- 1. 1. Isori oro melo ni a ni ninu ede Yoruba?
A) Mẹta B) Meje C) Mẹfa D) Mejo
- 2. 2. Ewo ni isori oro ti o n toka isele ninu gbolohun? Oro
A) Ise B) Oruko C) Asopo D) Aponle
- 3. 3. ....... jẹ ọkan lára awọn abala ìhun gbólóhùn ede yoruba
A) Apola B) Mofiimu C) Ọrọ orukọ D) Silebu
- 4. 4. Lara awọn iṣọri ọrọ ti àtòjọ láti hun gbólóhùn ede Yorùbá ni........
A) Silebu B) Mofiimu C) Ọrọ ise D) Fonọ́lọ́jì
- 5. 5. Àpólà inú ede yoruba jẹ melo
A) Meji B) Mẹta C) Marun D) Merin
- 6. 6. Lara awọn oríṣi Iro kọnsonanti ni awọn wọnyi ayafi.........
A) Kọnsonanti aikunyun B) Konsonanti ayinmupe C) Kọnsonanti akunyun D) Kọnsonanti aranmupe
- 7. 7. ......... Lo jẹmọ́ ètò Iro ede Yorùbá ati bí a ṣe n lo Iro ede Yorùbá
A) Gbólóhùn B) Silebu C) Fonọ́lọ́jì D) Mofiimu
- 8. 8. ......... Ni Iro ti a gbé jade nígbàtí idiwọ wá fún eemi
A) Kọnsonanti B) Fawẹẹli C) Silebu D) Mofiimu
- 9. 9. ....... Ni ọna ti a n Gba pa ìró jẹ nínú ọrọ tabi àpólà laiyan pipa Iro fawẹẹli tàbí kọnsonanti jẹ nínú ọrọ
A) Isunki B) Mofiimu C) Gbólóhùn D) Silebu
- 10. 10. Lara awọn àpẹẹrẹ isunki ni.....
A) Olodumare B) Adua C) Oluwa D) Ile iwe
- 11. 11. Gbólóhùn ọrọ LAYELAYE yóò di.........ti a ba pa ìró jẹ
A) Lailai B) Layeelayee C) Laelae D) Laylay
- 12. 12. ........ Ni ohun ini ẹni tí o ku, eyi tọka si dukia bíi ilẹ,oko owó ẹrú ati awọn nkán miran
A) Ogun B) Inawo C) Ọrọ sisọ D) Isinku
- 13. 13. Ọna melo ni yorúbá ma n Gba Pin ogun
A) Mẹta B) Meji C) Marun D) Mẹrin
- 14. 14. Ọna melo ni awẹ gbólóhùn Pin si
A) Mẹta B) Meji C) Marun D) Mẹrin
- 15. 15. .......... Ni pínpín ogun Si iye ọmọ ti oku bi
A) Olorijori B) Ilana ofin islam C) Dọgbadọgba D) Ìdí igi
- 16. 16. Lara awọn ìsọri ọrọ èdè yorúbá ni awọn wọnyi ayafi
A) Ọrọ asopọ B) Ọrọ òwe C) Ọrọ apọnle D) Ọrọ atọkun
- 17. 17. Lara awọn àpólà inú ede yorúbá ni awọn wọnyi ayafi
A) Àpólà asopọ B) Àpólà ọrọ orukọ C) Àpólà ọrọ ìse D) Àpólà apọnle
- 18. 18. Nínú ìwe litiresọ ta ká ni ni kilaasi.... orukọ iwe náà ni.......
A) Iwa ika B) Ololufẹ C) Isẹ Aje D) Ọdaju
- 19. 19.. orukọ ẹni tokọ iwe náà ni.....
A) Wasiu Akinpelu B) Olaleye Rukayat C) Adewoyin Sunday D) Bọsẹde iroko ọbaniyi
- 20. 20. Ninu iwe litireso, ọkọ adéọlá jẹ.....
A) Omoluabi B) Òní inure C) Alaanu D) Eyan buruku
- 21. 21. Nínú ìwe litiresọ, iwe ẹri melo ni adéọlá ni
A) Mẹrin B) Mẹta C) Meji D) Marun
- 22. 22. Nínú ìwe litiresọ, ọmọ ìlú wo ni adéọlá jẹ
A) Òyó B) Aha C) Okeho D) Eko
- 23. 23. Nínú ìwe litiresọ, ọmọ melo ni adéọlá bi
A) Mẹfa B) Meje C) Marun D) Meji
- 24. 24. ....... Ni ege ọrọ ti okere julọ ti ale fi eemi ẹnu wà pẹ lẹẹkan soso
A) Silebu B) Àmì ohun C) Fonọ́lọ́jì D) Mofiimu
- 25. 25. Ọna melo ni a lè gbà hun silebu
A) Meji B) Mẹta C) Marun D) Mẹrin
- 26. 26. Àmì ohun melo ni o wa nínú èdè yorúbá
A) Mẹrin B) Meji C) Mẹta D) Marun
- 27. 27. Nínú ìwe litiresọ...iyawo melo ni ọkọ adéọlá ni
A) Mẹrin B) Mẹta C) Marun D) Meji
- 28. 28. Àpẹẹrẹ kọnsonanti aranmupe asesilebu ni....
A) Osan B) Orombo C) Agbalumọ D) Isu
- 29. 29.Ami ohun melo ni AJANLEKOKO ni
A) Marun B) Mẹfa C) Mẹrin D) Meje
- 30. 30. Amin ohun tí owa nínú IGBA(GARDEN EGG) ni
A) Do Re B) Mi Do C) Do Mi D) Re Re
- 31. 31. Amin ohun tí o wa nínú IGBA (200) ni
A) Re Re B) Do Re C) Re Mi D) Mi Mi
- 32. 32. Amin ohun tí o wa nínú IGBA(CALABASH) ni
A) Re Re B) Re Mi C) Re Do D) Do Mi
- 33. 33. Àmì ohun tí o wa nínú ỌKỌ (HUSBAND)
A) Mi Re B) Do Re C) Re Do D) Re Re
- 34. 34. Àmì ohun tí o wa nínú ỌKỌ (hoe) ni
A) Mi Do B) Do Mi C) Re Mi D) Re Do
- 35. 35. Nínú ìwe Lítíréṣọ̀, isẹ wo ni adéọlá n se koto rí isẹ ìjọba
A) Káràkátà B) Isẹ Irun didi C) Olùkọ D) Isẹ ole jija
- 36. 36. Silebu melo ni ọrọ yìí ni "ỌLỌRUNKẸMI"
A) Meje B) Marun C) Mẹrin D) Mẹfa
- 37. 37. Àmì ohun to wa nínú ọrọ YORUBA ni
A) Re mi Do B) Do Re Mi C) Do Mi Re D) Re Do Mi
- 38. 38. Lara awọn oríṣi oku abami ni awọn wọnyi ayafi........
A) Ẹni tí Sàngó pa B) Adẹtẹ C) Abuke D) Arẹwa
- 39. 39. Oríṣi oku melo lowa ni ilẹ yoruba
A) Mẹta B) Mẹrin C) Marun D) Meji
- 40. 40. Lara awọn wahala to ropọ mọ ogun pínpín ni ilẹ yoruba ni awọn wọnyi ayafi.......
A) Ini ifẹ ara ẹni B) Gbigbe ara ẹni lọsí ile ẹjọ C) Ija laarin ọbakan D) Owu jijẹ
|