JSS2 YORUBA 3RD TERM EXAM
  • 1. _________ ni itunmo ede kan si omiran
A) Iranra eni lowo
B) Isunki
C) Ibanisoro
D) Aayan ogbufo
  • 2. Eni ti o n tumo ede kan si omiran ni a n pe ni
A) Alaroye
B) Elejo
C) Alalaye
D) Ogbufo
  • 3. E ni fe tunmo oro gbodo____
A) Lohun
B) Lowo
C) Buru
D) Gbo ede mejeeji daradara
  • 4. Ni nu aayan ogbufo,a gbodo fun oro ni
A) Itunmo ti ko ye rara
B) Itunmo ti o tobi
C) Itunmo ti o jin na si
D) Itunmo ti o bamu
  • 5. Itunmo 'Boundary' ni
A) Ibikan
B) Ile
C) Ise
D) Aala
  • 6. Itunmo 'Culture' ni
A) Iwa
B) Esin
C) Aaye
D) Asa
  • 7. Itunmo 'overlap' ni
A) Bu ara won
B) Ge ara won
C) Wonu ara won
D) Na ara won
  • 8. 'He was ashamed' tunmo si
A) Oju e ri
B) Won doju ti
C) Oju n dun
D) Oju tii
  • 9. ________ ni a fi n ke ' Ewi'
A) Imu
B) Oju
C) Enu
D) Emi
  • 10. A ma n lo 'Ewi' nibi ________
A) Ija
B) Ayeye
C) Oro aje
D) Ogun
  • 11. Ki aranmo to le wa ye,_______
A) Faweeli meji gbodo te le ara won
B) Faweeli ko gbodo bere oro na
C) Ko gbodo si faweeli ninu oro na
D) Konsonanti meji gbodo te le ara won
  • 12. Se isunki oro yii : ile + iwe
A) Ilewe
B) Iluwe
C) Ilewe
D) Ileiwe
  • 13. Gba + ise
A) Gbese
B) Gbase
C) Gbise
D) Gbaise
  • 14. Ninu ewi "ise logun ise" Ohun ti a ba fara sise fun________
A) Ni pe lowo eni
B) Ni so nu lowo eni
C) Ni se iku pani
D) Ni fi iya je ni
  • 15. Apa lara ________
A) Igunpa la ko mo
B) Ori la ba bo
C) Igunpa ni iyekan
D) Orunkun la ba mo
  • 16. Eko n so ni di_______
A) Opuro
B) Oga
C) Omose
D) Janduku
  • 17. Iro ti o ni agbara lati yi iro miran pada si tire ni________
A) Aranmo aforu
B) Iro afaranmo
C) Aranmo kikun
D) Iro agbaranmo
  • 18. Iro ti o yi pada gba abuda iro miran ni
A) Iro agbaramo
B) Isunki
C) Iro afaranmo
D) Iparoje
  • 19. Omobinrin ti o gbe ibi korun ni_____
A) Ibikunle
B) Eli
C) Aina
D) Ayan
  • 20. Omo ti iya re ko se nkan osu ti won fi bi ni
A) Dada
B) Ojo
C) Ilori
D) Odun
  • 21. Omo ti oyun re ju osu mesan lo ti won fi bi ni
A) Ige
B) Omope
C) Ajayi
D) Oke
  • 22. Omo ti o yi ara mo inu apo ni
A) Oke
B) Odu
C) Ige
D) Ola
  • 23. Apeere oruko idile "Onilu" ni
A) Olalomi
B) Ayangbade
C) Ogungbemi
D) Osuntoke
  • 24. Apeere oruko amu torunwa ni
A) Omoyeni
B) Gbemisola
C) Kehinde
D) Lamidi
  • 25. Apeere oruko Abiku ni
A) Idowu
B) Malomo
C) Ige
D) Tope
  • 26. Apeere oriki ni
A) Omotunde
B) Odun
C) Ojo
D) Alabi
  • 27. ________ wa ninu awon eelo isomoloruko
A) Omigbona
B) Ororo
C) Omitutu
D) Alubose
  • 28. Ni aye atijo ojo ___ ni a maa n so omobirin loruko
A) Kewa
B) Kejo
C) Keje
D) Kesan
  • 29. Ni aye atijo, awon okunrin ni won ma n so loruko ni ojo
A) Kejo
B) Kesan
C) Keje
D) Keta
  • 30. Ninu ewi "iwulo eko" Iwulo eko ju_________ lo
A) Oja ti ta lo
B) Orun si sun lo
C) Omo bibi lo
D) Ile kiko
  • 31. Eko n so ni di
A) Olosi
B) Jagidijagan
C) Eni yepere
D) Ilumoka laye
  • 32. Iwa ika tunmo si
A) Iwa alalubarika
B) Iwa afojudi
C) Iwa igberaga
D) Iwa buburu
  • 33. Lara iwa ika ni
A) Ere idaraya
B) Egbe alafowosowopo
C) Ikonileru
D) Eko kiko
  • 34. A le dekun iwa ibaje
A) Ti a ba bi omo pupo
B) Ti a ba fi ara wa si ipo omo lakeji
C) Ti a ba fe iyawo pupo
D) Ti a ba lowo lowo
  • 35. _________ nia fi n so oro meji papo ninu gbolohun
A) Oro aropo oruko
B) Oro asopo
C) Oro atokun
D) Oro ise
  • 36. Apeere oro atokun ni
A) Si
B) Iwo
C) Sun
D) Olu
  • 37. Apeere oro - ise ni
A) Ati
B) Awon
C) Dide
D) Fiofio
  • 38. Apeere oro - oruko ni
A) Emi
B) Sugbon
C) Ati
D) Ibadan
  • 39. Dudu gidigidi"je
A) Oro oruko
B) Oro atokum
C) Oro apejuwe
D) Oro ise
  • 40. Silebu melo lowa ninu oro wonyii "0luponmita"
A) Marun
B) Merii7
C) Mefa
D) Mee
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.