ThatQuiz Test Library Take this test now
jss2 yoruba 1st term exam 2025/26
Contributed by: College
  • 1. Ninu EWI-' ise ki I pa ni'
    Eni to sise lo jare ____
A) Ise
B) Owo
C) Osi
D) Aso
  • 2. ________ lo bomo je
A) Owo
B) Ole
C) Ise
D) Aso
  • 3. To a ba sise Ara en a
A) Yagaga
B) Doti
C) Baje
D) Daru
  • 4. Eni ba sise ni se n so di eni
A) Eyin
B) Ilele
C) Osi
D) Aponle
  • 5. Ai sise n fa _________
A) Igbega
B) Ariyanjiyan
C) Abuku
D) Aponle
  • 6. Eni ti ebi ba pa si le
A) De ibi giga
B) Jale
C) Lowo
D) Le ra moto
  • 7. Ti a ba sise, eje Ara a
A) Dudu
B) A ribi rin kaakiri ara
C) Gbona
D) Gbe
  • 8. Itoju Ara ni
A) Lilo Ara ni ilokulo
B) Ki ko idoti ba ara
C) Sise Ara loge
D) Bi ba ara je
  • 9. ________ je Ara iwa yoruba
A) Imototo
B) Obun
C) Idotasile
D) Ikorira
  • 10. Iwa obun Le fa
A) Igbega
B) Ilera
C) Aisan
D) Owo pupo
  • 11. Ona ti a Le fi toju Ara ni
A) Wiwo aso didoti
B) Ki ekanna doti
C) Iwe wiwe
D) Ji je ESO ti ko pon
  • 12. Awon ohun eelo itoju Ara ni iwonyii ayafi
A) Ose
B) Koinkoin
C) Omi
D) Ata
  • 13. "Ojoru" ninu ose ni
A) Sunday
B) Wednesday
C) Saturday
D) Friday
  • 14. "Ojobo " ni
A) Monday
B) Friday
C) Saturday
D) Thursday
  • 15. June ni a n pe ni
A) Agemo
B) Sere
C) Owewe
D) Ogun
  • 16. August ni a n pe ni
A) Belu
B) Owewe
C) Okudu
D) Sere
  • 17. September ni
A) Ogun
B) Belu
C) Igbe
D) Owawa
  • 18. Onka 1100 je
A) Egberundinlogorun
B) Egbefa
C) Eedegbefa
D) Eedegbeta
  • 19. Onka 1700 ni
A) Egberun
B) Egbesan
C) Edegbesan
D) Egbeje
  • 20. Onka 1900 ni
A) Egbesan
B) Eedegbewa
C) Aadosan
D) Ogosan
  • 21. Awon ohun eelo inu Ile ni iwonyi ayafi
A) Faanu
B) Patako
C) Ibusun
D) Aago
  • 22. A Le ri faanu ni ibi wonyi ayafi
A) Ile igbe
B) Ofisi
C) Ile itaja
D) Ile iwe
  • 23. Iwa ika je
A) Iwa daradara
B) Iwa obun
C) Iwa buburu
D) Iwa ole
  • 24. Awon wonyi ni iwa ika laye atijo ayafi
A) Ikonileru
B) Lilu iyawo
C) Ofinisofa
D) Fifi eniyan rubo
  • 25. Apeere iwa ika ode oni ni
A) Ifinisofa
B) Jijinigbe
C) Lile obinrin ni magun
D) Fifi eniyan rubo
  • 26. A Le dekun iwa ika nipa
A) Fifi iya je elese
B) Pipa elese
C) Gbigba alaafia laye
D) Gbigba Owo aito lowo elese
  • 27. Awon to won ma n ko ila ni a n pe ni
A) Olola
B) Kolakola
C) Onila
D) Ilagbemi
  • 28. Awon to won lu ilu ni
A) Ojo
B) Ode
C) Ayan
D) Agbe
  • 29. Blacksmithing ni
A) Agbede
B) Apeja
C) Akope
D) Onidiri
  • 30. Onigbajamo ni
A) Haircutter
B) Tailoring
C) Carving
D) Farming
  • 31. "Ise ona" ni
A) Blacksmithing
B) Shaving
C) Carving
D) Hunting
  • 32. Awon agba ma n fi "Owe"_____
A) Ba Oro je
B) Fa ija
C) Gba eto elomiran
D) Fi idi oro mule
  • 33. Pari owe yi. "a ki fi ikanju________
A) Wewu odi
B) Je eba mo iresi
C) La obe gbigbona
D) Mu Omi gbigbona
  • 34. Aja lo leru"________
A) Ere laja n se
B) Pepe ma to ja
C) Iro ni pepe n pa
D) Otito ni pepe n so
  • 35. #50 ni yoruba ni
A) Aadota naira
B) Ogbon naira
C) Ogorun naira
D) Ogun naira
  • 36. #200 ni
A) Igba naira
B) Ogoji naira
C) Irinwo naira
D) Edegbesan naira
  • 37. Agba ki WA Loja" _______
A) Ki ori baje
B) Ki ori daru
C) Ki ori omotuntun wo
D) Ki ede wo
  • 38. Eni a Fe la mo"
A) A ko mo ota eni
B) A ko mo olorire
C) A ko mo Eni to inu n bi
D) A ko mo Eni fe ni
  • 39. Pipe ni yi o pe,______
A) Akololo a pe baba
B) Omo a sare
C) Omi a denu
D) Ori a mi
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the site for test creation and grading in math and other subjects.