ThatQuiz Test Library Take this test now
jss3 Yoruba1st term exam 2025/26
Contributed by: College
  • 1. Ninu EWI - 'OORUN ASUNJU'
    oorun asunju _______
A) Ko mere wa
B) Dara ju lo
C) Se pataki
D) Se dandan
  • 2. Lasiko isinmi die, won ni ka gbafefe ki opolo WA o_______
A) Ji pepe
B) Gbona
C) Daru
D) Baje
  • 3. Ki a tun pada wo kilaasi pelu _____
A) Akotun agbara
B) Ibanuje
C) Ara gbigbona
D) Oju pipon
  • 4. Omo ilewe ti o ba yan oorun laayo, yi o
A) Rewa pupo
B) Yege daradara
C) Lopolo pipe
D) Ka iwe akati
  • 5. Ninu EWI yi "mojesin " tunmo si
A) Obi
B) Oluko
C) Iagbalagba
D) Omo ile-iwe
  • 6. Worobo je orisi
A) Ise adani
B) Ise ijoba
C) Aso tita
D) Owo sise
  • 7. Ipolowo oja ni
A) Ibaje oja
B) Fifi pamo oja
C) Jiji oja
D) Ikede oja tita
  • 8. Bayii ni a se n polowo "Garri"
A) Kikan lenu Garri
B) O gbe ku Garri
C) Fun fun loju Garri
D) Ayangbe gaari o
  • 9. Bayii ni a se n polowo "oyin "
A) Oyin duudu
B) Oyin ladun oyin
C) Oyin aladun
D) Oyin igan
  • 10. Airisese tunmo si
A) Ki eniyan rii ise to po
B) Ki eniyan ma fe sise
C) Ki Owo ise kere
D) Ki eniyan Mari ise se
  • 11. Airisese wopo ni orile ede Nigeria
A) Beni
B) Beko
C) Boya
D) O Le ri be
  • 12. Ohun ti o fa airisese ni
A) Oro aje orile ede ti ko lo deede
B) Ai ni ife si ise osu
C) Oro aje orile ede ti o ga soke
D) Opo Ile ise ko fe gba omode
  • 13. Bayii ni a se n polowo 'ewedu
A) Dudu obe ree
B) Ewedu to nyo
C) Ofe lewe be
D) Elewedu toko dee
  • 14. Owo sise fun ni ni anfani lati yan
A) Oko to wu ni lati fe
B) Ile to wu ni lati gbe
C) Oja to wu ni lati ta
D) Ede to wu ni lati so
  • 15. Ipinle melo ni eya Yoruba WA ni Ile naijiria
A) Meta
B) Mesan
C) Mewa
D) Meji
  • 16. Awon ilu wonyi "Ogbomosho,ilora,eruwa" WA labe ipinle
A) Ogun
B) Osun
C) Oyo
D) Kogi
  • 17. Ni ipinle Ekiti,ilu wo ni ko si nibe
A) Sepeteri
B) Aramoko
C) Ijero
D) Emure
  • 18. Ni ipinle eko ni ______ wa
A) Kaba
B) Ido
C) Agege
D) Ede
  • 19. ________ ni baba nla awa yoruba
A) Asara
B) Agbomiregun
C) Buremo
D) Oduduwa
  • 20. Esin _______ ni won Koko n sin ni ilu meka
A) Christeni
B) Iborisa
C) Musulumi
D) Meteta
  • 21. _______ ni olori aborisa nilu meka
A) Lamurudu
B) Asara
C) Oduduwa
D) Okanbi
  • 22. Ta ni baba buremo
A) Asara
B) Agbomiregun
C) Okanbi
D) Lamurudu
  • 23. Tani o fina Jo awon nkan aborisa ti won sin ni ilu meka
A) Buremo
B) Okanbi
C) Agbomiregun
D) Lamurudu
  • 24. Ilu wo ni oduduwa ATI awon eniyan re Koko de nigba ti won kuro ni ilu meka
A) Ghana
B) Ile ife
C) Sudan
D) Oke oya
  • 25. Ilu wo ni oduduwa ATI awon eniyan re pada tedo si nigbeyin
A) Ile ife
B) Sudan
C) Meka
D) Oke oya
  • 26. Ojo melo ni oduduwa ATI awon eniyan re fi rin de Ile ife
A) Eedegbeta ojo
B) Egbefa ojo
C) Aadorun ojo
D) Ogowa ojo
  • 27. Omo melo ni oduduwa bi
A) Meta
B) Marun
C) Eyokan
D) Mesan
  • 28. Okanbi bi omo
A) Meje
B) Mefa
C) Mesan
D) Eyokan
  • 29. Awon wonyi ni Omo okanbi ayafi
A) Orangun
B) Onisabe
C) Osawewe
D) Olupopo
  • 30. Alaketu jogun
A) Aso
B) Ile
C) Owo
D) Ade
  • 31. Olowu jogun
A) Aso
B) Ileke
C) Ile
D) Obirin
  • 32. Ta ni o jogun Ile?
A) Olowu
B) Alaketu
C) Oranmiyan
D) Oba ibini
  • 33. Tani o jogun eran osin?
A) Alaketu
B) Onisabe
C) Olupopo
D) Osawewe
  • 34. Ta ni o n gba isakole lowo awon egbon re
A) Olowu
B) Oranmiyan
C) Olupopo
D) Alaketu
  • 35. _______ ni o the ilu Oyo do
A) Alaketu
B) Olowu
C) Osawewe
D) Oranmiyan
  • 36. Tani o te ilu ila do?
A) Onisabe
B) Orangun
C) Alaketu
D) Onipopo
  • 37. Onka "131" je
A) Okanlelaadoje
B) Okanlelogbon
C) Okandinlogofa
D) Okanleladota
  • 38. Onka "165" je
A) Arunlelogofa
B) Aarunlelogofa
C) Aarundinladosan
D) Aarundinlogofa
  • 39. "adowa" je
A) 190
B) 140
C) 1000
D) 170
  • 40. "Aadoje"
A) 170
B) 70
C) 130
D) 75
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — a math test site for students of all grade levels.