AIC Yoruba JSS 1 1st term exam 2025/26
  • 1. Alifabeeti ede Yoruba je......
A) Mejila
B) Meedogbon
C) Merinla
D) Meedogun
  • 2. . ........... Ni iro ti ape nigba ti idiwo kosi fun eemi
A) Faweli
B) Silebu
C) Konsonanti
D) Mofiimu
  • 3. .Onka faweli ni akotan je.....
A) Marun
B) Mefa
C) Merin
D) Meje
  • 4. .Onka konsonanti ni akotan je.....
A) Mejidinlogun
B) Meedogbon
C) Metala
D) Merinla
  • 5. . m,n. je leta
A) Airanmupe
B) Aranmupe
C) Aferigipe
D) Afunpe
  • 6. Oruko Omo oduduwa ni.....
A) Okanbi
B) Oranmiyan
C) Oba ibini
D) Alaketu
  • 7. Yoruba gbagbo pe oduduwa ati awon eniyan baba re fi ............ rin lati Meka de ile_ ife
A) Ogorun ojo
B) Aadorun ojo
C) Aadoje ojo
D) Aadofa ojo
  • 8. ........ Ni otedo si ilu ketu
A) Alaketu
B) Oranmiyan
C) Olupopo
D) Onisabe
  • 9. . Oranmiyan tedo si ilu.......
A) Ila
B) Oyo
C) Owu
D) Ketu
  • 10. . Tani abikeyin awon Omo _ Omo oduduwa
A) Orangun
B) Onisabe
C) Oranmiyan
D) Olupopo
  • 11. Tani akobi awon Omo _ Omo oduduwa
A) Oranmiyan
B) Olowu
C) Onisabe
D) Orangun
  • 12. . Iro fawẹẹli ní...
A) A
B) F
C) L
D) B
  • 13. Ẹsin akọkọ ti wọn sìn Ni ilu mẹka ni ẹsin
A) Guru
B) Kisitẹni
C) Musulumi
D) Iborisa
  • 14. ...... Ni olori awọn eniyan bá ni ile - ifẹ
A) Ọba ibini
B) Agbọnmiregun
C) Agunlejika
D) Lamurudu
  • 15. . Alifabẹẹti ede Yorùbá Pin Si ọna....
A) Meje
B) Meji
C) Marun
D) Mẹta
  • 16. Apeere faweli aranmupe ni
A) An
B) B
C) Gb
D) U
  • 17. Faweli ______ ni 'O'
A) Gigun
B) Wewe
C) Perese
D) Roboto
  • 18. _______ ni baba buremo
A) Asara
B) Okanbi
C) Lamurudu
D) Oduduwa
  • 19. Ta ni o jogun "aso" ninu awon Omo oduduwa
A) Olowu
B) Alaketu
C) Oranmiyan
D) Onisabe
  • 20. Tani o jogun Ile
A) Oba ibini
B) Oranmiyan
C) Orangun
D) Alaketu
  • 21. Oba ibini jogun
A) Owo eyo
B) Iyawo
C) Ileke
D) Aso
  • 22. _______ ni ohun ti a ro lokan ni ori koko Oro kan ti a si ko sile
A) Orin
B) Asa
C) Aroko
D) Ere
  • 23. Ewo ni kii se Koko inu aroko
A) Ikadi
B) Ipin afo
C) Ifojusode
D) Igunle
  • 24. Ilapa ero ni
A) Koko kekeke
B) Oro aso keyin
C) Ise inu aroko
D) Akole oro
  • 25. Ipin afo ma n bere pelu
A) Faweli roboto
B) Leta nla
C) Leta kekeke
D) Faweli aranmupe
  • 26. Igunle ni
A) Ikojopo aroko
B) Ipari aroko
C) Ibere aroko
D) Aarin arako
  • 27. Okan ninu awon wonyi ko si ninu eelo inu ile
A) Tabili
B) Aga
C) Sibi
D) Patako
  • 28. A Le ri awon wonyi ni ayika Aya fi
A) Ekun
B) Ile eye
C) Ewe
D) Igi
  • 29. Onka 20 ni ____ ni ede yoruba
A) Ogbon
B) Mewa
C) Ogun
D) Ogoji
  • 30. Onka 35 ni
A) Metaala
B) Egbewa
C) Medogun
D) Marundinlogoji
  • 31. "Ogorun" tunmo si
A) 100
B) 80
C) 50
D) 20
  • 32. "Mejiidinlogun" ni
A) 13
B) 18
C) 22
D) 202
  • 33. "Okanlelogbon" ni
A) 16
B) 27
C) 31
D) 101
  • 34. "Metalelogoji"
A) 43
B) 34
C) I3
D) 25
  • 35. Onka "70" ni
A) Egbeje
B) Aadorin
C) Ogowa
D) Ogorin
  • 36. Ta ni otunmo ede oyinbo si yoruba
A) Samuel Atanda crowther
B) Samson Ajayi crowther
C) Samuel Ajayi crowther
D) Bishop annex Samuel
  • 37. Odun wo ni o tunmo ede yoruba si oyinbo
A) 1842
B) 1848
C) 1994
D) 2024
  • 38. Ijo wo ni o ran lowo
A) Ijo kerubu
B) Ijo Guru
C) Ijo CMS
D) Ijo musulumi
  • 39. Odun wo ni o se itebomi
A) 1825
B) 1920
C) 1861
D) 2025
  • 40. Omo ilu bo ni
A) Sudan
B) Ogun
C) Amerika
D) Oyo
  • 41. Ta ni baba nla awa Yoruba?
A) Okanbi
B) Lamurudu
C) Oduduwa
D) Asara
  • 42. Omo melo ni okanbi bi
A) Marun
B) Eyokan
C) Meje
D) Mesan
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.