Gba Pin ogun
A) Marun B) Mẹrin C) Meji D) Mẹta
- 14. 14. Ọna melo ni awẹ gbólóhùn Pin si
A) Mẹrin B) Mẹta C) Meji D) Marun
- 15. 15. .......... Ni pínpín ogun Si iye ọmọ ti oku bi
A) Olorijori B) Ìdí igi C) Dọgbadọgba D) Ilana ofin islam
- 16. 16. Lara awọn ìsọri ọrọ èdè yorúbá ni awọn wọnyi ayafi
A) Ọrọ asopọ B) Ọrọ apọnle C) Ọrọ atọkun D) Ọrọ òwe
- 17. 17. Lara awọn àpólà inú ede yorúbá ni awọn wọnyi ayafi
A) Àpólà asopọ B) Àpólà ọrọ ìse C) Àpólà apọnle D) Àpólà ọrọ orukọ
- 18. 18. Nínú ìwe litiresọ ta ká ni ni kilaasi.... orukọ iwe náà ni.......
A) Ọdaju B) Ololufẹ C) Iwa ika D) Isẹ Aje
- 19. 19.. orukọ ẹni tokọ iwe náà ni.....
A) Wasiu Akinpelu B) Olaleye Rukayat C) Bọsẹde iroko ọbaniyi D) Adewoyin Sunday
- 20. 20. Ninu iwe litireso, ọkọ adéọlá jẹ.....
A) Omoluabi B) Alaanu C) Òní inure D) Eyan buruku
- 21. 21. Nínú ìwe litiresọ, iwe ẹri melo ni adéọlá ni
A) Marun B) Mẹrin C) Mẹta D) Meji
- 22. 22. Nínú ìwe litiresọ, ọmọ ìlú wo ni adéọlá jẹ
A) Òyó B) Okeho C) Eko D) Aha
- 23. 23. Nínú ìwe litiresọ, ọmọ melo ni adéọlá bi
A) Meji B) Mẹfa C) Meje D) Marun
- 24. 24. ....... Ni ege ọrọ ti okere julọ ti ale fi eemi ẹnu wà pẹ lẹẹkan soso
A) Mofiimu B) Àmì ohun C) Silebu D) Fonọ́lọ́jì
- 25. 25. Ọna melo ni a lè gbà hun silebu
A) Meji B) Mẹta C) Mẹrin D) Marun
- 26. 26. Àmì ohun melo ni o wa nínú èdè yorúbá
A) Mẹta B) Marun C) Mẹrin D) Meji
- 27. 27. Nínú ìwe litiresọ...iyawo melo ni ọkọ adéọlá ni
A) Mẹta B) Marun C) Mẹrin D) Meji
- 28. 28. Àpẹẹrẹ kọnsonanti aranmupe asesilebu ni....
A) Agbalumọ B) Isu C) Osan D) Orombo
- 29. 29.Ami ohun melo ni AJANLEKOKO ni
A) Meje B) Mẹfa C) Marun D) Mẹrin
- 30. 30. Amin ohun tí owa nínú IGBA(GARDEN EGG) ni
A) Do Mi B) Do Re C) Re Re D) Mi Do
- 31. 31. Amin ohun tí o wa nínú IGBA (200) ni
A) Re Mi B) Do Re C) Mi Mi D) Re Re
- 32. 32. Amin ohun tí o wa nínú IGBA(CALABASH) ni
A) Re Re B) Re Do C) Do Mi D) Re Mi
- 33. 33. Àmì ohun tí o wa nínú ỌKỌ (HUSBAND)
A) Re Re B) Mi Re C) Re Do D) Do Re
- 34. 34. Àmì ohun tí o wa nínú ỌKỌ (hoe) ni
A) Mi Do B) Re Mi C) Re Do D) Do Mi
- 35. 35. Nínú ìwe Lítíréṣọ̀, isẹ wo ni adéọlá n se koto rí isẹ ìjọba
A) Isẹ ole jija B) Káràkátà C) Olùkọ D) Isẹ Irun didi
- 36. 36. Silebu melo ni ọrọ yìí ni "ỌLỌRUNKẸMI"
A) Meje B) Mẹfa C) Marun D) Mẹrin
- 37. 37. Àmì ohun to wa nínú ọrọ YORUBA ni
A) Do Re Mi B) Do Mi Re C) Re mi Do D) Re Do Mi
- 38. 38. Lara awọn oríṣi oku abami ni awọn wọnyi ayafi........
A) Abuke B) Adẹtẹ C) Arẹwa D) Ẹni tí Sàngó pa
- 39. 39. Oríṣi oku melo lowa ni ilẹ yoruba
A) Mẹta B) Mẹrin C) Meji D) Marun
- 40. 40. Lara awọn wahala to ropọ mọ ogun pínpín ni ilẹ yoruba ni awọn wọnyi ayafi.......
A) Owu jijẹ B) Ini ifẹ ara ẹni C) Ija laarin ọbakan D) Gbigbe ara ẹni lọsí ile ẹjọ
|