ThatQuiz Test Library Take this test now
AIC Yoruba 1st Term Exam for JS 3
Contributed by: College
  • 1. 2000 ní òǹkà Yorùbá ni___
A) Ẹgbẹrun
B) Ogún
C) Ẹgbàá rin
D) Ẹgbàá
  • 2. Kí ni 20,000 ní òǹkà Yorùbá?
A) Ẹgbàá wà
B) Ẹgbàá je
C) Ẹgbàafà
D) Ẹgbarun
  • 3. Ohun tí kò tọ́ tí a ṣe sí ọmọlàkejì ni ìwà___
A) Ìkà
B) Omolúàbí
C) Ìdọ̀tí
D) Ọ̀sì
  • 4. Ìwọ̀nyí ni ìwà ìkà tí ó wọ́pọ̀ ni ayé àtijọ́ àyàfi___
A) Ìfọmọṣowó
B) Ìfiniṣọfà
C) Ìfinirúbọ
D) Ìfiniṣẹrú
  • 5. Ìwà ìkà tí o wọ́pọ̀ lóde òní ni ìwọ̀nyí, àyàfi___
A) Ìjínigbé
B) Ìfiniṣọfà
C) Lílo ọmọ nílọ̀kulọ̀
D) Ìfiniṣowó
  • 6. Ọ̀rọ̀____lè ṣiṣẹ́ olùwà,ẹ̀yán, àti àbọ̀.
A) Orúkọ
B) àpèjúwe
C) àpónlé
D) ìṣẹ
  • 7. ____ ni àwọn Yorùbá gbà pé wọ́n ń sọ ọjà di ọ̀wọ́n.
A) Ọlójà
B) Èrò ọjà
C) Alágbàtà
D) Oníbárà
  • 8. À n ṣe òwò kí á le____
A) di ìyálọ́jà
B) ríhun ṣe
C) sọ́ọ̀tì
D) jẹ èrè
  • 9. Àǹfààní òwò ṣiṣe níwònyí àyàfi; Ó ń mú ____
A) kí a níṣẹ́ ẹni lọ́wọ́
B) ẹni di ọ̀lẹ
C) kí ìṣẹ́ àti òṣì pòórá
D) kí a tẹpá mọ́ṣẹ́
  • 10. ____tàbí káràkátà jẹ́ ọ̀kan nínú ara iṣẹ owó Yoruba.
A) Oúnjẹ jíjẹ
B) Aróbọ̀
C) Òwò ṣíṣe
D) Ìwà òtítọ́
  • 11. Ẹni tí ó ta ọjà tí kò jèrè ni won ní o____
A) tàtà jèrè
B) ṣòwò sọ́ọ̀ti
C) gbìyànjú
D) tẹpá mọ́ṣẹ́
  • 12. Ìwòyí ni iṣẹ tí ọ̀rọ̀ orúkọ le ṣe,ayafi____
A) olùwà
B) òpómúléró
C) àbọ̀
D) ẹ̀yán
  • 13. 'Bàbá Bọ́lá lọ sí oko'. Kí ni ọrọ orúkọ tí o se iṣẹ́ ẹ̀yán nínú gbólóhùn yìí?
A) Bọ́lá
B) Oko
C) lọ
D) Bàbá
  • 14. Èwo ni kìí ṣe álífábẹ̀ẹ̀tì ede Yorùbá
A) b
B) a
C) ae
D) o
  • 15. Àmì Ohùn òkè ni___
A) /
B) _
C) -
D) \
  • 16. Àmì wo ni ó bá ọ̀rọ̀ yí mu? kirakita--d:d:d:d
A) Kìrákítà
B) Kìràkìtà
C) kirakitā
D) kirákíta
  • 17. Àmì wo ni ó bá ọ̀rọ̀ yí mu? Dodo--d:d
A) Dódó
B) Dodo
C) Dòdò
D) Dọ̀dó
  • 18. Fáwẹ̀lì Yorùbá pín sí:
A) àìgbẹ̀fẹ̀ àti agbẹ̀fẹ̀
B) arẹ́họ́n ati àkùnyùn
C) àìránmúpè ati àrańmúpè
D) àfúnupè àti aṣẹ́nupè
  • 19. Tọ́ka sí ọ̀rọ̀-orúkọ olùwà nínú gbólóhùn yìí: "Ajá bàbá Olú tí jẹ ẹja náà"
A) bàbá
B) Ajá
C) náà
D) Olú
  • 20. "Ojó lọ ra ẹja tí yóò jẹ" Tọ́ka sí ọ̀rọ̀-orúkọ àbọ̀ nínú gbólóhùn yìí.
A) Ojo
B) lọ
C) ra
D) ẹja
  • 21. "Adébísí pa ẹran màálu jẹ". Èwo ni ọ̀rọ̀-orúkọ tí ó ṣiṣé ẹ̀yán nínú gbólóhùn yìí?
A) pa
B) ẹran
C) Adébísí
D) màálu
  • 22. Kí a tó lè di oníṣòwò,a gbọ́dọ̀ ní nǹkan wọnyí àyàfi____.
A) ìdọmọ ẹgbẹ́ ọlọ́jà
B) ní ìmọ̀ nípa ọjà ta fẹ tà
C) ẹ̀kọ́sẹ́ kátà-kárà
D) owó òkòwò
  • 23. Fífún òǹràjà ní díẹ̀ jẹ nínú ọjà tí à ń tà ni à ń pè ní_____.
A) ìtọ́wọ̀
B) ènì
C) àwín
D) sàn díẹ̀díẹ̀
  • 24. Ìwọ̀nyí ni àwọn owó tí a mọ àwọn Yorùbá sì àyàfi_____.
A) Owóróbo
B) Aróbọ̀
C) Aṣọ títa
D) Ìjínigbé
  • 25. ______ni à ń pe àwọn tí n ta ọjà pẹ́ẹ́pẹ́ẹ́pẹ̀ẹ́.
A) Oníwóróbo
B) Alájàpá
C) Aláróbò
D) Olóúnjẹ
  • 26. Ọ̀rọ̀ orúkọ inú gbólóhùn yìí "Motúnráyọ̀ sì tún rápálá wọlé" ni:
A) si
B) Motúnráyọ̀
C) tun
D) wọlé
  • 27. Kọ́ńsónáǹtì tó wà nínú èdè Yorùbá jẹ_____
A) 18
B) 17
C) 10
D) 9
  • 28. Èwo ni kọ́ńsónáǹtì tí a fi èjì ètè pè nínú àwọn wọ̀nyí?
A) g
B) b
C) f
D) d
  • 29. ___jẹ́ fáwẹ̀lì àyanupẹ̀
A) a
B) n
C) m
D) u
  • 30. ___jẹ kọ́ńsónáǹtì àrańmúpè.
A) s
B) p
C) t
D) n
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the site for test creation and grading in math and other subjects.