jss3 Yoruba1st term exam 2025/26
  • 1. Ninu EWI - 'OORUN ASUNJU'
    oorun asunju _______
A) Se dandan
B) Dara ju lo
C) Se pataki
D) Ko mere wa
  • 2. Lasiko isinmi die, won ni ka gbafefe ki opolo WA o_______
A) Ji pepe
B) Daru
C) Baje
D) Gbona
  • 3. Ki a tun pada wo kilaasi pelu _____
A) Ara gbigbona
B) Akotun agbara
C) Oju pipon
D) Ibanuje
  • 4. Omo ilewe ti o ba yan oorun laayo, yi o
A) Ka iwe akati
B) Yege daradara
C) Rewa pupo
D) Lopolo pipe
  • 5. Ninu EWI yi "mojesin " tunmo si
A) Omo ile-iwe
B) Oluko
C) Obi
D) Iagbalagba
  • 6. Worobo je orisi
A) Ise adani
B) Aso tita
C) Ise ijoba
D) Owo sise
  • 7. Ipolowo oja ni
A) Ibaje oja
B) Jiji oja
C) Fifi pamo oja
D) Ikede oja tita
  • 8. Bayii ni a se n polowo "Garri"
A) Kikan lenu Garri
B) Fun fun loju Garri
C) Ayangbe gaari o
D) O gbe ku Garri
  • 9. Bayii ni a se n polowo "oyin "
A) Oyin igan
B) Oyin aladun
C) Oyin ladun oyin
D) Oyin duudu
  • 10. Airisese tunmo si
A) Ki eniyan Mari ise se
B) Ki eniyan ma fe sise
C) Ki eniyan rii ise to po
D) Ki Owo ise kere
  • 11. Airisese wopo ni orile ede Nigeria
A) Beko
B) Boya
C) Beni
D) O Le ri be
  • 12. Ohun ti o fa airisese ni
A) Ai ni ife si ise osu
B) Oro aje orile ede ti o ga soke
C) Oro aje orile ede ti ko lo deede
D) Opo Ile ise ko fe gba omode
  • 13. Bayii ni a se n polowo 'ewedu
A) Ewedu to nyo
B) Elewedu toko dee
C) Ofe lewe be
D) Dudu obe ree
  • 14. Owo sise fun ni ni anfani lati yan
A) Ile to wu ni lati gbe
B) Oja to wu ni lati ta
C) Ede to wu ni lati so
D) Oko to wu ni lati fe
  • 15. Ipinle melo ni eya Yoruba WA ni Ile naijiria
A) Mewa
B) Meta
C) Meji
D) Mesan
  • 16. Awon ilu wonyi "Ogbomosho,ilora,eruwa" WA labe ipinle
A) Ogun
B) Kogi
C) Oyo
D) Osun
  • 17. Ni ipinle Ekiti,ilu wo ni ko si nibe
A) Sepeteri
B) Emure
C) Ijero
D) Aramoko
  • 18. Ni ipinle eko ni ______ wa
A) Ido
B) Agege
C) Ede
D) Kaba
  • 19. ________ ni baba nla awa yoruba
A) Buremo
B) Agbomiregun
C) Asara
D) Oduduwa
  • 20. Esin _______ ni won Koko n sin ni ilu meka
A) Christeni
B) Meteta
C) Iborisa
D) Musulumi
  • 21. _______ ni olori aborisa nilu meka
A) Oduduwa
B) Okanbi
C) Lamurudu
D) Asara
  • 22. Ta ni baba buremo
A) Agbomiregun
B) Lamurudu
C) Okanbi
D) Asara
  • 23. Tani o fina Jo awon nkan aborisa ti won sin ni ilu meka
A) Okanbi
B) Lamurudu
C) Buremo
D) Agbomiregun
  • 24. Ilu wo ni oduduwa ATI awon eniyan re Koko de nigba ti won kuro ni ilu meka
A) Ile ife
B) Oke oya
C) Sudan
D) Ghana
  • 25. Ilu wo ni oduduwa ATI awon eniyan re pada tedo si nigbeyin
A) Sudan
B) Meka
C) Oke oya
D) Ile ife
  • 26. Ojo melo ni oduduwa ATI awon eniyan re fi rin de Ile ife
A) Ogowa ojo
B) Eedegbeta ojo
C) Egbefa ojo
D) Aadorun ojo
  • 27. Omo melo ni oduduwa bi
A) Meta
B) Marun
C) Mesan
D) Eyokan
  • 28. Okanbi bi omo
A) Mesan
B) Eyokan
C) Mefa
D) Meje
  • 29. Awon wonyi ni Omo okanbi ayafi
A) Onisabe
B) Olupopo
C) Osawewe
D) Orangun
  • 30. Alaketu jogun
A) Ade
B) Ile
C) Owo
D) Aso
  • 31. Olowu jogun
A) Obirin
B) Aso
C) Ileke
D) Ile
  • 32. Ta ni o jogun Ile?
A) Alaketu
B) Oba ibini
C) Olowu
D) Oranmiyan
  • 33. Tani o jogun eran osin?
A) Alaketu
B) Osawewe
C) Olupopo
D) Onisabe
  • 34. Ta ni o n gba isakole lowo awon egbon re
A) Olowu
B) Alaketu
C) Oranmiyan
D) Olupopo
  • 35. _______ ni o the ilu Oyo do
A) Osawewe
B) Oranmiyan
C) Olowu
D) Alaketu
  • 36. Tani o te ilu ila do?
A) Orangun
B) Onipopo
C) Onisabe
D) Alaketu
  • 37. Onka "131" je
A) Okanleladota
B) Okanlelogbon
C) Okandinlogofa
D) Okanlelaadoje
  • 38. Onka "165" je
A) Aarunlelogofa
B) Arunlelogofa
C) Aarundinlogofa
D) Aarundinladosan
  • 39. "adowa" je
A) 190
B) 170
C) 140
D) 1000
  • 40. "Aadoje"
A) 75
B) 130
C) 70
D) 170
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — a math test site for students of all grade levels.