ThatQuiz Test Library Take this test now
YORUBA PRY5 1ST TERM EXAM 2024/2025
Contributed by: College
  • 1. 1. Nínú ìwe alawiiye, (akọle : ogun idanwo)tani o mu awọn ọmọ lọ sì ile onisegun
A) Ẹgbọn bọsẹ
B) Bọsẹ
C) Bọla
D) Dupẹ
  • 2. 2. Nínú akole ogun idanwo ìwe alawiiye...awọn wo ni wón ro pe awọn yóò gbà gbogbo maaki tan
A) Ẹgbọn Bola
B) Bọsẹ ati dupẹ
C) Tolani
D) Bola
  • 3. 3.ninu iwe alawiiye akọle ogun idanwo..Ta ni kogba pe ogun idanwo n bẹ
A) Bọla
B) Dupẹ
C) Ṣeṣan
D) Ẹgbọn bọsẹ
  • 4. 4. Nínú ìwe alawiiye akọle ogun idanwo.. ẹni tí inú rẹ dùn bí se ka ìwé ibeere idanwo ni..........
A) Bọsẹ
B) Dupẹ
C) Bọla
D) Ẹgbọn bọsẹ
  • 5. 5. Nínú ìwe alawiiye akọle ogun idanwo...tani o sọ pe ohun dáràn ninu yara idanwo
A) Dupẹ
B) Bọsẹ
C) Bọla
D) Ẹgbọn bọsẹ
  • 6. 6.ninu iwe alawiiye akọle ọwọ ẹyin....iye awọn orukọ orisirisi ti a pè owo ẹyin nínú ẹkọ yìí jẹ
A) Mewa
B) Mẹfa
C) Marun
D) Meje
  • 7. 7. Nínú ìwe alawiiye akọle owo ẹyin... Ọkan nínú awọn nkan ti awọn eniyan n fi dipò owó abẹtẹlẹ ni
A) Suuru
B) Igberaga
C) Ara wọn
D) Faari
  • 8. 8. Gbólóhùn alabọde ni a tún mọ Si......
A) Aṣẹ
B) Ẹlẹyọ ọrọ ìse
C) Alakanpọ
D) Ọlọpọ ọrọ ise
  • 9. 9. Àpẹẹrẹ ọrọ ìse yii.(..........) Le duro' gẹgẹ bí gbólóhùn alabọde
A) Jẹ
B) Si
C) Na
D) Jade
  • 10. 10. Ẹni tabi ohun tí o se nnkan nínú gbólóhùn ni.........
A) Abọ
B) Oluwa
C) Ẹyàn
D) Ẹpọn
  • 11. 11. ........ Ni ẹni tabi ohun tí a ṣe nnkan Si nínú gbólóhùn
A) Abọ
B) Ẹyàn
C) Ẹpọn
D) Oluwa
  • 12. 12. ......... Ni a mọ sì ọrọ tabi atopọ tí o n gbé oye tabi ero kíkún jade
A) Silebu
B) Ọrọ ise
C) Lẹta
D) Gbólóhùn
  • 13. 13. Adirẹsi mélòó ni lẹta gbẹfẹ ni
A) Mẹta
B) Meji
C) Ọkan
D) Mẹrin
  • 14. 14. Lẹta...... Kí i ni akọle
A) Aṣẹ
B) Gbẹfẹ
C) Aigbagbẹfẹ
D) Iroyin
  • 15. 15. Ọwọ........ Ni adirẹsi ma n wa
A) Ẹyin
B) Ọtun
C) Iwaju
D) Osi
  • 16. 16. Ipin mélòó ni lẹta Pin si
A) Merin
B) Meji
C) Mẹta
D) Marun
  • 17. 17. ......... Ni ọna àròkọ ti a ma n Gba sọ ohun to wa nínú wa Si ẹlòmíràn yala boya ololufẹ ẹni tabi òbí ẹni tabi ọgá ile isẹ kan
A) Silebu
B) Lẹta
C) Gbólóhùn
D) Ọrọ
  • 18. 18. Ọrẹ mí ọwọn jẹ.............nínú lẹta gbẹfẹ
A) Inifẹ ẹni
B) Ìkíni
C) Ibuni
D) Ipọnni
  • 19. 19. ...... lẹta ti aa n kọ Si awọn ènìyàn ti wọn wa ni ipò kan ni ibi isẹ aladani tabi Si àjọ ilu
A) Gbẹfẹ
B) Aṣẹ
C) Iroyin
D) Aigbagbẹfẹ
  • 20. 20. Lara awọn ti a ma n kọ lẹta aigbagbẹfẹ Si ni awọn wọnyi ayafi....
A) Alága ìjọba ìbílẹ̀
B) Giwa ile isẹ
C) Olootu ìwe iroyin
D) Ololufẹ ẹni
  • 21. 21. Adirẹsi mélòó ni lẹta aigbagbẹfẹ ma n ni
A) Meji
B) Mẹta
C) Mẹrin
D) Ẹyọkan
  • 22. 22. Kínní 195 ni èdè yorúbá
A) Marunlenigba
B) Ọgọwa
C) Marundinigba
D) Meedofa
  • 23. 23.bawo ni ase lé pe figọ yìí lede yorúbá 170
A) Ọgọwa
B) Aadọwa
C) Ọgọsan
D) Aadọsan
  • 24. 24. Aadọwa ni figọ jẹ....
A) 190
B) 200
C) 170
D) 160
  • 25. 25. Orukọ miran fún ọgọwa ni....
A) Ọkanlaadofa
B) Ọdunrun
C) Igba
D) Okanlelọgọfa
  • 26. 26. Ìtumọ lẹta gbẹfẹ ni ede gẹẹsi ni...
A) Formal letter
B) Semi formal letter
C) Informal letter
D) Package letter
  • 27. 27. Ìtumọ gbólóhùn alabọde ni èdè gẹẹsi ni.......
A) Simple sentence
B) Compound complex sentence
C) Compound sentence
D) Complex sentence
  • 28. 28. Ìtumọ gbólóhùn alakanpọ ni èdè gẹẹsi ni..........
A) Simple sentence
B) Compound complex sentence
C) Complex sentence
D) Compound sentence
  • 29. 29. Ìtumọ lẹta aigbẹfẹ ni èdè gẹ̀ẹ́sì ni.........
A) International letter
B) Informal letter
C) Formal letter
D) Semi formal letter
  • 30. 30. 99 ni onka yoruba jẹ........
A) Ọkanlelaadọrun
B) Ọkandinladọrun
C) Ọkandinlọgọrun
D) Ọkanlelọgọrun
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the site for test creation and grading in math and other subjects.