- 1. 1. Tani babanla awon yorùbá
A) Oduduwa B) Asara C) Lamurudu D) Orangun
- 2. 2. Alifabeeti ede Yoruba je......
A) Mejila B) Meedogbon C) Merinla D) Meedogun
- 3. 3. ........... Ni iro ti ape nigba ti idiwo kosi fun eemi
A) Silebu B) Mofiimu C) Faweli D) Konsonanti
- 4. 4.Onka faweli arin je....
A) Meji B) Merin C) Meta D) Marun
- 5. 5.Onka faweli ni akotan je.....
A) Mefa B) Merin C) Marun D) Meje
- 6. 6.Onka konsonanti ni akotan je.....
A) Meedogbon B) Merinla C) Mejidinlogun D) Metala
- 7. 7.Ti aba lo ipo tan_ an_na ofun, ale pin konsonanti si orisi ona......
A) Marun B) Meta C) Mefa D) Meji
- 8. 8 Ti aba lo ibi isenupe ale pin konsonanti si ona......
A) Marun B) Mejo C) Mewa D) Meje
- 9. 9 Awon leta aferigipe ni .....
A) F B) t,s,d,n,r,j C) K,g D) J,s
A) Afunpe B) Aferigipe C) Aranmupe D) Airanmupe
- 11. 11. Oruko Omo oduduwa ni.....
A) Okanbi B) Oranmiyan C) Oba ibini D) Alaketu
- 12. 12. Yoruba gbagbo pe oduduwa ati awon eniyan baba re fi ............ rin lati Meka de ile_ ife
A) Aadorun ojo B) Aadoje ojo C) Ogorun ojo D) Aadofa ojo
- 13. 13. Tani won Koko fi je oba akoko ni ile _ ife
A) Asara B) Buremo C) Oduduwa D) Lamurudu
- 14. 14. ........ Ni otedo si ilu ketu
A) Olupopo B) Onisabe C) Oranmiyan D) Alaketu
- 15. 15. Oranmiyan tedo si ilu.......
A) Ketu B) Ila C) Owu D) Oyo
- 16. 16. Tani abikeyin awon Omo _ Omo oduduwa
A) Onisabe B) Olupopo C) Oranmiyan D) Orangun
- 17. 17. Tani akobi awon Omo _ Omo oduduwa
A) Olowu B) Oranmiyan C) Orangun D) Onisabe
- 18. 18. Orisi isori Oro melo lowa ninu ede yoruba
A) Mefa B) Meje C) Mesan D) Mejo
- 19. 19. .......... Ni awon oro ti won le daduro ni ipo oluwa, abi abọ tabi eyan ninu gbolohun
A) Oro atokun B) Oro oruko C) Oro ise D) Oro eyan
- 20. 20. ........... Je oluse isele inu gbolohun
A) Atokun B) Eyan C) Abo D) Oluwa
- 21. 21. .......... Ni olufaragba nnkan ti oluwa se ninu gbolohun
A) Abo B) Atokun C) Oluwa D) Eyan
- 22. 22. ....... Lowa ni ipo oluwa ninu gbolohun yii... Bola losi ilu amerika
A) Losi B) Amerika C) ILu D) Bola
- 23. 23. Apere Oro oruko ni ipo abo ninu gbolohun yii.. ogbeni Abdul afeez na akeeko bi eran
A) Eran B) Abudul afeez C) Ogbeni D) Akeeko
- 24. 24 ........ Ni awon ti an lo dipo oro_ oruko ninu gbolohun
A) Oro aropo oruko B) Oro atokun C) Oro ise D) Oro oruko
- 25. 25. Apere Oro aropo oruko ninu gbolohun yii.... O Ra iwe
A) O B) Ora C) Ra D) Iwe
- 26. 26. Melo ni abuda Oro aropo oruko
A) Mefa B) Marun C) Merin D) Meta
- 27. 27. Melo ni Oro aropo afara joruko
A) Mefa B) Merin C) Marun D) Meta
- 28. 28. Onka Konsonanti airanmupe je....
A) Metala B) Merindinlogun C) Mejila D) Merinla
- 29. 29. Onka faweli iwaju je.....
A) Meji B) Meta C) Marun D) Merin
- 30. 30. Onka konsonanti akunyun je ......
A) Mokanla B) Merinla C) Metala D) Mejila
- 31. 31. Kọnsonanti aikunyun ni
A) B B) G C) Gb D) Ṣ
- 32. 32. Iro fawẹẹli ní...
A) A B) B C) L D) F
- 33. 33. Ẹsin akọkọ ti wọn sìn Ni ilu mẹka ni ẹsin
A) Iborisa B) Kisitẹni C) Musulumi D) Guru
- 34. 34. ...... Ni olori awọn eniyan bá ni ile - ifẹ
A) Ọba ibini B) Lamurudu C) Agunlejika D) Agbọnmiregun
- 35. 35. Ipinlẹ melo ni iran yoruba wa ni naijiria
A) Mẹwa B) Mẹsan C) Meje D) Marun
- 36. 36. 100 ni onka yoruba jẹ
A) Ọgọrun B) Ogoji C) Aadọrun D) Ogoje
- 37. 37. Ọrọ orukọ ninu gbólóhùn yìí nì...mo jẹ ẹwa lamulukẹ sun lalẹ ana
A) Ana B) Lamulukẹ C) Mo D) Ẹwa
- 38. 38. Alifabẹẹti ede Yorùbá Pin Si ọna....
A) Meji B) Mẹta C) Meje D) Marun
- 39. 39. Agbalagba jẹ ọrọ oni silebu...
A) Meje B) Mẹrin C) Meji D) Marun
- 40. 40. ...... Ni o ṣiṣẹ ẹyàn nínú gbólóhùn yìí....ile iwosan ni Shola wa
A) Ile B) Shola C) Iwosan D) Ni
|